YO/Prabhupada 0234 - Idayatọ to gaju ni lati di olufokansi Olorun



Lecture on BG 2.4-5 -- London, August 5, 1973

Nrsimhadeva si beere lowo Prahlada Maharaj Bimi ni oun ko oun, to ba fe Prahlada Maharaja si daaun, Oluwa mi, awa ti feran nkan aye yi ju baba mi si ni fe awon nkan aye gan nitorina emi na mo si feran nkan aye yi gan Olorun ni eyin je e si fe bun mi ni abukun Emi na mo si le gba ibukun ti mo ba fe. mo si mo Sugbon kini iwulo gbogbo eyi? Kilode ti ma se beere ibukun mi. Mo ti ri baba mi Alagbara lo je, gbogbo awon angeli si beeru oju pupa re O si di Olori gbogbo agbaye. Eyan to lagbara lo je Sugbon gbogbo owo, agbara, iyi to ni, e ti paari e ni asiko kan soo so Kilode te fe kin tu gba iru awon ibukun bayi? Ti mo ba gba ibukun, igberaga mi asi po ma wa beeri si ni se isekuse, eyin na sile paari gbo ey ni iseju kan Nitorina mi o si fe ibukun aye yi Mo si fe ke fun mi ni ibukun to ma so mi di iranse awon iranse yin. E fun mi ni ibukun to ma so mi di iranse awon iranse yin, kon se pe kin di iranse yi.

O si gbadura to po fun Olorun Lehin gbogbo adura yi, inu Oluwa si tutu. Oluwa mi mo ni ibukun kan ti mo fe ota tinu tinu ni baba mi je si eyin nkan to je ko ku ni yen Mo si fe ke dariji, ko si pa da si ijobo yin. Iwa omo vaisnava ni yen Ko beere nkankan fun ara re O mo wipe Ota tinu tinu ni baba re je si Oluwa, sugbon o si beere ibukun fun baba re. Ki Oluwa si gba ni Ijoba re geg na Oluwa Nrsimhadeva so wi pe " Baba re ni kan ko sugbon baba ti baba re, ti de iran mẹrinla wan, gbogbo wan lo ma pada si ijoba mi Nitoripe lati ebi yi lo ti wa gege na enikeni to ba di Vaisnava (elesin) Oluwa, Onise to daju lo je fun ebi re Nitoripe gbogbo awan ton ni asepo pelu re gbogbo wan lon ma pa da si ijoba Olorun Gege bi eyan to ba pade iku ninu ija Ijoba asi mu awon ebi re Gege na, eyan to ba di Elesin Oluwa, ko si ipo to le ka. Gbogbo nkan to ba fe lo ni. Yatra yogeśvaro hariḥ yatra dhanur-dharaḥ pārthaḥ (BG 18.78). Ibikibi ti Krsna ba wa, ati awon elesin re, iṣẹgun ati ogo lo ma wa ni be. Eleyi daju