YO/Prabhupada 0381 - The Purport to Dasavatara Stotra
Purport to Sri Dasavatara Stotra -- Los Angeles, February 18, 1970
Pralaya-payodhi-jale-dhṛtavān asi vedam, vihita-vahitra-caritram akhedam. Eni ni ojo ifarahan ti Olorun Krsna ni irisi re bi elede. Osi yo ile-aye yi kuro ninu omi okun Garbhodaka nigbaton ti boo inu re. Agbaye ti awan wo yi, idaji leleyi. Idaji keji kun fun omi, ninu omi yi ni Garbhodakaśāyī Viṣṇu wa. Esu kan, Hiraṇyākṣa, si ti ile aye yi sinu omi na, sugbon Olorun Krsna si yo isogbe aye yi kuro pelu irisi re bi elede. Eni ni ojo tti eleyi sele, Varāha-dvadaśī. Wanpe ni Varāha-dvadaśī. Eni yi osi da ka korin, ka awon orisirisi eda Olorun ninu agbaye yi. Eja ni eda t'alakoko. Jayadeva Gosvami lo s'adura wanyi. O si ni akewi Vaisnava, to wa sinu aye yi l'odun orundinlegberin seyin ki Olorun Caitanya to farahan. Elesin to ga gan loje, iriki re tose pataki ju ni Gīta-govinda., osi lokiki nigbogbo agbaye. Gīta-govinda. Gīta-govinda ni koko oro nigbati Krsna ban fon fere nipa Radharani. koko oro Gita-govinda niyen. Akewi yi na, Jayadeva Gosvami, losi s'adura yi, pralaya-payodhi-jale-dhṛtavān asi vedam. O sowipe, " Olorun mi, nigbati ile aye yi fe paare, omi si kun ninu e. Nigbayen leyin si mu awon Veda ninu oko-omi. eyin lesi mu oko-omi yi danni koba ma wonu omi pelu irisi eja nla yin." Ni alakoko wan mu eja yi ninu koko bi eja kekere. leyin igba die osi dagba si , wansi fisinu koko omi nla. Bayi ni eja na se bere sini dagba si. Eja yi losi sowipe " ile aye yi ma paari. Mu gbogbo awon Veda sinu oko-omi, masi fun ni idaabo." Gege na Jayadeva Gosvāmī sin gbadura, " Olorun mi, eyin te toju awon Vedas, nigbati aye yi fe tan, ninu irisi yin bi eja." Eyi to kan ni Kūrmāvatāra. Wansi po omi okun. L'apa kan awon orisa, ni apa keji awon esu. Ori-oke nla tonpe ni Mandara-parvata ni irin ton fi ro omi-okun yi. Lori eyin Olorun ni irisi re bi ijapa niibi isinmi fu ori-oke yi. o sin gbadura wipe " Eyin si wa bi ijapa lati di ibi isinmi. Eleyi si sele nitoripe eyin re sin nyún E. Eyin ti gba ti ori-oke Mandara yi, ko nyún eyin re." Irisi Olorun to kan ni Varaha, ti elede. osi fun agbaye yi nigbala pelu eyin-erin re, osi fi gbogbo agbaye yi sori eyin erin re. Eyin na le rori wo lati mo bose tobi to. gbogbo agbaye yi nigbana si jo osupa toni ila lori re. Beena keśava dhṛta-varāha-śarīra. " Olorun mi, eyin ti wa bi elede nla yi. Eje kin saadura mi si yin." Irisi kerin ni Nṛsiṁha-deva. Nṛsiṁha-deva si farahan lati fun Prahlāda Mahārāja nigbala, omo odun marun losi je Baba re to j'esu sin fun ni isoro. Beena, o jade ninu opo ile na, bi idaji okurin, idaji kiniun. nitoripe Hiraṇyakaśipu gba ibukun lati Brahmā, pe okurin kankan tabi eranko o le fi ku pa. Olorun si wa bi eda tio kin se okrin tabi eranko. Iyato laarin ogbon wa ati t'Olorun niyen. ain rowipe a le tan Olorun je pelu ogbon wa, sugbon Olorun l'ogbon ju wa lo. Hiranyakasipu si fe tan Brahma je pelu awon ibeere tio da. Nialakoko, o fe wa laaye lai ku. Brahma sofun, " Kolese se, emi gan o le wa laaye lai ku. Koseni kankan ninu ile-aye yi tio ni ku. Kolese se." Esu ni Hiraṇyakaśipu je, awon esu si l'ogbon gan. O si rowipe mole gba ona toyato lati le gbe lai ku." O si gbadura si gbadura si Brahma pe " Daakun funmi ni ibukun yi, pe okurin tabi eranko o le paami, " Brhama sowipe, " Beeni, boseje niyne." "Mio ni ku lori ile, lori ofurufu, tabi lori omi." Brahma sowipe, "Bee ni." "awon ohun-ijagun aye yi o ni paami." " O daa be." bayi, osi fi ogbon fi yipo lati de ono tama jeko wa lai ku. Sugbon Olorun si l'ogbon tojepe, lai fowokan awon ibukun t Brahma fun, osi pa. O sowipe " Wan o ni pami ni oju ojo tabi lale." Brahma sowipe " Beeni." Beena wansi pa ni irole, laarin ojo ati ale. Eyin o le sowipe ojo ni tabi ale. Wansi fu ni ibukun pe " Wan o ni pa mi ni ofurufu, lori ile ati lori omi." wansi gbe sori itan kon to pa. wansi fun ni ibukun pe " ohun-ijagun teyan se tabi ohun-ijagun t'Olorun se kole pa mi." Wansi fun, " O daa be." Wansi fi ekana pa. Beena, gbogbo awon ibukun ton fun si wa paa, sugbon wansi fi ku pa. Gege na, ale s'eto, ale ni ilosowaju ninu imoye sayensi, sugbon iseda a si pa wa. Koseni to le sa kuro. pelu ogbon ori wa, awa o le sajade. Awon ofin merin ile aye yi ni ibimo, oku, ojo arugbo ati aisan. Ale da awon ogun sile, awon ohun ijagun, awon ona orisirisi, sugobn eyin o le jade kuro ninu awon ofin merin wanyi, kosejo agbara yin. Itan-akoole Hiranyakasipu yi si jerisi. Hiraṇyakaśipu je ikan ninu awon eyan ton feran eto oro aje, osi fe gbadun fun ayeraye, sugbon kole gbe. fun igbana. Gbogbo nkan ti tan.