YO/Prabhupada 0323 - Creating a Society of Swans, Not of Crows



Lecture on SB 3.25.12 -- Bombay, November 12, 1974

pavarga ni ile aye yi je. teba fe fi ipaari si eleyi, apavarga loje. Nibi oruko to je ni apavarga-vardhanam, basele jeki ifarasi igbala wa posi. Awon eyan ti yode to jepe kosi bonsele ni oye nioa nkan ti igbala je. Kole ye wan. gege bi awon eranko. teba sofun eranko pe igbala wa, kilo fe mo? Kosi bosele ye. Fun iru eda bayi ko. Gege na ile-aye tawayi dabi tawan eranko Awon eyan o mo itunmo apavarga tabi igbala. Wan o mo. Sugbon asiko kan wa tojepe awon eyan mo wipe ile aye eda wa fun apavarga. Apavarga, lati kuro ni ise pa, pha, ba,bha,ma. apavarga-vardhanam niyen. gege na awon ibeere Devahuti ati awon idaaun, ti Kapiladeva ma fun, apavarga-vardhanam niyen. Nkan ta fe niyen. Ilana to wa ninu awon Veda niyen. Tasyaiva hetoh prayateta kovidah. Gbogbo eyan gbudo gbiyanju fun apavarga. gbogbo eyan gbudo gbiyanju. " bawo ni mosefe toju ara mi?" Awon sastra o fi be soro to le lori itoju ara, pe " egbu do sisse fun itoju ara." Sastra sowipe, " Oma wa. Oti wan be gan. Asi wa." sugbon awa o nigbagbo bayi, " Olorun ti funwa, oun fun awon eranko, awon eye, awon igi, gbogbo eyan, kilode ti kosele funmi? Ejekin lo asiko mi fun apavarga." Awon eyan o nigbagbo. Kosi ikeko bayi mo. NItorina loye ke ni asepo pelu awon eyan to lori, ema ba awon eyan bi eye kurro rin, sugbon awon bi siwani. Lehin na ema logbon.

Lati da awon eyan ton da bi eye siwani ni itumo fun egbe imoye Krsna yi, awa o fe awon kuroo. Awon eye kuroo o fe gbo nipa eto na. Awon nkan ajeko lon fe, idoti. Nkan ton feran niyen. Punah punas carvita-carvananam (SB 7.5.30). Punah punas carvita-carvananam. tawa ba ti so nkan nu... Taba jun tan ,asi so ewe na nu. Awon ounje ajeku kan wa lori awon ewe yi, nkan ti awon eye kurro ati aja feran niyen. Okurin kankan to logbon o le losi be. Sugbon awon kuroo wanyin ma lo sibe. Bi ile aye yi se ri niyen. Punah punas carvita-carvananam (SB 7.5.30). Ka ma je ajeku. gege beya to je ireke to tu danu sori titi. teyan mi ba wa je nkan to ti tu danu yi, ode loje. Ogbudo mo wipe, " Kos'omi kankan mo ninu e, kini mofe ri ninu nkan bayi? Sugbon eranko lonje. Wansi fe je. gege na awujo ile-aye yi, dabi awon ton tun ajeku je. Baba si ran omo re losi ile-iwe lati le ko bosele pa owo, asi fe iyawo fun, sugbon o mowipe, "Ise yi moti se, moti pa owo, moti fe yawo, moti bimo, sugbon mio ni itellorun. Kilode ti mofe k'omo temi na se iru ise bayi? Nkan ton pe ni ka ma tun ounje ajeku je. A tun je. " " Ko temi lorun, sugbon kilode ti mo fe k'omo mi sise na?" Baba gidi o ba ki omo re je ounje ajeku. baba gidi niyen. Pita na sa syaj janani na sa syat, na mocayed yah samupeta-mrtyum. Elaa magboyun gidi to wa niyen. Okurin o gbudo di baba, obirin o gbudo di'ya afi tonbale fun awon omo wan nigbala lati owo iku. ise baba ati iya niyen.