YO/Prabhupada 0411 - They have Manufactured a Gorgeous Truck: Gut, gut, gut
Departure Lecture -- Mexico City, February 18, 1975
Ati fi ile ati baba wa sile, ati sokale sinu ile aye yi atin jiya gan nisin. (Isotunmo ti Hrdayananda ninu ede Spanish) gege bi omode olowo sen kuro niile lati ni ominira, a si bere sini rin kakiri, ton peja awon eyan. (Ede Spanish) Omo olowo o ni nkankan se. Ohun elo baba re ti to fun lati gbe dada ninu aye yi. (Ede Spanish) Beena, awa na ni awon apeere bayi ninu awon ilu geesi, opolopo ninu awon omo olowo na man kuro nile lati lo fajogbon. (Ede Spanish) Ipo wa niyen, awon eda ninu aye yi beena lase ri. (Ede Spanish) Ati wa sinu ile aye yi latgi gbadun ara wa. (Ede Spanish) ninu igbadun iye-ara wa ati gbagbe baba wa loke, Olorun. (ede Sapnish) Ise ile aye yi ni latgi funwa ni isoro ni ile aye wa. (Ede Spanish)
- kṛṣṇa bhuliya jīva bhoga vāñchā kare
- pāśate māyā tāre jāpaṭiyā dhare
itumo re ni wipe lesekese ti awon eda bafe gbadun laisi Krsna, lais'Olorun, lesekese loma bosinu idimu maya. (Ede Spanish) Ipo wa niyen. Awa labe idimu maya, asi le jade kuro ninu e, bonse salaaye ninu Bhagavda-gita (BG 7.14), mām eva ya prapadyante māyām etāṁ taranti: "Enikeni toba teriba funmi le jade kuro ninu idimu maya". (Ede Spanish) beena awa sin se iwaasu imoye Krsna yi, tabi imoye Olorun, kasi ko won lati teriba fun Krsna, beena wan jade lati idimu maya. (Ede Spanish) Awa o sini ife okan kankan ju eleyi lo. (Ede Spanish) Awa ti salaaye pe, " Olorun leleyi. E teriba fun. E ronu nipa re nigbogbo igba, ke dobale fun. Lehin na ile aye yin ma ni ilosiwaju." (Ede Spanish) Sugbon awon eyan ni aye isin dabi were. (Ede Spanish) Fun igbadun iye ara won, won sise lat'aro d'aale. beena awon olufokansi si ni ibanuje lokan lati ri won bayi. (Ede Spanish)
Prahlāda Mahārāja sowipe " ibanuje okan mi si po gan tin ba ri awon eyan wanyi." Tani won? Tato vimukha-cetasa māyā-sukhāya bharam udvahato vimūḍhān (SB 7.9.43). Awon asiwere wanyi, vimūḍhan, wanti da awujo to dara. Kini yen? Gege bi ilu yin teni oko ton gba ilele titi. lati gba nikan, wanti da oko sun: " Gut, gut, gut, gut, gut, gut, gut". (Ede Spanish) Awon eyan le gba titi wanyi. Awon eyan po gan ton le se. Sugbon wan rin kaakiri, awon oko sin gbale. (Ede Spanish) O p'ariwo gan, alebu re si po gan, sugbon won rowipe, "Ilosiwaju awujo wa leleyi." (Ede Spanish) Notorina Prahlāda Mahārāja sowipe, māyā-sukhāya. lati ni isinmi lati ile gbigba - kosi isinmi kankan, wansi ni isoro imi - sugbon won ronu wie, " Nisin aw o gbodo gba ilele mo. Itura niyen fun wa>" (Ede Spanish) Beena, a le lo abe lati ge run, sugbon wanti ni ero to po nisin. (Ede Spanish) Lati da awon eron wanyi, wanti da awon ile-ise to po. (Ede Spanish) Beena teba wo awujo yi, die die eyin na ma ri wipe awujo esu loje. (Ede Spanish) Ugra-karma. Ise awada nitumo Ugra-karma. (Ede Spanish)
Beena kosi nkankan tose awon nkan tole funwa nitura, sugbon agbodo wo boya itura tabi isoro lonje siwa. (Ede Spanish) Nitorina ile aye eda wa lati lo asiko wa fun imoye Krsna. (Ede Spnish) Ko wa fun ilokulo. (ede Spanish) Nitoripe awa o mo nigbati iku ma de. (Ede Spanish) T'awa o ba lo askiko yi dada, a le ku leyikeyi asiko, asi ma gba ara eda imi ti iseda yi ba funwa. (Ede Spanish) Nitorina mofe ki gbogbo yi parapo pelu egbe imoye Krsna yi, e gbe ile aye yi jeje kiku baa ma mu yin lowo Krsna. (Ede Spanish) kasi gbiyanju lati koju si nkan tanse lati awon ofin, ati orin kiko, igba merindin logun, toba kere ju. lehin na o daju pe awa ni idaabo. (Ede Spanish) Beena eyin ni awon iroyin nipa pipe aye yi. E ma lo nilokulo. E tesiwaju bayi, ile aye yin mani ilosiwaju. (Ede Spanish) Awa o fi ipaari si awon nkan tole je k'ani itura sugbon a fe ki awon nkan wa ni iwonba toye. (Ede Spanish) Beena taba tele awon ofin wanyi tasi korin fun igba meridinlogun, ipo wa to daju niyen. (Ede Spanish) Mofe ke tele ilani yi. Ife okan mi niyen. Ese pupo. (Ede Spanish)
Olufokansi: Jaya! jaya!