YO/Prabhupada 0623 - The Soul is Transmigrating from One Body to Another



Lecture on BG 2.13 -- Pittsburgh, September 8, 1972

dehino 'smin yathā dehe
kaumāraṁ yauvanaṁ jarā
tathā dehāntara-prāptir
dhīras tatra na muhyati
BG 2.13

Isoro towa nisin niyen. Awon eyan o mo nipa agbara to wa ninu ara eda. Nibi ninu Bhagavad-gita, wanti salaye, dehi. Onile ara eda nitumo Dehi. Awon eda eyan nikan ko, sugbon awon eranko na, awon eda.. awon eda to wa laye yi won to 8,400,000. Awon lonpe ni dehi. Onihun ara yi nitumo Dehi. Aja, ologbo, eda eyan, Olori, tabi awon eda giga tabi kekere. Gbogbo awon eda wanyi, olori ara wan lonje. Awa na le jeerisi. E mo gbogbo nkan nipa inira ati igbadun ara yin. Mo monipa inira ati igbadun ara temi na. Beena iseda aye yi ti funwa ni ara ed ayi fun ise wa. asi ni ara to yato, asi huwa to yato. Konsepe ise teyin se ati ise timon se jora. Ise aja yato si t'okunrin Nitoripe ara aja yato si ara timo ni. Gbogbo wa. Beena dehino 'smin yathā dehe (BG 2.13). dehi, eda tabi agbara towa ninu ara yi.

Beena awa sin paaro ara eda yi. Dehino 'smin yathā dehe kaumāraṁ yauvanaṁ jarā (BG 2.13). asiko ojo-ori omo kekere nitumo Kaumaram. Omo-okurin nitumo Yauvanam, ati ojo arugbo nitumo jara. Beena mole ranti, arugbo nimi, mole ranti, nigbakan moni ara omo kekere, nigbakan moni ara omo- okurin. Nisin moti ni ara arugbo yi. Beena botilejepe ara omode yi ati ara omo okurin yi o si mo, sugbon mosi wa laaye. Otooro niyen. Gbogbo wa la ni oye eto yi. Oni asiko re toti koja, asiko re nisin ati ojo iwaju re. Beena omo okunrin at'obirin ni gbogbo yin tewa nibi. Beena eyin ti ni igba teyin je omo kekere, omode. beena eyin sini ara yin lojoowaju. On duro deyin, Moti ni ara na, sugon tiyin sin duro deyin. Beena lasiko to koja, lojoowaju, nisin ati loowaju, o le yewa ninu eyikeyi asiko ninu aye wa. nitorina ipari oro yi niwipe nigbati ara eda timo ni yi nisin... Aadorin odun ni iye ojo ori mi nisin. Beena nigbati ara eda yi batan, masi ri ara eda imi. Bi mose ni nisin, lati asiko omode si omo kekere, lati omo kekere si omo-okurin, si ara arugbo, beena kilode teyin o se ni gba ara imi? Otooro towa niwipe, awon eda, tabi eda, sin paaro ara eda kan si keji. Ofin to wa ninu eto imoye mimo leleyi. emi ni agbara ara eda. Ero lasan ko loje. Awon onisayensi aye isin won rowipe akojopo ohun elo aye yi lara wa je. pe nigbakan ni awon ohun elo aye yi dede mu bere sini huwa eda to wa laaye. Sugbon otooro ko niyen. Toba je oto, lehin na awon onisayensi sonle da aye sile pelu kemika. Sugbon tit di'sin awon onisayensi o le da ara kokoro gan sile, kama wa soro nipa awon eranko ton tobi gan.