YO/Prabhupada 0671 - Enjoyment Means Two - Krishna and You

From Vanipedia
Jump to: navigation, search
Go-previous.png Previous Page - Video 0669
Next Page - Video 0706 Go-next.png

Enjoyment Means Two - Krishna and You - Prabhupāda 0671


Lecture on BG 6.16-24 -- Los Angeles, February 17, 1969

awon afokotun; ayi je apejuwa agbara eyon ti ole ri imo oye ti ara re ni mimo ni ole gbadun ifakanbale

prabhupada: okan mimo. eyi ni otumosi okan mimo okan mimo tumosi wipe ki ani oye imo ti ara wa, wipe a je ti krsna(olorun) eyi ni otumosi okan mimo ni asikoyi okan mi ko wa ni mimo, kilode? mon ronu wipe mo je ti eleyi, mo je ti eniyen, mo je ti ibeyen sugbon ti okan mi ba wa ni isora gerege, emi je ti krsna(olorun) eyi ni abo oye pipe mi, benii

awon afokansin...' lati gbadun tabi she ayeye ninu ara yi.ni ona yi awa ninu anailopin,

prabhupada: ayeye ni ara yi, je wipe krsna(olorun) ni oba gbogbo ara adase yoga. wipe moje emi eni kookan nigbati mowa ni samādhi pelu visnu oba gbogbo ara, eyini ifakanbale okan ti oba gbogbo ara ati ara yi ,ti wan ba gbadun, gbigbadun yi ko le je ti eyan kan, wan gbodo pe meji she iwo ti ri iriri ti eyan kan gbadun, rara ki eyan se ayeye nikan ko se nse, ayeye igbadun tumosi eyan meji-krsna(olorun) ati iwo oba gbogbo ara ati iwo, bi oshe ma rii niyen iwo ole gbadun fun ara e nikan,eyi ko see ipo re, benii tesiwaju

awon afakansin:eyon ti oba wa ni ona alailopin aduni ibukun, ti owa niifakanbale, gbadun ara re ninu oye isaro olorun ti aba se ise to si , eyon ko ni kuro ninu asha ododo, ti oba ti mo oye yi yio ri wipe ko si oye to oga ju eleyi lo ti eyan ba wa ninu ipo yi, ko ni ifoya, ti oba wa ninu isoro ti o ga julo

prabhupada: ninu isoro ti o ga, ti oba ni igbagbo wipe e mi je ara olorun(krsna) nitorinati isoro ti o ga ba wa ni ile aye e ,eyi ni iteriba o mo wipe krsna(olorun) yi o dabo bo e ki iwo gbiyanju ti ee, lo oye re, sugbon fi igbagbo si krsna(olorun) Bālasya neha pitarau nṛsiṁha (SB 7.9.19) ti krsna(olorun) ba gbagbe ee kosi owun kankan ti ole ran ee lowo kosi iwon kankan ti ole daabobo ee, ma ronu... je ka gba wipe eyan ti ku opolopo akose mose dokita ni o toju re ogun ti o dara ni won fun, lati le jeki aye re gun? rara eyi kole se ise duro ti krsna ba fisile, pelu gbogbo ogun ti dokita ba fun yio si ku benani ti krsna ba wa pelu re, to ko ba lo ogun kankan yio si ye eyon ti oba fi okan re si krsna(olorun) owun ni oni iteriba owun ti oshee pataki fun eyon ti oni iteriba fun krsna(olorun) ni wipe olorun Krsna yio daabobo inu re yio si dun bi omokekere bi omode se ni iteriba fun awon obi re, o si gbekele fun won baba mi wa nibe, iya mi wa ni be; bayi inure dun Kadāham aikāntika-nitya-kiṅkaraḥ (Stotra-ratna 43 / CC Madhya 1.206). ti iwo ba mo wipe eyon kan wa nibe ti oje atilehin, ti o je eyon ti oman gbawala ninu isoro kankan, se inu re ko ni dun sugbon ti oba se gbogbo owun funrare, se inu re dun bekanna, ti oba ni igbagbo ninu aisiji krsna, wipe krsna yio fun ni aabo ti o ba de wa ni igbagbo ninu krsna, eyi ni ofin ayo idunnu iwo ole ni idunu ayo,ni ibo miiran, eyi kos nse Eko bahūnāṁ vidadhāti kāmān (Kaṭha Upaniṣad 2.2.13). eyi ni koko oro na ti oba wa ni ipo ti ko daa krsna(olorun) si nse adabo bo ee ti krsna ko se adabo bo ee, iwo kole wa ni ile aye fun wakati kan krsna(olorun) ni anu topo, ti oba gbegbo, ti oba se aisiro re, nigbehin na iwo yio ni ayo nisin krsna daabo bo ee, sugbon iwo ko mo, nitoripe oti fi ile aye re si owo re nitorina o ti fun e ni ominiran, wipe ki o se owun kowun ti ofe se, ma si dabo bo ee sugbon ti oba se iteriba fun olorun, krsna yi o toju re, eyi ni o je adabo ti o je pataki be baba ati omo re, omo ti oba dagba ko ni toju baba ee, kini baba e le se? se owun ti ofe se sugbon omo ti owa ni adabo baba re, otoju dada won so eleyi ninu bhagavad gita, iwo ori,samo 'haṁ sarva-bhūteṣu (BG 9.29). mo dogba si gbogbo eyon Na me dveṣyaḥ; kosi eyon kankan ti o je ota mi bawo ni owa se ni ota? gbogbo eyon ni omo krsna bawo ni owa se je ota krsna(olorun)? oje omo olorun,eyi ko se nse, oje ore olorun sugbon agbodo se anfani,ofere si wa,eyi ni isaan wa, isaan aye yi oje ore gbogbo eyan, Samo 'haṁ sarva-bhūteṣu sugbon eyan to ba ranti ,ti oni oye, wipe krsna ni o n dabobo mi ni gbogbo ona eyi ni ayo aye ni ayo ile aye yii