YO/Prabhupada 0313 - All Credit Goes to Krishna



Lecture on SB 3.26.42 -- Bombay, January 17, 1975

Ise awaon elesin ni lati fun Oluwa logo. Wan o so fe keni kankan yin wan logo. Ni otooro kosi nkankan lati fi yin wan logo. Krsna loye ka yin logo. Awon elesin o ni jeke yin wa logo Osi le je eyan pataki sugbon koni gba Awon ise pataki ton se wa lati yin Krsna logo. Kon se bi awon eyan aye isin ton fe kon yin wan logo. Rara. Sva-karmaṇā tam abhyarcya siddhiṁ vindati mānavaḥ (BG 18.46). Sva-karmaṇā. Ele se ounkoun teba fe bi ise. Sugbon ninu ise teyin se egbudo jeki Krsna wa bi Olorun, nitoripe ounkooun ton sele, labe Idari Krsna lon sele. Orun ran lojojumo, l'asiko to ye kosi gbona ju, tabi ko tutu ju, bose ye ko je, uttarāyaṇa, dakṣiṇāyana - gbogbo nkan lon sise dada, labe idari Eledumare. Mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ (BG 9.10). Ema rowipe Orun sise lasana fun ara re. Krsna ni oga re. Yasyājñayā bhramati sambhṛta-kāla-cakraḥ. Nkan pataki to lagbara l'orun je ninu agbaye wa yi. Aimoye Orun to wa. Orun kan soso leyeyi, osin jise Krsna. Yac-cakṣur eṣa savitā sakala-grahāṇāṁ rājā samasta-sura-mūrtir aśeṣa-tejāḥ. Aśeṣa-tejāḥ, aimoye ina, aimoye oru. Aśeṣa. Aśeṣa-tejāḥ. Kosi nkankan to le dabi Orun wa yi. Kosi nkan na ninu agbaye wa. Fun aimoye odun , lat'orun ni gbogbo ina ati oru tin jade, sugbon kosi dinku. gege boseje lati ibere lose wa, lehin igba to fun wa ni gbogbo ina ati oru yi, gege boseje losi wa.

gege na tin nkan aye yi le fu wa ni aduru ina ati oru yim tosi wa boseje, gege na Olorun na, pelu agbara re le se nkankana. Asi wa boseje. Kosi bosele dinku. Pūrṇasya pūrṇam ādāya pūrṇam eva avaśiṣyate (Īśo Invocation). Tawa bale ri nkan aye yi, ton sise lati aimoye odun tio dinku- Oru sin jade, ina sin jade, Kilode t'Olorun o le se nkankan? Nitorina ni Īśopaniṣad se sofun wa wipe pūrṇasya pūrṇam ādāya pūrṇam eva avaśiṣyate. teba gba gbogbo agbara Krsna lati Krsna, asi wa bose wa teletele. Sugbon ni asiko tawayi , oma ya yin lenu Orisirisi awon " Olorun aye isin" lowa, Mi o fe daruko. Sugbon osi ni Olorun aye isin kon to wa, to fun elesin re ni agbara re, lehin igba to pada sokan re o bere sini sukun Elesin re bere loo re Oluko, kilode teyin sen sukun,? " Oti tan funmi nisin, moti fun e ni gbogbo agbara mi. Moti fun e nigbogbo nan ti moni, otan funmi niyen" Nkan emi koleleyi. Nkan aye yi niyen. Moni rupees Ogorun, tin ba fun yin, owo ma tan ninu apo mi. Sugbon bayi ko ni Krsna se rei. Krsna le da aimoye Krsna imi , sugbon asi wa bose wa. Krsna ni yen. Agbara re o le tan. Nkan ton pe ni pūrṇasya pūrṇam ādāya pūrṇam eva avaśiṣyate (Īśo Invocation).

Iru afarawe yi ko le ranwa lowo. Olorun gidi,

īśvaraḥ paramaḥ kṛṣṇaḥ
sac-cid-ānanda-vigrahaḥ
anādir ādir govindaḥ
sarva-kāraṇa-kāraṇam
(Bs. 5.1)

Sarva-kāraṇa-kāraṇam, kole tan lailai. Wan si sowipe,

yasyaika-niśvasita-kālam athāvalambya
jīvanti loma-vilajā jagad-aṇḍa-nāthāḥ
viṣṇur mahān sa iha yasya kalā-viśeṣo
govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi
(Bs. 5.48)

Aimoye awon agabaye ton jade ninu ateegun eemi re, Lehin toba de mii sinu gbogbo awon agbaye yi ma tan. gege bayi ni awon agbaye yi sen jade. Jagad-aṇḍa-nāthāḥ. Jagad-aṇḍa-nāthāḥ. Jagad-aṇḍa, agbaye ni itunmo re je, ati natha, Olorun agbaye, itumo re ni Olorun Brahma. Osi ni igbaye to wa gbe fun ninu aye yi. Kini asiko na? Asiko ateegun eemi Maha- Visnu.