YO/Prabhupada 0245 - Gbogbo eyan lo fe gbadun iye-ara re



Lecture on BG 2.9 -- London, August 15, 1973

Krsna ni Olori iye-ara wa gbogbo agbaye fe gbadun Oto oro ni wi pe " Ni alakoko eje ki Krsna gbadun. Oga lo je. Lehin an ale gbadun" Tena tyaktena bhuñjīthā. iwe Īśopaniṣad so wipe Krsna ni oniwun gbogbo nkan aye yi Īśāvāsyam idaṁ sarvam: (ISO 1) "Krns loni gbogbo nkan aye yi asise wa ni yen. Krsna ni oniwun gbogbo nkan sugbon eyin rowipe emi mi Oniwun gbogbo nkan itanran-ẹni leleyi Ahaṁ mameti (SB 5.5.8). Ahaṁ mameti. Janasya moho 'yam ahaṁ mameti. itanran-ẹni lele yi. Gbogbo eyan ronu pe " ara mi ni mi" lehin na gbogbo nkna ninu aye yi wa fun igbadun mi asise ilaju wa ni eni leleyi Sugbon agbudo mo wipe " Olorun ni oniwun gbogbo nkan aye yi, iwonba to ba de fun mi ni temi" Tena tyaktena bhuñjīthā. Imoye Vaisnava ko leleyi, Oto oro lo je Koseni to je Olori. Īśāvāsyam idaṁ sarvam. Krsna na so wipe " Onigbdun ni mi, Oniwun ni mo je" Sarva-loka-maheśvaram (BG 5.29). Mahā-īśvaram. Nla ni Itumo maha. Ale so wipe Olori ni awa na sugbon Olori to gaju ni Krsna " Olori awon Olori". Krsna ni yen Kosenikeni to je Olori fu ara re.

Nitorina eyan le s'apejuwe Krsna pelu oruko Hṛṣīkeśa. Hṛṣīkeṇa hṛṣīkeśa-sevanaṁ bhaktir ucyate (CC Madhya 19.170). Itumo bhakti ni wi pe agbudo di iranse Hṛṣīkeśa pelu hṛṣīka. iye-ara wa itumo hṛṣīka. Krsna ni olori iye-ara wa, nitorina awon iye-ara ti moni Krsna ni Oga wan. gege na, itumo bhakti ni wi pe agbudo fi iye-ara fi se ise fun olori wa Itumo bhakti ni yen, ise ifarafun Oluwa Ti eyan ba fi iye-ara re fi se igbadun kama ni yen je, nitoripe ise t'olori kon ni yen Kama ati prema Ife Krsna ni Itumo Prema, ka sise gbogbo nka fun Krsna. Prema ni yen, Ife itumo kama ni wi pe gbogbo nkan wa fun igbadun mi iyato to wa ni yen. awon iye-ara daabi irinṣẹ́ Eyan le se ise lati te arare lorun, tabi ko si ise lati te krsna lorun Sugbon teba si ise fun itelorun Krsna, eyin na ma ni aseyori teba si ise fun itelorun ara yin, ko le si ilosiwaju ninu aye yin Nitoripe itelorun arayin o sese laisi Krsna Hṛṣīkeṇa hṛṣīkeśa-sevanaṁ bhaktir ucyate (CC Madhya 19.170).

Nitorina eyan gbudo ya iye-ara re si mimo Lasiko ta wa, gbogbo eyan fe ni itelorun ara wan Ahaṁ mameti. Janasya moho 'yam (SB 5.5.8). Puṁsaḥ striyā maithunī-bhāvam etat. Gbogbo aye yi.. Eda meeji lo wa laye yi, akọ ati abo ako si ise lati le ni itelorun ara re, gege bi abo na ko si ife gidi... nitoripe, larin okurin ati obirin kosieyi ninu wan to fe se ise fun itelorun ikeji Gbogbo eyan se ise fun itelorun ara wan Obirin niife Okurin nitoripe o fe ki Okurin na le telorun, gege na ni ti Okurin Nitorina ti isoro die ba wa ninu itelorun awon meejeji, wan si gba ikọrasilẹ "Mi o fe mo" Nitoripe itelorun ara wan lon wa tele Sugbon wan si tanrawan je " Mo ni ife re, Moni ife re" Ko soro ife, kama ni gbogbo e. Ninu aye tawa yi, ko soro ife gidi Ife ile-aye yi, iyanjẹ lo je " Mo ni ife re nitoripe O lewa gan, mo de fe gbadun ara mi" Mo gbadun ara mi nitoripe, o si we gan Puṁsaḥ striyā maithunī-bhāvam etat. enile-aye yi ni yen Igbadun ni nkan ti gbogbo aye mo Yan maithunādi-gṛhamedhi-sukhaṁ hi tucchaṁ kaṇḍūyanena karayor iva duḥkha-duḥkham (SB 7.9.45).