YO/Prabhupada 0301 - Awon eyan ton gbonju - Gbogbo wan lon jo



Lecture -- Seattle, October 2, 1968


Agbudo ni oye nipa egbe imoye Krsna lati awon eko Oluwa Caitanya Ni Odun ogorunmaarun atijo, osi farahan ni Ilu Bengal ninu igberiko Orile-ede India. O se waasu imoye Krsna ise apifunni to muwa niwipe, gbogbo awon ton bi sinu orile-ede India gbudo gba imoye Krsna sokan wansi pin kakiri ni gbogbo agbaye. Lati jise yi, awa ti wa si orile-ede yi ibeere mi niwipe, ke gbiyanju lati ni oye imoye Krsna yi, pelu gbogbo ogbon teni. Ema kan tele lai roriwo. Elo ogbon, ati ibeere, imoye, ariyanjiyan,- eda eyan leje - ema ri pe o dara gan, ko soro. Ati te jade iwe ton pe ni, Eko Oluwa Caitanya, pelu orisiris iwe na Egbiyanju ke ka wan. asi ni iwe irohin ton pe ni "Back to Godhead. nitoripe awa njo, iyen owipe alaironu eyan laje ijo tawan jo si se pataki gan: teba bawa jo eyin na ma ribe Kon se awon asiwere kan ton jo. rara awon eyan ton logbon ju lon jo. Osi dara gan pe awon omode na lese- seri bi omode to wa nibi- gbogbo agbaye lese. E wa, ke korin Hare Krsna, ke jo lehin na ema ni ilaju. O si rorun gan. Kosi idi fun imoye to legan, tabi, ka soro pupo nkan to rorun. Kilo de rorun? Alagbara ni Olorun, gbogbowa la mobe. nkankan na laje pelu alagbara yi taba si ni asepo pelu alagbara, awan ma di alagbara gege bi ara yin, apa kekere ara yin, bi ika owo, ose pataki bi gbogbo ara yin. sugbon teba yo apa kekere yi kuro lati odindin ara yin, kole wulo mo. Ko wulo. ika owo, apa kekere ara yin loje sugbon teba ni irora, ele na owo to po si Ema sonwo fun ologun kobale pari irora na ti ologun ba sowipe, " agbudo, kilon pe na, " ge kuro, bibeko gbogbo ara yin ma ni isoro" teba de ti ge kuro, ko wulo mo. ko wulo mo. egbiyanju lati ni oye oro yi. teba ni ẹrọ itẹwe, ti ìdè re ba sonu, kole sise mo. teba gbe lo si ibi atunṣe. asondollar mewa. ema sonwo lesekese. sugbon ìdè kekere yi toba kuro ninu ero itewe, ko niwulo mo Gege na nkankanna laje pelu Olorun taba sise pelu Olorun, itumo yen niwipe teba sise ni imoye Krsna tabi Olorun pe " nkankanna nimo je..." gege bi ika owo ton sise pelu ara mi tinba ni irora die mole mo gege na teba sise ninu imoye Krsna, ile aye yin mani ilosiwaju teba si yo ara kuro ninu imoye Krsna, isoro ma wa. Isoro ma wa ai ni apeere to po lojojumo ninu iwaasu wa agbudo gba imoye Krsna yi taba fe kin inu wa dun, lehin na ale pada si ipo wa. Egbe Imoye Krsna niyen