YO/Prabhupada 0491 - Against My Will So Many Distresses Are There
Lecture on BG 2.14 -- Germany, June 21, 1974
Beena teyin ba keeko nipa aye yi lati'beere ara wa, ninu oyun iya wa, isoro loje. Isoro to po gan wa, ibanuje towa po gan. Lehin na teyin ba dagba, ibanuje yi na ma dagba si. ibanuje yi o le tan. Lehin na janma, lehin na ojo arugbo, lehin na aisan. Beena botilejepe eyin ni ara eda yi... awon oni sayensi, won da awon nkan sile , awon ogun, awon nkan tuntun. kilon pe? Streptomycin? Awon nkan to po. Sugbon kosi bonsele fi ipaari si aisan na. Kolese se, sa. Ele da awon ogun to da lati sewosan awon aisan. Kole se iwosan na. Fun igba die nikan. Sugbon kosi onisayensi na toti da ogun tojepe " Teba mu eyin o le ni aisan mo." Kolese se. " Egbodo mu ogun, kolesi iku mo." Kolese se. Nitorina awon ologbon won mo dada, pe ibi yi duḥkhālayam aśāśvatam (BG 8.15). Wanti salaaye ninu Bhagavad-gita, Ibi ibanuje loje. teyin ba duru sibi... sugbon ode laje, awa o le mo. Ati gbabee " Ile aye yi daa. E je kin gbadun e." Ko daa rara, awon iyi po wa nigbogbo'gba. Ibanuje yi tabi toun, aisan yi tabi toun. Inira yi, wahala toun. Ibanuje meta lowa: adhyātmika, adhibhautika, adhidaivika. ibanuje ara eda nitumo Adhyātmika. isoro lati iseda nitumo adhidaivika. iseda. lesekese ìwàrìrì ilê le sele. Lesekese ais'ounje lese, koma s'onje mo, k'ojo poju, tabi koma s'ojo, tabi oru to poju, tabi otutu to poju, Agbodo gba awon ibanuje yi mora, l'ona meta. Ikan tabi meji gbodo wa. sugbon ko ye wa pe " Ile aye yi kun fun isoro, nitoripe moti ni ara eda yi." Nitorina ise okurin to logbon ni lati sewaadi bosele fi ipaari si gbigba ara eda yi. Ogbon ori niyen. Oye ko mowipe " Gbogbo'gba nimo wa ninu ibanuje, Ara mi ko nimi, sugbon mo wa ninu ara eda yi. Nitorina o daju pe ara i ko nimi. Ti, bakana tabi keji, mole gbe laisi ara eda yi, lehin na ibanuje yi ma tan. Ogbon ori niyen. Nkan tose se loje. Nitorina ni Krsna se sokale wa. Nitorina ni Oluwa se wa, lati funwa ni itosona pe " Ara yin ko niyin. Ei leje, emi mimo. nitoripe eyin wa ninu ara eda yi lesen jiya bayi." Nitorina Krsna ti funwa nitosona pe " Nitori ara eda teni lesen ni ibanuje yi." Egbiyanju lati ni oye naKilode teyin se ni awon inira ati igbadun wanyi? nitori ara yi na.
Nitorina nkankanna ni imoye Buddha yi je, pe egbodo pari pel'ara yi, nirvana, nirvana. Imoye toni niwipe gbogbo inira ati gbadun teyin ni, nitori ara eda yi tei. Awa na gbabee.