YO/Prabhupada 0409 - There is no question of interpretation in the Bhagavad-gita



Cornerstone Laying -- Bombay, January 23, 1975

wanti fun egbe wa yi ni ase, osi ni ise to po gan ton se. Nitorina ibere ti moni fun awon olugbe Bombay, nipataki awon ton je omo egbe pelu wa, niwipe kon gbiyanju ati wo basele jeki egbe wa yi ni ilosiwaju ni ilu Bombay. Beena awon obirin at'Okurin wa nibi. Ounkoun t'awa n'se daju, kosi nkankan toje nkan afori da. Gbogbo daju gege boseje ninu Bhagavad-gita. Lori iwe Bhagavad-gita lati da egbe yi - Bhagavad-gita bose je. Awa o se isotunmo. Isotunmo iranu, nitoripe.... Mosi sowipe " iranu," nitoripe kilode teyin fe se isotunmo si oro Krsna? Se mo ju Krsna lo? Tabi se Krsna fi apa kan sile funmi lati se isotunmo mi si? Beena kini iwulo Krsna? Tinba se isotunmo temi, timo rowipe mo ju Krsna lo, iranu niyen. Bawo ni mo sele ju Krsna lo? Ti awa ba fe gba anfaani Bhagavad-gita yi, agbodo gba Bhagavad-gita gege boseje. Gege bi Arjuna se gba, lehin igba to gbo Bhagavad-gita, o sowipe, sarvam etam ṛtaṁ manye: " Moti gba gbogbo oro yi, Kesava, ounoun to ba so. Moti gba gbogbo e, lai yipada." Oye Bhagavad-gita leleyi, konsepe kin gba Bhagavad-gita kin se isotunmo iranu temi si ki awon eyan ba le gba imoye temi. Bhagavad-gita ko niyen. Kosejo pe eyan se isotunmo si Bhagavad-gita. Teyan o ba ni oye lehin na lele se isotunmo. Ti awon nkan ba daju... Tin ba sowipe, " gbohungbohun leleyi," gbogbo eyan lo mope gbohungbohun leleyi. Kini'di lati se isotunmo si? Ko wulo. Iranu wa niyen, lati ko awon eyan ni ikoku ko. Kole si isotunmo kankan si Bhagavad-gita. Gbogbo nkan ninu e lo daju. Gege bi Bhagavan Krsna se so... Krsna o sowipe " E di sannyasi ke fi gbogbo ise yin sile." Rara. Krsna sowipe, sva-karmaṇā tam abhyarcya saṁsiddhiḥ labhate naraḥ (BG 18.46). E duro si ibi tewa. E sise yin lo. Kosi'di lati kuro. Sugbon e fokan yin si Krsna ke ni ilosiwaju ninu aye yin. Oro ifiranse Bhagavad-gita leleyi. Bhagavad-gita o le da idamu sinu awujo awon eyan tabi ninu eto mimo. Rara. Ogbodo wa ni pipe gege bi awon olori se fe. Olori to si daju lo ni Krsna.

E gbiyanju lati jeki ile-ajosin yi ni ilosiwaju eyin arakurin at'obirin Bombay. Awa sini ibi to da. Asi fe ko ile-ajosin keba le wa lati lo asiko die pelu wa l'opin ose. Gbogbo awon Okurin at'obirin tio sise mo, ele wa sibi awa sini aye fun gbogbo yin. sugbon e gbiyanju lati ti awon ofin Bhagavad-gita fun gbogbo aye. Ibukun orile-ede India niyen. Ife okan Caitanya Mahāprabhu niwipe enikeni ton ba bi si India, bi eda eyan, konse bi ologbo ati aja... Ologbo at'aja o le se nkan gidi fun awon eyan. O sowipe,

bhārata-bhūmite manuṣya-janma haila yāra
janma sārthaka kari' kara para-upakāra
(CC Adi 9.41)

"Enikeni toba ti ni ibimo re bi eda ni ilu India, Bhārata-bhūmi, e gbiyanju lati jeki ile aye yi ni ilosiwaju." Nitoripe eyin ti ni ipo yi, besele jeki ile aye yin ni ilosiwaju. Bhagavad-gita leleyi. E gbiyanju lati ni oye re, e jeki ile aye yin ni ilosiwaju, lehin na e pin oro ifiranse yi si gbogbo agbaye. paropakāra niyen. Beena ni otooro, India ati awon olugbe India, won wa fun paropakāra. Koye ka tan awon eyan je. Ise wa ko niyen. Niotooro nkan ton sele iyen. Gbogbo awon eyan ton jade lati India. wan jade lati lo tan awon eyan je. Sugbon asiko talakoko leleyi ti India ti fun awon ara'ta ni imoye mimo. Awa na le jerisi. Asi fun awon eyan, aw a o bere nkankan. Awa o toro je lowo won, " E funmi ni iresi, e funmi lowo, e funmi ni nkan bayi bayi." Rara. Ati fun won ni nkan to daju, wan si mu ni pataki. Bibeko, kilode ti awon okurin at'obirin wanyi, wan sise fun egbe imoye Krsna yi? O ni nkan ton ri, nkan gidi. Ise yi si lagbara, agbara to da. won o ronu bi olugbe America tabi Canada tabi Australia. Awa na o ronu mo bi olugbe India. lori ipo mimo nkankan ni wa.

vidyā-vinaya-sampanne
brāhmaṇe gavi hastini
śuni caiva śva-pāke ca
paṇḍitāḥ sama-darśinaḥ
(BG 5.18)

Akeko to daju leleyi. Ātmavat sarva-bhūteṣu. Oniselu pataki ton pe ni Cāṇakya Paṇḍita na ti jerisi pe,

mātṛvat para-dāreṣu
para-dravyeṣu loṣṭravat
ātmavat sarva-bhūteṣu
yaḥ paśyati sa paṇḍitaḥ

Asa to lagbara leleyi, Bhagavad-gita boseje. Beena awon arakurin at'obinrin to wa nibi, e gbiyanu lati jeki ile-ajosin yi ni ilosiawaju, e ka Bhagavad-gita lai se isotunmo iranu kankan si. Mosi pe ni iranu nitoripe awon isotunmo wanyi o wulo rara. Gbogbo nkan daju, lati ibere lo.

dharma-kṣetre kuru-kṣetre
samavetā yuyutsavaḥ
māmakāḥ pāṇḍavāś caiva
kim akurvata sañjaya
(BG 1.1)

O daju gan.