YO/Prabhupada 0521 - My Policy is Following the Footstep of Rupa Gosvami
Lecture on BG 7.1 -- Los Angeles, December 2, 1968
Ebiyanju lati mo nipa imoye Krsna yi. E gbudo se adase bakanna tabi keji egbiyanju lati ni ifarafun Krsna. Yena tena prakāreṇa, bakanna. gege teba niife fun eyan, ema se ounkooun lati le ri onitoun... ko le rara. Awa mo ilana tele gba. awon eranko gan mo bonsele ri nkan gba Ijakdai aye yi niwipe gbogbo wa lafe de ipinnu yi. eyin na egbiyanju, ema sironrun.. eyin na efogbon wa besele ri Krsna mu. Nkan to ba je ki ile-aye yin ni ilosiwaju niyen..
- yena tena prakāreṇa manaḥ kṛṣṇe niveśayet
- sarve vidhi-niṣedhāḥ syur etayor eva kiṅkarāḥ
- (Brs 1.2.4)
opolopo awon eyan lowa ninu egbe imoye Krsna nisin. Die die nimo fin ye wan, Sugbon awon ton se adase egbe imoye Krsna yi ni orile-ede India, oni ofin to po ton tele awon eyan mi le sowipe, "Swamiji yi o laju, awon ofin re ti po ju" Sugbon emiko mo dawan le.. gege bonseje niyen. Nitoripe kolese se taba fe fun yin nigbogbo awon ofin wanyi ni'lu yin Ilana mi niwipe agbudo tele ilana Rūpa Gosvāmī. O sowipe, bakanna tabi keji ejekan gbokan le Krsna. Nkan timo ( kose gbo). wanma tele awon ofin wanyi toba ya. Ni alakoko ejekan ni ife fun Krsna. Yoga ti Krsna ti salaaye fun wa niyen, mayy āsakta-manāḥ pārtha. egbiyanju lati ni ifarafun si Krsna. Kilode teyin o le ni ifarafun Krsna? Orisirisi nkan to dara wa ninu imoye Krsna yi. Ani awon aworan, aworan kikun, awan jo nigbami, asi ni orin, ati ounje to da gan, asi ni awon aso to daara gan, ati awon ilera, awon asiwere wanyi kosi bonsele ni ifarafun, awon nkan gidi bayi. osi rorun gan. Kini di toje pe awon eyan o le gba ilana yi? nitoripe asiwere ni onitoun. Otan oto-oro nimo sofun yin. enikeni toba fe le wa bami jiyan pe awon tionife fun imoye Krsna pe asiwere nigbogbo wan. mole fihan hin. Ema sebi awon asiwere wanyi. Egbiyanju lati di okurin ologbon. gege bi onkowe Caitanya-caritāmṛta se so, kṛṣṇa yei bhaje sei baḍa catura. enikeni toba ti gba imoye yi sokan, okurin ologbon loje. ema sebi awon Ode ti'po kini, sugbon egbiyanju lati di okurin ologbon. Ibeere mi niyen.
Ese pupo ( Idobale) Seni ibeere kankan?
Nijo tokoja awon omo-ile iwe ton wa si po gan, nisin kosenin kankan mo. nitoripe wan fe di asiwere to gaju, otan. Oto-oro niyen. Afi teyan ba logbon kole gba imoye Krsna yi sokan. Wanfe fi awon eyan yan wan je, bakanna tabi keji.Otan. Nkan lasan, to rorun pelu abajade to da gan - wan ko lati gba sokan.