YO/Prabhupada 0481 - Krishna is All-attractive, Krishna is Beautiful



Lecture -- Seattle, October 18, 1968

Beena ijiyan yi pe, awon ohun ptaki ninu eje wa nio sise mo; nitorina laye se pari - rara. ijiyan ati idaaun to po gan lowa. Niotooro, koko oro to wa niwipe awa sin soro lori agbara iwe mimo, awon eda mimo ati oluko mimo. Bose yeko ri niyen. Eyin o le da nkan tiyin sile pel'opolo kekere, at iye-ara yin tio daju. Awon eda eyan o daju gege bi omode to wo orun, ati onisayensi ton wo orun na. Awon omode ni imoye kankan nipa orun. Ti omode na be keeko lowo onisayensi ole mo nipa agbara orun. Nitorina awon nkan t'ale ko peloju lasan iwonba die niwon, kode daju. egbodo loba awon olori - ninu gbogbo eto aye. Beena teyin bafe mo nipa Olorun, egbodo ni idaabo ninu Bhagavad-gita. Kosi oun tele fi ropo. Eyin o le fori ro wipe " bayi bayi l'Olorun se ri, boya bayi l'Olorun se ri," " Kos'Olorun," " Olorun ti ku," " Olorun wa laaye." Oro iranu ni gbogbo e. Nibi Krsna sowipe

mayy āsakta-manāḥ pārtha
yogaṁ yuñjan mad-āśrayaḥ
asaṁśayaṁ samagraṁ māṁ
yathā jñāsyasi tac chṛṇu
(BG 7.1)

teyin ba nigbagbo pe Krsna, Oluwa lon soro fun ara re, bi Arjuna se nigbagbo, lehin na lema ni oye nipa Olorun. Bibeeko kolese se. Asaṁśayam.

Beena ilana to wa ni talakoko, mayy āsakta-manāḥ. Eyin gbodo fun okan yin ninu ise Krsna. Ilana yoga niyen, tawa sin salaaye fun awon eyan ninu imoye Krsna. Imoye Krsna.. fun apeere teyin ba ti ina ile yin, sinu ile ton pin ina monamona, ina ma wa ninu ile re ni gbogbo'gba. Beena, teyin ba fokan lori Krsna, kode le na. Gbogbo eda loni ifarasi Krsna. Krsna lewa gan, Krsna si ni awon itan akoole to po. Gbogbo Veda lo kun fun awon ise Krsna. Bhagavad-gita lo kun fun ise Krsna. Beena taba ni oye wipe alagbara l'Olorun je, ipo lasan nipa oye yi leleyi. Sugbon agbodo gunke si, kaba le mo bose lagbara to. Bose lagbara to, ko le lati mo, nitoripe iye ara o daju sugbon eyin gbodo gbiyanju lati gbo nipa awon ise Oluwa nigbogbo'gba, nipa ipo Oluwa, kesi ronu nipa re, bayi ele daajo si, ele jiyan na. Lehin na ele ni oye nipa eni t'Oluwa je laisi isiyemeji. Ibere t'alakoko ni, mayy āsakta-manāḥ. Ninu apa iwe to keyin, Krsna ti salaaye, pe eni toba n'ronu nipa Krsna nigbogbo'gba, oun ni yogi t'ipo kini, Ni orile-ede yi awon eyan mo nipa eto yoga gan, sugbon awon eyan o monipa eni toje yogi t'ipo kini. wanti juwe bi yogi t'ipo kini yi seri ninu Bhagavad-gita: yoginām api sarveṣāṁ mad-gatenāntarātmanā (BG 6.47), ninu aimoye awon yogi, yogi tabi bhakti-yogi ton ri ninu okan ara re, irisi Krsna, oun ni yogi ti'po kini. oun lo gaju. Beena egbdo tesiwaju ninu eto yoga to gaju yi, wanti salaaye nipa re nibi, mayy āsakta-manāḥ: pelu ife okan to po.