YO/Prabhupada 0629 - We are Different Sons of God in Different Dresses



Lecture on BG 2.13 -- Pittsburgh, September 8, 1972

Beena lati ni imoye Krsna, agbdo ni oye nkan meta:

bhoktāraṁ yajña-tapasāṁ
sarva-loka-maheśvaram
suhṛdaṁ sarva-bhūtānāṁ
jñātvā māṁ śāntim ṛcchati
(BG 5.29)

Gbogbo wa lan gbiynaju lati ni idunnu. Ijakadi fun igbese aye yi. sugbon t'aba ni oye awon nkan ofin meta wanyi pe Oluwa nui baba wa to gaju, Oluwa nui onihun to gaju, ore to gaju, awon nkan meta wanyi, teyin ba ni oye na, lehin na eyin ma ni alafia lesekese. lesekese. Eyin wa ore toma ranyin lowo, to po. Sugbon teyin ba gba Oluwa, Krsna, bi ore, ore to gaju, gbogbo isoro yin ti tan. Beena t'wa ba gba Oluwa, bi onihun to gaju, gbogbo isoro wa titan. Nitorpe awa sin rowipe awa lani awon nkan aye yi toje pe Olorun loni> Awa sin sowipe Ile America leleyi, awon olugbe America lon ni; ile awon olugbe Africa leleyi. "Rara. Oluwa loni gbogbo ile wanyi. Awon omo orisiri Oluwa ninu orisirisi aso. Asi le gbadun oun ini baba wa, Oluwa, lai fun elomi ni isoro. Gege bi awon ebi, tan gbe pelu awon aburo wa. Beena, ounkoun ti baba, ati iya wa ba fun wa lawa ma je. Awa o kin je nkan telomi. Iwa to da koniyen. Beena, teyin ba ni imoye Olorun, imoye Krsna, lehin na isoro aye yi ma tan - etoo awujo, esin, aro aje, oselu - gbogbo nkan loma tan. Otooro niyen. Nitorina agbdo gbiyanju lati ti egbe imoye Krsna yi siwaju fun ijeere gbogbo awujo eda. Asin bere lowo awon eyan to logbon nipati awon akeeko, lati parapo pelu egbe yi, e gbiyanju lati ni oye nipa egbe yi. Awa si ni awon iwe to po gan, won to mejila. Beena ele ka awon iwe wanyi, lati ni oye nipa egbe yi, kesi parapo pelu wa.

Ese pupo. Hare Krsna. ( Atewo lati ajo)