YO/Prabhupada 0509 - These People say the Animals Have no Soul



Lecture on BG 2.18 -- London, August 24, 1973

Prabhupāda: Vinā paśughnāt (SB 10.1.4). Oro oba niyen.. kini yen?

Elesin: Yudhiṣṭhira.

Prabhupāda: Yudhiṣṭhira ko .

Elesin: Parīkṣit, Parīkṣit Mahārāja.

Prabhupāda: Parīkṣit Mahārāja. Osowipe imoye Olorun, Krsna awon ton jeran kosei bosele yewan. Vinā paśughnāt (SB 10.1.4). Nivṛtta-tarṣair upagīyamānāt. Eyin na ma riwipe awon ton jeran, awon Onigbagbo ati musluman, kole yewan. Alaseju niwan.Kosi bonsele monipa emi ati Olorun. Wansi ni ejo ton ro, wande rope elesin lon je. Kini itumo ese, kiini itumo iwa dada, awon nkan wanyi o le ye wan nitoripe wan peran. kolese se. Nitorina ni Oluwa Buddha se soro nipa ahimsa. Ahimsa nitoripe osi daloju pe gbogbo eda ma los'orun apaadi ton ba tesiwaju pelu eran pipa "Mo gbudo fi ipari si ton ba fe logbon loojo waju" Sadaya-hṛdaya darśita: apa meji. lowo kan kofe ki awon ma pa awon eranko mo. l'apa keji ori wipe " gbogbo agbaye am los'orun apaadi. gege na oye kin sen nkan". nitorina lose sowipe ara o l'emi, nitorope kosi bi awon eyan wanyi yi sefe ni oye iru nkan bayi Nitorina kose so nkan nipa emi tabi Olorun. O sowipe " Ema peran mo". Tin ba yin e lekana, a niyin lara. kilode tefe fun elomi niinira? kosejo, amope ko l'emi ko so nkan kan nipa emi. awon eyan wanyi sowipe awon eranko o le emi sugon oun na si ni inra teba fe pa teyen ba ni inira, kilode tefe fun elomi? ilana Buddha niyen. Sadaya-hṛdaya darśita-paśu-ghātam. Nindasi yajña-vidher ahaha śruti-jātam. O si sowipe: " Awon Veda o dami loju". nitoripe orisirisi ofin lowa ninu Veda, awon ofin tioni je ke peran. Sugbon wan le peran to ba fe s'ebo. sugbon Buddha o gba fun awon ebo ton se. Nitorina nindasi. ibaniwi nitumo Nindasi. Nindasi yajña-vidher ahaha śruti-jātaṁ sadaya-hṛdaya darśita. Kilode? Okurin jeje loje pel'okan to daa Imoye Krsna niyen. Olorun dara gan Kosi fe. sugbon toba yeko se, a se. sugbon ti Olorun pa fiku pa eyan oyato si tawa. Oun lo dara ju Enikeni ti Krsna ba pa lesekese loma ni'gbala. Awon nkan bayi si wa. Kosi besele se isiro emi, sugbon o wanbe, ara wa asi paari nijokan. toba si ko lati jagun, to rowipe o le fun awon ebi re ati Oluko re ni'daabo nijokan wansi ku. leni tabi ola itumo Antavanta niyen. kasowipe baba agba re ti darugbo. sele fi ku pa nisin nitoripe o le ku lehin odun kan si osu mefa, O le ku nitoripe oti darugbo. Ariyanjiyan to wa niyen Nkan tose pataki niwipe Krsna fe ki Arjuan jagun Kogbudo fi ise ksatriya le. Koye ki ipaari ara awon eyan je ibannuje fun Nitorina lose fun wa ni ilana pe: " Ara wa yato si emi wa. Ma rowipe, eyan le fiku pa emi Dide ko ja. Ilana to wa niyen.

Ese pupo.