YO/Prabhupada 0503 - To Accept Guru Means to Inquire from Him About the Absolute Truth
Lecture on BG 2.15 -- Hyderabad, November 21, 1972
Vedānta-sūtra ni asọye Śrīmad-Bhāgavatam. Jīvasya tattva-jijñāsā, jīvasya tattva-jijñāsā. Ile aye wa niyen. Jivasya, gbogbo eda, Nipataki awon eda eyan nitoripe awon aja at'ologbo kosi bonsele se'beere nipa otito to gaju Nitorina, ipari oro yi niwipe, ile-aye eda, awa o gbudo lo ni ilokulo lati huwa bi awon eranko. ogbudo se'beere nipa Otito to gaju. Athāto brahma jijñāsā. ogbudo gbiyanju lati ni oye na. Tad viddhi, tattva-darśibhiḥ. lati awon tattva-darśī Jñāninaḥ, tattva-darśinaḥ, oro to waniyen. Ninu gbogbo awujo eda eyan, ati ran awon omode losi ile-iwe ni eto towa. gege na tabafemo nipa awon eto mimo, tad-vijñānārthaṁ sa gurum eva abhigacchet (MU 1.2.12). Dandan ni itumo Abhigacchet. Kosejo idakeji eyan o le sowipe, boya ni mofe lo". Rara. Teyin o bafe lo, wanma yanyin je. Eto Vaiṣṇava niyen . Ādau gurvāśrayam. agbudo teriba fun oluko, ilana t'alakoko niyen. Ādau gurvāśrayaṁ sad-dharma-pṛcchā. Konsepe mofese nitoripe gbogbo eyan tinse: "Ma si gba oluko. Nisin ise mi titan. Emi na tini Oluko" Rara. Tattva-jijñāsā. Jīvasya tattva-jijñāsā. LAti beere nipa otito to gaju ni idi fun Oluko. Jijñāsuḥ śreya uttamam. Oro Veda niyen. Eni tofemo ni Jijñāsuḥ Jijñāsuḥ śreya uttamam. Śreyaḥ.Iwulo niitumo Śreyaḥ uttamam, ere to daju. Eyan tobafemo nipa ere todaju lo titi ninu aye, fun eyan bayi, ogbudo gba Oluko.
- tasmād guruṁ prapadyeta
- jijñāsuḥ śreya uttamam
- śābde pare ca niṣṇātaṁ
- brahmaṇy upaśamāśrayam
- (SB 11.3.21)
egbe imoye Krsna wa niyen. Awa fe ko awon eyan nipa iwuo aye yi. Bhagavata ni idi fun aye-mimo. Dharmān bhāgavatān iha. Teyan bani oye nipa aye-mimo, toba ni oye nipa aye re na, eyan bayi asi ni imoye toda kini ipinnu fun aye yi, iru ise wo loye kase, kiniide aye yi Egbe imoye Krsna wa niyen.
Ese pupo. Hare Krsna.