YO/Prabhupada 0290 - Awon eyan ti ko le gbadun ifekufe ton ni l'okan, lati ibe ni ibinnu tin wa
Lecture -- Seattle, September 30, 1968
Upendra: Prabhupāda, kini itumo Ibinnu?
Prabhupāda: ifẹkufẹ ni Itumo ibinnu ti eyan bani ifẹkufẹ lokan, to ba de ni isoro lati gbadun eni na ba bere sini binnu iwa imi fun ifẹkufẹ niyen. Kāma eṣa krodha eṣa rajo-guṇa-samudbhavaḥ. ti eyan ba sini ìjánu, dandan ni wioe eni na ma ni ifekufe lokan eyan na asi binnu to ba le fun lati gbadun ifekufe to ni lokan. lehin, idamu ma mu eni na lehin na eyan ma sonu. praṇaśyati Nitorina agbudo gbiyanju lati ni idari lori ibinnu wa pelu ifekufe lokan wa Itumo idari yi niwipe agbudo mu okan wa sinu awon iwa rere, agbudo fi ìjánu sile. Ipo meta lowa ninu ile-aye yi; inurere, ìjánu ati aimokan. Nitorina enikeni toba fe mo ni pa Olorun eyan na gbudo fi okan re lori ipo inurere. bibeko kolesese Nitorina awa sin so fun awon ton keko lodo wa pe " ema se bayi, ema se yen" Nitoripe wan gbudo fin okan wan lori ipo inurere, bibeko kosi bo sele ye wan awo eyan ton wa lori ipo ijanu tabi aimokan, kosi bon seleni oye imoye Krsna Gbogbo aye si wa labe ipo ijanu ati aimokan sugbon ilan wa si rorun gan, teba tele awon ofin merin te si korin Hare Krsna lesekese lema koja awon ipo ile-aye yi gege na lori ipo Ijanu ni Ibinnu wa.