YO/Prabhupada 0539 - Try to Understand this Krishna Consciousness Movement



Janmastami Lord Sri Krsna's Appearance Day Lecture -- London, August 21, 1973

taba fe ifokanbale ati alaafia ninu awujo wa, agbudo mu imoye Krsna yi ni pataki. Ibeere wa niyen. ema fi sere, egbe imoye Krsna yi. Egbe wa yi le yanju gbogbo isoro aye yi, ati awon isoro agbaye yi t'awujo, ti oloselu, t'omoye, t'esin, t'owo - gbogbo nkan ni egbe Krsna yi le yanju. nitorina lasen bere lowo awon ijoba, gege bi Olori wa to wanbe egbiyanju lati monipa egbe imoye Krsna yi. itosona si dabi onisayensi, wansi se pataki. kon soro ogbon, tabi igbagbo lasan. egbe toni sayensi to po ninu re. awan sin pe gbogbo awon eyan lati gbogbo ilu pe : egbiayanju lati ni oye nipa re. teba si mu ni pataki eyina ma riwipe egbe imoye Krsna yi lo daju fun gbogbo awujo eyan. otooro niyen. enikeni tobafe wa lewa. Ale soro nipa ounkoun teba fe. Kṛṣṇa bhūliyā jīva bhoga vāñchā kare. koye ka...

lati leni aye tionipari ni ipinnu aye yi. Tyaktvā dehaṁ punar janma naiti (BG 4.9), nkan tati gbagbe niyen. awa kon gbe ile-aye yi bi awon aja ati ologbo, laisi imoye kankan pe ale ni aye to da nigbati konisi ibimo tabi iku ko. awa o tie mowipe alese amṛtatvam sugbon kosi nkan tio sese. Amrtatvam. koseni tofe ku. oto-oro niyen. koseni tofe darugbo, koseni tofe ni aisan. iru iwa tani leleyi. Kilode? nitoripe ninu irisi wa, kosejo ibimo, iku, ojoarugbo, aisan. lehin igbati awon eda bagunke lati awon ed alomi, eye, eranko, eso, igi, teba wa de ara eyan bayi... Aśītiṁ caturaś caiva lakṣāṁs tād jīva-jātiṣu. ilana itiranya leleyi. awa ti de ara eda. lehin na agbudo mo nkan ti ipinnu aye wa je. ipinnu aye yi ni lati koja iku, amṛtatvam, ele koja iku teba gba imoye Krsna yi sokan. Krsna ti sofun wa. Otto-oro ni. Agbudo ni igbagbo. Janma karma me divyaṁ yo jānāti tattvataḥ. teba gbiyanju lati mo nipa Krsna, niotooro, tattvatah, , tyaktvā dehaṁ punar janma naiti (BG 4.9), lehin igba teba fi ara yi sile, konisidi pe efe gba ara imi. lesekese teba koja ipo pe eyin tun ni ara, itumo re niwipe eti di alainipaari. nitoripe nibeere alainipari ni gbogbo wa.

nitorina ni Krsna sen farahan, lati ko wa logbon, pe " alainipaari ni wa. gege bi emi nkankan leje pelu mi. gege bi moseje alainipaari. beena leyin na seri. eyin sin gbiyanju lati ni idunnu ninu aye yi".

mamaivāṁso jīva bhūto
jīva-loke sanātanaḥ
manaḥ saṣṭanindriyāni
prakṛti-sthāni karṣati
(BG 15.7)

ten sise gan fun..... nkan toda niwipe eti gbadun aye ninu orisirisi ara, bi ologbo, bi aja, bi orisa, bi igi, bi eso, bi kokoro. nisin teni ara eyan emafoju si igbadunnnu aye yi Egbiyanju lati mo nipa Krsna. Ase sastra niyen Nāyaṁ deho deha-bhājāṁ nṛloke kaṣṭān kāmān arhate viḍ-bhujāṁ ye (SB 5.5.1). eni lati sise gan bi awon aja ati elede teba gbadun, ipinnu ile-aye eda koniyen. agbudo gba inira die sara, itumo ile aye eda niyen. Tapo divyaṁ putrakā yena śuddhyet sattvam. egbudo ya simimo. ipinnu ile-aye wa niyen. Nibo ni mole fi ile-aye sattva mi si? Brahma-saukhyam tv anantam. wani igbadun tiolopin, ati idunnu ltiolopin. Igbadun gidi leleyi Ramante yogino 'nante satyānanda-cid-ātmani iti rāma-padenāsau paraṁ brahmābhidhīyate (CC Madhya 9.29).