YO/Prabhupada 0713 - The Busy Fool is Dangerous
Lecture on SB 1.16.23 -- Hawaii, January 19, 1974
kosi iwulo kankan pelu anfani lati tun ile aye yi nitoripe eyin o le gbe nibi. Eyin ni iwonba agbara Beena fun nkan imi ni agbara yi wa fun. Beena eyin o lo agbara yi fun nkan to wa fun, teba lo agbara yi fun igbadun ie aye yi... Niotooro kosi bi inu yin sefe dun. Bibeko, kilode ti awon omo-okurin at'obirin wanyi ni ibanuje? Nitoripe iru ilosiwaju yi kole funwa ni idunu. Otooro niyen. Nitorina, teba loasiko yin nilokulo fun awon nkan tio da, kosi besele ni ilosiwaju, ipadanu niyen Wan o mo.
Wanti salaaye ninu Śrīmad-Bhāgavatam. Parābhavas tāvad abodha-jāto yāvan na jijñāsata ātma-tattvam. Parabhava. Ipaadanu nitumo Parabhava. Tavat, "so long." Ipaadanu ni ise awon eyan ile aye yi je. Parābhavas tāvad abodha-jātaḥ. Aboda. Ode nitumo Abodha, oniranu, ode, asiwere, alaimokan. Ode ni gbogbo wa je. Beena t'awa o ba keko, ode lama je, beena ounkoun t'ode ba se ilokuklo asiko niyen je. Nitoripe.. Kilon pe? Awon oniranu ton sise gan. T'ode ban sise gan, ilokulo agbara re niyen. gege bi obo. Obo man sise gan. Nitooro, gege bi Darwin se so, lati awonh obo lonti wa. Ise obo ilokulo asiko niyen je. On sise gan. Nigbogbo igba lema ri ton sise. Ode ton sise gan alebu loje. Awon eyan merin lowa, awon ole to gbon, awon ologbon ton nise lowo, awon ole tio gbon ati awon ode tio nise lowo. Eyi to daju ni Ole to gbon. Gege bi awon adaju. Wan yole sugbon wan gbon. Eda to gaju nkiyen. Wan sise dada. ikeji ni eyi to gbon tosi nise lowo. Agbudo lo ogbon wa die die. Iketa ni ole tio gbon - ole tio si gbon na. Ikerin ni: ole toni ise lowo. Eleyi ni o da rara Gbogbo awon eyan wanyi, wani ise lowo. Ninu gbogbo awon orile-ede wanyi Wanti nji oko tio kin lo esin - "Hons, hons" ( ton se bi ariwo oko) gege bayi Sugbon niotooro, wan o logbon. Ode tonise lowo. Nitorina ni won sen da gbogbo isoro wanyi. Otooro niyen. Wan nise se, sugbon ode nigbogbo wan, nitorina lonse da isoro sile.