YO/Prabhupada 0541 - If You Love Me, Love My Dog



Sri Vyasa-puja -- Hyderabad, August 19, 1976

kosi besele fun awon oro Olorun ni itunmo imi. Kolese se itumo dharma ni dharmāṁ tu sākṣād bhagavat-praṇītam (SB 6.3.19). kosi besele da esin yin ninu ile yin. iwa asiwere niye, iranu loje. sākṣād bhagavat-praṇītam ni itumo Dharma. gege bi ofin. itumo ofin niwipe ounkoun tijoba ba fun e. iwo o gbudo datiesile nile e. fun apeere tijoba ba sowipe loju titi esun segbe kan boya otun ab'osin. eyin o le sowipe kilode ti miole lo s'apa keji tin ba fe? Rara, ewo o le se bayi. omo-odaran loma je Ni aye isin na - lati aye atijo, orisiri ilana esin lo wa. sugbon esin to daju ni ounkooun ti Olorun tabi Krsna baso Sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66). itumo esin leleyi. Kosi besele da nkan yin sile.

Nitorina ninu Śrīmad-Bhāgavatam, ni ibeere dharmaḥ projjhita-kaitavo 'tra paramo nirmatsarāṇām (SB 1.1.2). awan eyan le beere sini ni ilara fun nitoripeoni awon akeko to daju ti gbogbo wan s'adura fun ton se puja Rara, bi ilana na se ri niyen. Ema jeki ilara ba inu yin je Ācāryaṁ māṁ vijānīyān nāvamanyeta karhicit (SB 11.17.27). alabasepo Olorun ni Acarya je. Yasya prasādād bhagavat-prasādo. teba gbadura si acarya na, lehina inu Krsna, Olorun asi dun si. taba fekin inu re dun ese nkan toma jeki inu awon alabasepo re dun "teba feran mi, oye ke niife aja mi". Ninu Bhagavad-gītā wan sowipe ācāryopāsanam. Ācāryopāsanam. Agbudo s'adura si awon acarya.

yasya deve parā bhaktir
yathā deve tathā gurau
tasyaite kathita hy arthaḥ
prakāśante mahātmanaḥ
(ŚU 6.23)

Mantra lati awob Veda niye nad-vijñānārthaṁ sa gurum evābhigacchet (MU 1.2.12).

tasmād guruṁ prapadyeta
jijñāsuḥ śreya uttamam
śabde pāre ca niṣṇātaṁ
brahmaṇy upaśamāśrayam
(SB 11.3.21)

Tad viddhi praṇipātena paripraśnena sevayā (BG 4.34). Ilana to wa niyen guru na gbudo wa lati ilana parampara. Lehin a le sowipe o daju. Bibeko asiwere loje. ogbudo wa latinu awon parampara lati le ni oye nipa tad-vijñānam sayensi to gaju, egbudo loba guru, kosi besele sowipe " mole ni oye nipa re nile£ Rara Kole sese bayi. ase sastra niyen. Tasmād guruṁ prapad. taloye ko gba guru? eso aso koni Guru je, gege bi aja teni, awujo awon eyan nisin kon fe toju Guru. Rara, beeko. toloyeko gba guru? Tasmād guruṁ prapadyeta jijñāsuḥ śreya uttamam (SB 11.3.21). Enikeni toba gbiyanju lati mo nipa sayensi emi. Tad vijñānam. Oṁ tat sat. Oun loye ko gba guru. Eto aso koni guru je.