YO/Prabhupada 0357 - I Want to Begin One Revolution Against Godless Civilization
Morning Walk -- December 11, 1973, Los Angeles
Prabhupada: Ara mi ofi be ya, sugbon kilode ti mon gbiyanju? Ise apifunni mi niyen. Mofe iyipada kan sile. Awujo wan tio ni Olorun kankan, si keji. Ise mi niyen. Awon ilu America lonma daju lati bonsele tesiwaju, kon si di olori. Nitoripe Olori ni wan tele, sugbon nisin wan gbudo di olori to daju, gege na idunnu ma wa sinu gbogbo aye yi. Mole ko wan bonsele se. Ti awon okurin ijoba ba wa bami, mole kowan bonsele di Olori agbaye yi. Olori to daju, konse Olori eke. Nitoripe Olorun si funwan ni orire to po gan. Egebe wa yi si beere ni Ameerica. Ilu New York nimoti bere. gege na oye ki joba mu ni pataki (Isinmi)
Hṛdayānanda: Eyin sowipe America lose pataki ju?
Prabhupada: Beeni.
Hṛdayānanda: Se ro pe..
Prabhupada: Itorina ni mo se wa s ilu yin......
Hṛdayānanda: O da be..
Prabhupada: ....itoripe eyin lese pataki ju. Nisin pelu iranlowo mi oye d'eyan pataki gidi, konse eke.
Hṛdayānanda: Se kin duro sibi kin se waasu.
Prabhupada: Ah?
Hṛdayānanda: toba se pataki bayi mole joko sibe kin se waasukin si ran Rupanuga lowo.
Prabhupada: Beeni. E jiki gbogbo eyan ni orile-ede ni imoye Olorun, nitoripe wan ti fenu wan sowipe, " Olorun nimo gbekele" Nisin wan gbudo mu nipataki. Kini itumo "Olorun"? Kini itumo " Igbekele"? Emu ise ni pataki tawan se yi. Ninu Olorun la gbekele; nitorina lawa se fun ni gbogbo aye wa. Igbekele ninu Olorun niyen. Konsepe eyin fa siga ninu yara eden sowipe egbekele Olorun. Iru igbekele wo niyen. Igbekele gidi.