YO/Prabhupada 0254 - Guru lole salaaye itumo imoye Veda



Lecture on BG 2.8 -- London, August 8, 1973

Ni alakoko eyan ni gbogbo wa je Krsna na so wi pe... Gbogbo awon jagunjagun wanyi, gbogbo awon Oba wonyi, atiwo na Arjuna Kon se pe teletele awa o wa laaye awa o de le se alaisi ni ojo iwaju Gege na ilana yi lati Krsna emi, ati iwo pelu gbogbo awon oba ton pejo si bi gbogbo wa ti wa laaye teletele Gege ba ase je awon eda ototo, beena ni awon Oba wanyi se je lojowaju gbogbo wa ma si walaaye Nibo wa ni oro alaisi laaye Iranu ni awon eyan ton rope awa je alaisi laaye tele Nitorina lati mo nkan bo se je agbudo sumo krsna gege bi Arjuna se se śiṣyas te 'ham: (BG 2.7) Nisin akeko ni mo je si e. E ko mi leko Śādhi māṁ prapannam. o teriba fun yi. Mio ba yin soro lori ipo kanna Itumo pe enyan gba guru ni wipe oukooun ti guru ba so, agbudo gba Bibeko, ema gba guru. Egbudo mura si. Itumo prapannam niyen Tad viddhi praṇipātena (BG 4.34). Ema fun guru ni idanwo, egbudo teriba fun Guru " mo fe fun ni idanwo lati wo nkan to mo" Kini iwulo pe eyan guru na? Nitorina Arjuna sow ipe, Lehin eyin koseni to le gbami la ninu idamu ti mo ni Yac chokam ucchoṣaṇam indriyāṇām (BG 2.8). Mi o le rori mo nitoripe iye-ara tani, iye-ara eke lo je Iye-ara gidi wa ninu wa. Hṛṣīkeṇa hṛṣīkeśa-sevanam (CC Madhya 19.170) Agbudo sin krsna, Hṛṣīkeśa... Agbudo mo wipe otooro ni Krsna je Nigbana ni ale di iranse Krsna. Hṛṣīkeṇa. Tat paratvena nirmalam. Nigbati iye-ara wa ba ya si mimo Indriyāṇi parāṇy āhur indriyebhyaḥ paraṁ manaḥ, manasas tu paro buddhir (BG 3.42). Ipo ototo lo wa. Anfanni ara eyan, iye-ara ni gbogbo tansi sugbon ti eyan ba ni idari lori iye-ara re, asi wa si beere sini ronu wo Teba kuro ni ipo eyan to ronu wo, ema bosi ipo eyan to logbon Teba koja ipo awon eyan to logbon ema bo si ipo awon eyan ton ya si mimo Ipo awon eyan ton ya si mimo niyen. orisirisi ipo lo wa Ni ipo ara eyan, eyan le bere pratyakṣa-jñānam. itumo Pratyakṣa ni nkan ta le foju ri. Orisirisi ipo imoye lo wa Pratyakṣa, aparokṣa, pratyakṣa, parokṣa, aparokṣa, adhokṣaja, aprakṛta. Imoye ti eyan ba ni lati nkan to foju ri nikan, imoye na o daju nitorina awa fun awon oni sayensi ni idanwo imoye ton ni lati nkan ton foju ri loti wa, imoye lati ṣàdánwò itumo imoye ṣàdánwò ni nkan ti ale foju ri. Pratyaksa Gbogbo eyan so wi pe: Afe ri Olorun" Olorun o kin se nkan aye yi tale fi oju lasan wo, pratyaksa Anubhava ni oruko imi fun Olorun. gege mi inu yara yi, ko si ba sele ri oorun lati bi Sugbon amo pe oorun ran. Bawo le se mo? Kon se dan dan pe ke mo? Awon ọ̀nà imi wa lati mo Iyen je aparokṣa. Pratyakṣa parokṣa aparokṣa. Imoye je adhokṣaja ati aprakṛta, nkan toju ogbon oju wa lo Nitorina ninu Bhagavad-gita wan ko si be: adhokṣaja Nkan ti obgon ori wa o le ka gege na bawo ni asele mo awan nkan ti ogbon ori wa oto. nkan tan pe ni śrota-panthā. Egbudo gba imoye lati awon Veda Imoye Veda lati guru loti wa Nitorina agbudo gba krsna bi guru to gaju, tabi asoju re Nigbana ni gbogbo isoro aye yi ma kuro Yac chokam ucchoṣaṇam indriyāṇām (BG 2.8).