YO/Prabhupada 0587 - Every One of Us is Spiritually Hungry
Lecture on BG 2.20 -- Hyderabad, November 25, 1972
Beena teyin ba rowipe, aso mi nimi, aimokan teni niyren. Nkan ton sele leleyi. Bipe awa n'fo aso yi n'ise rere fun agbaye yi je. Kasowipe ebi n'pa yin, mosi mu aso yin ti mo fo dada pel'ose, sema ni itelorun? Rara. Kolese se. Beena gbogbo l'ebi eto nkan mimo n'pa. Kilode ti awon eyan wanyi fe fo aso a'tewu yi? Kolesi alafia kankan. Ise rere fun agbaye yi bipe won fo vāsāṁsi jīrṇāni. Otan. itumo iku, wanti salaaye dada, pe nigbati aso mi ma darugbo masi paaro aso na. Beena, ipaaro aso wa nitumo ibimo ati iku. Wanti salaaye dada. Vāsāṁsi jīrṇāni yathā vihāya (BG 2.22). Jīrṇāni, aso toti gbo, ewu toti gbo, oye ka sonu, kasi mu aso tuntun. Beena, vāsāṁsi jīrṇāni yathā vihāya navāni gṛhṇāti. Aso tuntun. Beena arugbo nimi.
Beena, ti mio ba nigbala, tin ba ni awon eto to po lati yonju ninu aye yi, Lehin na mogbodo gba ara eda imi. Sugbon Teyin o ba ni eto kankan mo, niṣkiñcana... niṣkiñcana leleyi je. Niṣkiñcanasya bhagavad-bhajanonmukhasya. Caitanya Mahāprabhu sowipe, niṣkiñcana. Eyan gbodo ni ominiran pipe, ominiran lati awon nkan aye yi. Oye ki awon nkan bayi yi su wa. Lehin na o daju pe a le losi odo metalokan.