YO/Prabhupada 0299 - Eni toje Sannyasi ko le pade iyawo re mo
Lecture -- Seattle, October 4, 1968
Tamāla Kṛṣṇa: Prabhupāda, lehin igbati Caitanya gba sannyāsa, ninu iwe eko Caitanya wan sowipe o loba mama re. Mosi rope enyan toje sannyāsi ko lese bayi.
Prabhupāda: Rara, eyan toje sannyāsī kole pada loba iyawo re eyan toje sannyāsī ko gbudo pada sile rara, ko gbudo ri iyawo re mo sugbon o le pade... kon sepe Caitanya Mahāprabhu pada lo sile, oni nkan tosele Advaita Prabhu lo mu mama Caitanya wa ri lehin igbati Caitanya Mahāprabhu, gba sannyasa odabiwipe oyawere fun Krsna asi lo s'odo Ganges laimo pe Ganges lo wa Asi rope " Odo Yamuna. Mofe lo si ilu Vrndavana gege na Nityananda Prabhu si ran Okurin kan mofe tele Caitanya. E sofun Advaita pe komu ọkọ oju-omi kekere wa si ghāṭa kobale mu losi ile re inu Caitanya Mahāprabhu si dun lehin na o ri Advaita ton duru de lori ọkọ oju-omi osi bere lowo Advaita, kilon se nibi? Odo Yamuna leleyi Advaita si sowipe " Oluwa mi, ibikibi teba wa ibe na ni Yamuna wa, ejo e telemi" lehin na o tele Advaita losi ile re Nigbato dele oso fun Advaita kilode tose paro funmi, omumi wa sile re. Vrndavan ko lawa. kilode? Kosi wahala, Oga e sese de (erin) .. ejo ko lesekese lo ran okurin loba iya re nitoripe omowipe Caitanya Mahaprabhu tigba sannyāsa kode ni pada wasile mo iya re si feran re gan, nitoripe oun ni omo-okurin soso ti iya re ni nitorina lose pada iya re Advaita losi to gbogbo eleyi lesekese ti iya re de, Caitanya Mahaprabhu si dobale fun Omo-okurin odun merinlelogun lo je, nitorina nigbati Iya re ri pe O si gba sannyasa iyawo re si wa nile, gege bi obirin o bere sini sunkun Caitanya Mahaprabhu si bere sini so awon oro to dun lenu O sowipe " Iya mi, eyin lefunmi ni ara timoni, gege na oyekin lo arami ninu ise teyin se Sugbon ode nimoje, moti se asise. E dariji mi gege na nkan to sele nibe si mu ibanuje wa