YO/Prabhupada 0715 - Become a Lover of God. This is First-Class Religion



Lecture on SB 1.16.25 -- Hawaii, January 21, 1974

Bhavān hi veda tat sarvaṁ yan māṁ dharmānupṛcchasi. Dharmaraja tabi Yamaraja je ikan ninu awon eyan mejila pataki ton toju awujo eda ofin dharma niyen. Esin konitumo Dharma Ise wa nitumo Dharma. Gbogbo wa lani ise tan se. beena dharmaṁ tu sākṣād bhagavat-praṇītam (SB 6.3.19). Olorun fun ara re lon fun wa ni ise yi. Tena tyaktena bhuñjīthāḥ (ISO 1). niotooro, ofin dharma yi, base ko lati Bhagavad-gita.... Krsna sowipe, sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66). Ema da esin yin sile, Isoro to wa niyen. Dharmaṁ tu sākṣād bhagavat-praṇītam (SB 6.3.19). Aimoye igba tati salaaye eto yi, pe isotunmo ti ede geesi fun dharma ni " esin" - Itunmo esin ni lati tele awon ofin Olorun. Esin ni yen. konse nkan ta daale Iru dharma bayi o le ranwa lowo. Nitorina, ninu Śrīmad-Bhāgavatam, ni ibere wan sowipe, dharmaḥ projjhita-kaitavo 'tra: (SB 1.1.2) " Awon esin ton yan awon eyan je, eti wa sita." Bhagavata-dharma leleyi. Kosejo iyanje. Ni oruko iyanje ati dharma, ofin esin, iru nkan bayi o le ran awujo eda lowo.

Olorun fun ara re ti salaaye nipa dharma gidi. Dharmaṁ tu sākṣād bhagavat-praṇītam (SB 6.3.19). Eyin o gbodo ko lati ibomi afi lat@olorun fun ara re Wanti salaaye dada ninu Bhagavd-gita, sarva-dharmān parityajya mām... (BG 18.66). Lati teriba fun Eledumare Olorun, esin ni yen. Lati teriba ni kan ko, sugbonlati se bosefe, bayi ema d'ololufe Olorun Esin ipo kini leleyi. Aimoye igba tati salaaye. Sa vai puṁsāṁ paro dharmo yato bhaktir adhokṣaje (SB 1.2.6). Iru esin tole ko yin besele d'ololufe Olorun l'esin to daju. teyin ba d'ololufe Olorun, ile aye yin ti ni ilosiwaju niyen. Ele se ounkoun fu Olorun. Bibeko, nigbogbo igba lema bere " kilode toye kin se bayi? Kilode toye kin se bayi...? Itumo re niwipe kosife kankan. Ikeko to wa niyen. Gege b'asele ko awon alaimokan, koni ife kankan, asi bere, " kilode toye kin se? Kilode toye kinse? Ijeere wo lowa?" Awon ibeere to po gan ma wa nibe Sugbon t'ife ba wa, koni si ibeere kankan. gege na Bhagavad-gita ti ko wa ni nkan to po, yoga, jñāna, karma ati orisirisi nkan to po lehin gbogbo e, Krsna sowipe, sarva-guhyatamam: "Nisin moti sofun yin ilana to daju." Kiniyen? Sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja... (BG 18.66). Asiri to gaju.