YO/Prabhupada 0633 - We are just like the Shining Sparks of Krsna



Lecture on BG 2.28 -- London, August 30, 1973

Beena ipo aye yi lati aimokan emi loti wa wan se awon ise ese wansi looopo sinu re. Sugbon won o ni oye kankan bi won sele jade kuro ninu idimu yi. prakṣepātmika-śakti, āvaraṇātmika ti māyā leleyi. Botilejepe oti yipo sugbon osin rowipe oti ni ilosiwaju, ninu eto imoye sayensi. Imoye to ni niyen. Okurin jeje yi sin so funwa pe agbeho alumoni loje. Beena elero agbeho alumoni, ise ni lati je ki inu iho ton gbe wa gbigbe fun awon eyan ton sise ninu e. Se ti ri bayi, Oti wonu ile bi ile ekute, osi fe se ihoo yi dada. Lehin igba toti kawe tan pelu awon iwe-eri, ise toni ni lati wonu okunkun, iho ninu ile, osin sewaadi sayensi latii jeki ategun ninu iho na wa dada fun awon eyan ton sise ninu iho na. O ti fi ategun towa nita sile ategun ofe yi. Wanti dalebi pe oma wonu ile, inu re sin dun nitori iliosiwaju toni ninu eto sayensi. Nkan ton sele niyen. Ilosiwaju sayensi.

Beena manute anartham. Vyāsadeva niyen. Vyāsadeva,ko to ko Śrīmad-Bhāgavatam pelu itosona lati Nārada, osi sasaro lori ipo towa. Bhakti-yogena manasi, samyak praṇihite amale, apaśyat puruṣaṁ pūrṇaṁ, māyāṁ ca tad-apāśrayam (SB 1.7.4). O si ri wipe, awon nkan meji lowa: māyā ati Kṛṣṇa. Māyāṁ ca tad-apāśrayam. To ni idaabo lati Krsna. māyā yi o le duru laisi Krsna. Sugbon māyā o le se nkankan lori Krsna. Nitoripe kosi nkankan tole se Krsna, Sugbon awon eda laye yi, yayā sammohito jīva, awon eda laye yi, won wa labe oju maya. Sugbon kosi nkankan tole se Krsna. Gege bi orun ati ina orun. Itumo Ina orun ni akojo awon erunrun wanyi. Ina orun niyen. Awon oni sayensi ti jeerisi. ina sana. Beena, sana Krsna lawa na je. Bi orun ni Krsna se ri. Kṛṣṇa - sūrya-sama, māyā haya andhakāra. Nisin ti sanmo ba jade, maya, kole se nkankan fun orun. Sugbon awon erunrun kekere, o le se nkan si won. E gbiynaju lati ni oye oro yi. Orun leleyi, labe e aimoye milim awon sanmo wa. sanmo yi ti bo ina orun yi toje akojopo awon erunrun wanyi ton dan. Beena maya tabi sanmo yi kosi bosele bo orun, sugbon o le bo awon erunrun kekere ton dan. Beena o le kan wa, sugbon kole kan Krsna.