YO/Prabhupada 0596 - The Spirit cannot be Cut into Pieces



Lecture on BG 2.23 -- Hyderabad, November 27, 1972

yasyaika-niśvasita-kālam athāvalambya
jīvanti loma-vilajā jagad-aṇḍa-nāthāḥ
viṣṇur mahān sa iha yasya kalā-viśeṣo
govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi

Beena nibi, ibere imoye mimo yi, emi, emi mimo yi, kosi nkankan tole ge si wewe. Nainaṁ chindanti śastrāṇi nainaṁ dahati pāvakaḥ. Nisin egbiyanju lati ni oye nipa eto na. Awa sin rowipe aown oni sayensi ni asiko wa yi, won rowipe. kole s'aye kankan lori isogbe orun. Rara. Awa eda wa nibe. Awa ti gba awon imoye wanyi lati Vea pe aye n'be nibe. Awon eda eyan bi awa na si wa nibe. Sugbon ara ina lon ni. Otan. Nitoripe awa o le siro pe " Bawo ni awon eda sefe gbe ninu ina?" Lati daaun si isoro yi, Krsna sowipe nainaṁ dahati pāvakaḥ. (segbe:) Kilode teyin se joko sibe? Wasi bi. Nainaṁ dahati pāvakaḥ. Kosi na kankan tole jo emi na. Toba jepe a le fina jo, beena ninu ilana awon Hindu, nigbateyin ban fina jo ara iku, lehin na eyin ti jo emi ara re na pelu. Looto, awon alainigbagbo rowipe, t'aba jo ara eda gbogbo e ti tan. Awon alakowe giga, won ronu bayi. Sugbon nibi, Krsna sowipe, nainaṁ dahati pāvakaḥ. "kosi besele fian jo." Bibeko bawo lose wa laaye? Na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). wanti salaaye gbogbo nkan na. Emi wa kole jona, beena kosi besele ge si wewe. Lehin na: na cainaṁ kledayanty āpaḥ. Beena kosi besele d'omi si. Kole tutu toba wonu omi. Nisin ninu ile aye yi, awa ti riwipe ounkoun toba je koba tie le gan.. bi okuta tabi irin, ale ge si wewe. Wan ni awon ero tole ge. Ale ge ounkoun si wewe. ale fina jo ounkoun na. Bi ina yi se gbona to leyatoo si ara won sugbon kosi nkankan tawa ole fina jo. Lehin na gbogbo nkan teba fi sinu omi loma tutu. Sugbon nibi wanti sowipe, na cainaṁ kledayanty āpo na śoṣayati mārutaḥ: kole ba ategun lo na. Owa tayeraye. Itumo re niwipe kosi ipo aye kankan tole kan emi wa. Asaṅgo 'yaṁ puruṣaḥ.

Ninu awon Veda wan sowipe awon eda o ni nkankan se pelu ile aye yi. Idaabo lasan loje, won o fowokan. Gege bi ara mi seje, botilejepe aso yi sin bomi lara; ko somo mi lara. Ko paapo. Ara i si yato s'ara mi. Beena, emi wa si yatoo si idaboo ile aye yi. Lori awon ife okan to yato nikan. lose jepe awa sin gbiyanju lati ni idari lori ile aye yi. Gbogbo wa lale ri bee.