YO/Prabhupada 0292 - E waadi Olorun pelu imoye ti eyin ni
Lecture -- Seattle, October 4, 1968
Prabhupāda:: Govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi.
Olufokansi: Govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi
Prabhupāda:: Se fun ni iranlowo? Beeni Eda to gaju gbogbo eda lawa fe (erin) Awa o fe elomi. Govindam ādi-puruṣaṁ. Sugbon t'eyan ba le mu eda to gaju gbogbo eda lo, lehin na eni le mu gbogbo eyan fun apeere ninu awon Veda ni Upanisad wan so wipe, yasmin vijñāte sarvam evaṁ vijñātaṁ bhavanti. teba leni oye nipa Olorun, eti ni oye gbogbo nkan niyen Kosi iwulo pe eyan fe ni oye nkanmi. Yasmin vijñāte sarvam etaṁ vijñātaṁ bhavanti. Gege na Bhagavad-goa si sowipe,
- yaṁ labdhvā cāparaṁ lābhaṁ
- manyate nādhikaṁ tataḥ
- yasmin sthito na duḥkhena
- guruṇāpi vicālyate
- (BG 6.20-23)
Gbogbo eyan lon wa igbese aye to ma fun ni alafiaa Ipinnu gbogbowa niyen. Kiode te sen tiraka? ipinnu kanna la fe de gege bi awon ton sere bọọlu apa meejeji lofe isegun lori ikeji gege na gbogbo wa lafe ni nkan sugbon lati ipo to yato si ara wan kon se gbogbo eyan lon le nkankanna. awonmi wa idunnu ile-aye yi, awonmi fe oti amupara awonmi fe ni asepo t'okurin ati obirin, awonmi wa owo awonmi wa imoye, awonmi wa nkan to po sugbon nkan soso lo wa taba le ni imoye Olorun, gbogbo wa lama ni itelorun lehin na " ama sowipe mio fe nkankan mo" Svāmin kṛtārtho 'smi varaṁ na yāce (CC Madhya 22.42). apeere to po wa gege bose ri niyen. teba ni oye Krsna, imoye teni se pataki gan, etini oye gbogbo nkan etini oye sayensi, etini oyue isiro, etini oye fisiki, .. ẹkọ nipa eledumare, imoye, ijuwe akọsilẹ, gbogbo nkan. Osi da gan Bhagavata so wipe saṁsiddhir hari-toṣaṇam (SB 1.2.13). ounkooun ise teyan ban se, ko si isoro sugbon teba le wa Olorun pelu imoye teni, ilosiwaju teni niyen Oni sayensi leje, kosi nkan to baje pelu ise sayensi teyin se ema ri Olorun na. Ilosiwaju yin niyen oniṣowo leje? pelu owo teni ewa Olorun Ololufe leje? Ewa Olori awon Ololufe eyin wa nkan to dara, to lewa teba ti ri Olorun gbogbo nkan tenwa ema ri ninu Olorun eda toni lewa ju ni Itumu Krsna teban wa nkan lehin teba ri Krsna gbogbo nkan tenwa ema riwan Nitorina ni oruko re se je Krsna.