YO/Prabhupada 0232 - Awon ton jowú Olorun. Esu ni wan



Lecture on BG 2.4-5 -- London, August 5, 1973

Pradyumna: O si da ti mo toro je ju kin pa awon eyan to da bi oluko si mi olojukokoro ni gbogbo wan sugbon agba lon je si mi Ta ba pa wan, gbogbo eje wan a wa ni owo wa.

Prabhupāda: Isoro t'alakoko fun arjuna ni wi pe ogbudo pa awon ebi re Ore re Krsna si kigbe mo " kilode to yoole bayi? ma je ti aya re ja, iru aanu bayi owulo. Uttiṣṭha. Dide ko ja Ti mi o ba fe se nkan ma bere si ni fun yin ni orisirisi ejo se ri bayi? ni isin arjuna ti gbe ejo Oluko jade " Krsna mo gba pe aya min ja, nitoribe mo wa ni iwaju awon ebi mi" Sugbon so fe kin pa Oluko mi? Droṇācārya ati Bhīṣmadeva, oluko ni wan je simi se fe kin pa Oluko mi? Gurūn hi hatvā. ko de kin se Oluko lasan Awon Okurin wonyi, eda lasan ko lon je. Mahānubhāvān Eyan pataki ni Bhīṣma ati Droṇācārya.Mahānubhāvān. kathaṁ bhīṣmam ahaṁ saṅkhye droṇaṁ ca madhusūdana (BG 2.4). Oluko ni kan ko lon je, Awon eyan to se pataki ni wan Oruko imi fun Krsna ni Madhusudana, itumo re... Ota Krsna ni Madhu je, gege na Krsna si pa Madhu "Madhusudana ni Oruko re je, awon ota re lo ti pa. Sele fun mi ni ipo pe eyin na ti pa Oluko yin" Gege na kilode te fe kin pa Oluko mi? Iṣubhiḥ pratiyotsyāmi pūjārhāv ari-sūdana. Ota ni itumo Ari-sūdana tumo Madhusūdana, ni " Eni to pa Esu ton pe ni Madhu" Arisudana,.. Ota ni Itumo Ari gege na Krsna ti pa awon Esu to po ton si wa ba ja Nitorina wan sin pe ni Arisudana.

Ti krsna ba ni awon Ota, awon na ma ni. Ni Ile-aye yi eyan gbudo ni awon ota Matsaratā. Ilara ni itumo Matsaratā gege bi ile-aye yi se ri niyen Awon Ota Olorun ton ni'ilara si Olorun, Esu ni wan pe wan ti eyan ba ni ilara, o le ye wa. Sugbon si Olorun ni ale aana, eyan kan wa ri mi O de bere sini jiyan pe kilode ta fi gba Krsna bi Olorun ìjiyàn to mu wa niyen. Krsna na ni awon Ota Sugbon oun ni kan ko, gbogbo awon eyan to wa ninu aye yi, Ota Krsna lon je Nitoripe wan fe duro sori ipele kan pelu Krsna. Krsna sowi pe bhoktāram: " Emi ni Olori laarin awon Onigbadun" Sarva-loka-maheśvaram: (BG 5.29) Emi ni Olori to gaju awon iwe mimo veda si so be na " īśāvāsyam idaṁ sarvam (ISO 1) gbogbo àbùdá aye yi ti'Olorun ni Sarvaṁ khalv idaṁ brahma. Nkan ti Veda wi ni yen Yato vā imāni bhūtāni jāyante. Ati Olorun ni gbogbo nkan ti wa Janmādy asya yataḥ (SB 1.1.1). nkan ti Olorun so ni yen Sugbon awon eyan o fe gba nitoripe ota ni wan je si Olorun. " Kilode te so wipe Olori to gaju ni Krsna"? Olori na nimi Kilode te so wipe Olorun ni Krsna je, Emi na mo ni Olorun imi.