YO/Prabhupada 0379 - The Purport to Dasavatara Stotra
Purport to Dasavatara Stotra, CD 8
Pralaya-payodhi-jale dhṛtavān asi vedam. orin ti akewi Vaisa=nava Jayadeva Gosvami ko niyen. Koko oro towa niwipe, nigbati gbogbo aye fe tan, ile aye yi si kun fun omi. Nigbati gbogbo aleyi ma paari, koni s'omi, gbogbo ile aye yi ma gbe pelu orun. Orun asi lagbara tokoja mejila eyi to wa nisin. Bayi gbogbo omi ninu aye yi ma gbe tan. Nitorina gbogbo eda ninu ile aye yi ma ku, lehin na , nitori orun yi, gbogbo nkna ma jo tan. ojo ma ro fun odun ogorun, ojo to tobito omi latinu imu erin, gbogbo agbaye asi kun fun omi. Nkan ton pe ni pralaya-payodhi. L'asiko ipaari aye yi9, pralaya, gbogbo agbaye yi.. Gege bi isin o kun fun ategun, nigbana a kun fun omi. Nigbana Olorun asi wa gbe awon Veda ninu oko-oju omi, wansi so oko-oju omi yi si apa eja nla. Irisi Krsna ni eja nla yi je. Nitorina losen s'aadura, keśava dhṛta-mīna-śarīra jaya jagadīśa. So mīna-śarīra. Eyi to kan ni kṣitir iha vipulatare tiṣṭhati tava pṛṣṭhe dharaṇi-dhāraṇa-kiṇa-cakra-gariṣṭhe. wansi po okun yi, irisi Olorun to kan ni ijapa. Wan si gbe meru-parvata sori eyin ijapa na, tabi gbogbo aye yi ma wa lori eyin ijapa yi. eda keji leleyi Eja ni t'alakoko, lehin na ijapa. Lehin na varāha-avatāra.. Esu kan tonpe ni Hiraṇya, Hiraṇyakaśipu ati Hiraṇyākṣa. Pelu iwa esu re asi ju Ile aye yi sinu omi-okun Garbho. Okun wa ninu agbaye yi. Idaji agbaye yi kun fun Garbhosamudra, lori ibe ni Garbhodakaśāyī Viṣṇu wa, lati ara re ni idodo na ti hu, tosi fun Brahma ni ibimo. gbogbo awon isogbe wanyi wa lori awon apa igi t'alakoko, ton jade lati'kun Garbhodakaśāyī Viṣṇu. Osi ni esu kan pelu oruko Hiraṇyākṣa, oun lo fi ile aye yi sinu omi, nigbana ni Olorun si jade bi eda Varaha Varaha si jade bi kokoro lati imu Brahma, nigbato fi sori owo re, osi bere sini tobisi. Bayi lose ni ara to tobi gan, pelu eyin-erin re lofi mu ile-aye yi jade kuro ninu omi okun Garbho. Nkan ton pe ni keśava-dhṛta-varāha-rūpa. iye to kan ni tava kara-kamala-vare nakham adbhuta-sṛṅgaṁ dalita-hiraṇyakaśipu-tanu-bhṛṅgam. Hiraṇyakaśipu, esu imi leleyi tosi fe wa ninu aye lai ku. Brahma si fun niibukun pe koni ku lori ile, tabi ofurufu tabi ninu omi. Gege na, lati jeki gbogbo awon ibukun ti Brahma fun, kon wa bonse je.. Olorun Krsna si fe ki oro awon elesin re daju. Brahma si fun ni ibukun pe, "Beeni, iwo o ni ku lori ile, tabi lori omi, tabi lori ofurufu." Sugbo Nṛsiṁha-deva si wa sinu aye bi idaji-kiniun, idaji-okurin, nitoripe Hiraṇyakaśipu si gba ibukun lati Brahman pe koni ku l'owo okurin tabi eranko. gege na lose yosi bi eda teyan o le pe ni okurin tabi eranko, osi gbe esu yi sori itan ese re, konse ile, omi tabi ofurufu. kosi fe pa pelu ohun-ija kankan. Nitorina ni Olorun se pa pelu awon ekana re. Eyan o le sowipe ohun-ijagun l'ekana je. Osife tan Brahma je, sugbon Olorun si l'ogbon ju lo O si tan Hiraṇyakaśipu je, lehin na o fi ku pa. Keśava dhṛta-narahari-rūpa. Dalita-hiraṇyakaśipu -tanu -bhṛṅgam. gege bi ekana wa, ale pa awon kokoro pelu e. Ele pin awon kokoro simeji pelu ekana yin. Gege na, Hiraṇyakaśipu si je esu nla, sugbon o da bi kokoro kekere niwaju Olorun, Olorun si pa pelu ekana re.