YO/Prabhupada 0238 - Olorun dara, Oun lo daju



Lecture on BG 2.3 -- London, August 4, 1973

Ataḥ śrī-kṛṣṇa-nāmādi na bhaved grāhyam indriyaiḥ (CC Madhya 17.136). iwa Krsna yi, bawo ni awon araye sele ni oye re? wan si ni aṣiṣe nitoripe ogbon lasan lon ni gege na awon iwa elesin Krsna, awon Vaiṣṇava. iwe mimo si so wi pe. Vaiṣṇavera kriyā mūdra vijñeha nā bujhaya (CC Madhya 17.136). nkan ti Vaiṣṇavera na ban se eyan to l'ogbn ju laarin wan ko le ni oye nkan ton se Nitorina awa ogbudo farawe awon Olori giga sugbon agbudo se gege bi wan se so Ko le se se. Krsna fe ki Arjuna ja. Iyen o so wi pe agbudo ma to awon eyan ni ja iyen ma buru, eyan to buru ko ni Krsna je ounkooun to ba se dara, Oluwa dara. Oun kooun to ba se agbudo gba be. lehin ounkooun ti eyan ban se lai ni aṣẹ awon olori, iyen o da Ko si ni lati gba aṣẹ lowo enikeni. Īśvaraḥ paramaḥ kṛṣṇaḥ (Bs. 5.1). Oun ni Olori to gaju ko ni iwulo fun ilana lati enikeni. Ounkooun to ba se si da. awa o gbudo ko nipa Krsna bo se wun wa Krsna ju idanwo wa lo Olori lo je si gbogbo eyan Nitorina awon eyan ti o ni, iwoye atinu wa, krsna o le ye wan ni ibi O da bi wi pe O ti eyan lati ja.

klaibyaṁ ma sma gamaḥ pārtha
naitat tvayy upapadyate
kśūdraṁ hṛdaya-daurbalyaṁ
taktvottiṣṭha parantapa
(BG 2.3)

Oro pataki ni Parantapa, "Ksatria lo je, Oba ni e" Ati ko awon oniranu logbon ni ise to ni Ise to ni lati se ni yen. Ko soro pe ofe dariji awon oniranu tẹlẹtẹlẹ awon Oba... adajo ni Oba fun ara re Wan si mu olè wa ba Oba, ti Oba ba fe O le ge ori olè na kuro... gege bi Ise Oba se je teletele ni yen laipe gan ni Ilu Kashmir ti awon eyan ba mu olè, wan mu wa si iwaju Oba ton ba le fihan pe O ji nkan lesekese ni Oba ma ge owo re kuro ko si to ogorun odun to koja gege na iyen je ikilọ fun gbogbo awon ton jale " nitorina ko eni ton jale ni Kashmir Toba je pe enikan so nkan nu, ko seni to ma fowo kan Oba si p'àṣẹ pe ti eyan ba ri nkan ni elele, ema fowo kan Eni to son nkan re nu, a pada wa mu fun ar re. eleyi o to Ogorun odun lo.. oye ka ni iru ifiyajẹ ẹlẹṣẹ bayi Laye isin ifiyajẹ ẹlẹṣẹ bayi o se se mo. wan kin pokunso mo fun awon apaniyan. Iranu ni gbogbo eleyi je. Wan gbudo fi ku pa apaniyan. Koro soro pe edariji Awon apaniyan ni kan ko. Awon ton pan eranko gan e pokunso gbogbo wan Bi Ijoba se je ni yen. Oba gbudo muna.