YO/Prabhupada 0460 - Prahlada Maharaja Is Not Ordinary Devotee; He Is Nitya-Siddha
Lecture on SB 7.9.7 -- Mayapur, February 27, 1977
Beena Prahlāda Mahārāja... Osi ni ijiyan pelu baba re, sugobn eyan lasan ko loje. Baba re je eyan pataki, seti ri bayi. O si ni idari lori gbogbo agbaye. Beena omo talaka ko loje. Omo okurin olowo loje. Prahlada Maharaja. baba re si fun leeko to po. Niotooro l'odun marun to kan. Beena janmaiśvarya-śruta-śrī. Gbogbo nkan lowa nibe, sugbon Prahlada Maharaja o f'okan si ipo aye re Osi gbekele gbogbo idunnu ninu ise ifarasi Olorun ton se. Nkan tafe niyen. beena awa o le dede gun ipo yi. Nitya-siddha loje. Bi mosefe salaaye teletee, eyikeyi asiko ti Krsna ba sokale, awon olufokansi nitya-siddha re si man tele wa. Beena gaurāṅgera saṅgi-gaṇe, nitya-siddha boli māne, tara haya vrajabhūmi vāsa, like that, Narottama dāsa Ṭhākura... Gege bi śrī kṛṣṇa caitanya prabhu nityānanda śrī advaita gadādhara śrīvasadi gaura bhakta vṛnda. Beena awon alabasepo ti Caitanya Mahaprabhu, nitya-siddha lonje. Eyin o lese kema ri won, ke wa bere sini fori ro eyi tefe s'adura si... (isinmi)
Krsna ti farahan - Panca tattva. Kṛṣṇa ni īśa, ati Nityānanda Prabhu, Oun ni prakāśa, ifesi t'alakoko t'Oluwa. Oluwa si ni awon irisi to po. Advaita acyuta anādi ananta-rūpam ādyaṁ purāṇa-puruṣam (Bs. 5.33). O ni aimoye awon irisi wanyi. Beena iris t'alakoko ni Baladeva tattva, Nityananda; ifesi re na, Advaita; agbara mimo re, Gadaghara ati agbara tinu re Srivasa. Beena Caitanya Mahaprabhu ti farahan pelu panca.., pañca-tattvātmakam. Eyin o le pawa ti, teyin ba rowipe " Eleyi nikan ni mo fe s'aadura si..." asise nla niyen, "... Caitanya Mahaprabhu tabii Caitanya-Nityananda" Rara. Egbodo s'aadura si Panca-tattva, pañca-tattvātmakaṁ kṛṣṇam, ni pipe. Beena, Hare Kṛṣṇa mahā-mantra, oruko merindinlogun, Hare Kṛṣṇa, Hare Kṛṣṇa, Kṛṣṇa Kṛṣṇa, Hare Hare, (ajo na daaunsi) Hare Rāma, Hare Rāma, Rāma Rāma, Hare Hare. Beea eyin o le kowan paapo. Egbodo se gege bi sastra. Mahājano yena gataḥ sa panthāḥ (CC Madhya 17.186). Teyi ba kuro lona sastra, lehin na ile aye yi o le ni ilosiwaju.
- yaḥ śāstra vidhim utsṛjya
- vartate kāma-kārataḥ
- na siddhim avāpnoti
- na sukhaṁ na parāṁ gatim
- (BG 16.23)
Beena teyin ba fe sunmo lori ipo kanna bi Prahlada Maharaja, awa ogbodo farawe lesekese. Agbodo tele sādhana-bhakti, sādhana-bhakti, fun gbogbo awon eyan; ati kṛpa-siddha, iyen yato gan. Awa o le siro boseje. ti Krsna bafe, lesekese o le jek'eyan ka se pataki. krpa-siddha niyen. Beena awon ipo meta olufokansi lowa: nitya-siddha ati sādhana-siddha ati kṛpa-siddha. nitya-siddha ni Prahlāda Mahārāja. sadhana-siddha lasan ko loje tabi .... niotooro, kosi iyato kankan, boya sadhana-siddha tabi krpa-siddha tabi nitya-siddha, sugbon oye ka ranti pe Prahlada Maharaja o kin se olufokansi lasan, nitya-siddha loje. Nitorina lesekese loni awon aami mimo, asta-siddhi. Aṣṭa-siddhi, seti ka ninu iwe "Nectar of Devotion. Beena awon aami idunu mimo wanyi, ekāgra-manasā. Ekāgra-manasā, "pelu àkíyèsí toje pipe." Lati ni iru àkíyèsí bayi le gba aimoye odun. Sugbon Prahlada Maharaja - lesekese. omo odun marun, nitoripe nitya-siddha loje. Oye ka ranti ni gbogbo'gba pe awa o le farawe. "Nisin, Prahlada Maharaja tini ekāgra-manasā, emi na fe di bayi." Rara. Kolese se. Ele se sugbon bayi ko.