YO/Prabhupada 0417 - Happy In This Life and Next Life
Lecture & Initiation -- Seattle, October 20, 1968
beena emu egbe imoye Krsna yi ke ni idunnu ninu aye yi ati ikeji. Teyin ba le pari ife yin si Krsna ninu aye yi, eti pari ise yin. Bibeko, ounkoun teyin ba se ninu aye yi, ma wa pelu yin. Kole tan. Wan ti salaaye ninu Bhagavad-gita, pe śucīnāṁ śrīmatāṁ gehe yoga bhraṣṭo sañjāyate (BG 6.41). Enikeni toba le se yoga yi dada ni pipe, o si l'aye lati ni ibimo ninu ebi olowo, tabi ibimo ninu ebi mimo. yiyan meji. kadaa pe eyin ba ni ibimo ninu ebi mimo tabi ebi olowo, eyin ma ni ara eda ninu aye to kan. Sugbon teyin o ba mu egbe imoye Krsna yi ni pataki, eyin o le mo nkan tema di ninu aye to kan. Orisirisi eda 8,400,000 lo wa, eyin le wonu ikan ninu wan. Teyin ba d'igi.. Gege bi mose ri ni ilu San Francisco. Wan sowipe " Igi yi ti wa nibe fun odun ẹ̀ẹ́dẹ́ɡbarin," Wan duro sori aga fun odun ẹ̀ẹ́dẹ́ɡbarin. Nigbami awon oluko ma sofun awon omo ile-iwe ton ba ti huwa kuwa pe "e duro sori aga." Beena awon igi wanyi jiya , " E duro," lati ofin iseda. Ele d'igi, tabi aja, tabi ologbo tabi eku. Orisirii eda lowa sugbon ema jeki ara eda eniyan koja yin. Eje ki ife teni fun Krsna ninu aye yi wa ni pipe ki aye yin bale dun ninu aye yi ati aye to kan.