YO/Prabhupada 0724 - The Test of Bhakti



Lecture on SB 7.9.15 -- Mayapur, February 22, 1976

Ile aye yi je alebu nla fun awon olufokansi. Wan beru ibi gan. Iyato to wa niyen. Awon eyan ninu ile-aye yi. "Wan ronu pe ile aye yi dara. Awa gbadun. E jeun, ke mu, ke gbadun>" Sugbon awon olufokansi wan beru ibi. Bawo lasele jade kuro nib?" Guru Mahraja mi sowipe " Ile aye o da fun okurin jeje." Asi sowipe. " okurin jeje o le gbe ninu ile aye y." kole ye awon alainigbagbo bi ile aye yi se lee to. Duhkhala... Kṛṣṇa sowipe duḥkhālayam aśāśvatam (BG 8.15). Iyato laarin awon elesin ati awon alainigbagbo leleyi. duhkhalayam, wan fe jeko di sukhalayam. Kolese se.

Afi ti ile aye yi ba su wa, eyan na o le wonu imoye mimo Bhaktiḥ pareśānubhavo viraktir anyatra syāt (SB 11.2.42). idanwo bhakti leleyi. Teyan ba wonu ipo ise fun Olorun, ile aye yi ma su eni na. Virakti. kole si mo. Āra nāre bapa (?). Jagai-Madhai wansi feran ile aye yi gan, wan feran obirin, oloti niwan,wan si jeran... Awon nkan wanyi ti di nkan ti gbogbo awon eyan n'se. sugbon awon olufokansi sin beru gan Nitorina lawa se sowipe, " e ma moti, ema se imo ako ati abo laise igbeywao, ema jeran." Aya wa n'ja. Sugbon won o mo. Mūḍhaḥ nābhijānāti. Won o mo Won se lo. Gbogbo agbaye lon se. Won o mope nkan buru lon daaa le pelu gbogbo awon ese wanyi.

Beena lati jade kuru ninu awon iwa wanyi agbodo se tapasa, tapasya.

tapasā brahmacaryeṇa
śamena damena vā
tyāgena śauca...
yamena niyamena vā
(SB 6.1.13)

ILosiwaju ninu eto emi leleyi, tapasa. Nkan talakoko ni tapasya, pe afi nka aye yi sile. Nkan ton pe ni tapasya niyen. Tapasā brahmacaryeṇa. lati se tapasya yi, nka n talakoko ni brahmacarya. Lati ma se imo ako ati abo nitumo Brahmacarya. Nkan ton pe ni brahmacarya niyen.