YO/Prabhupada 0742 - Inconceivable Power of the Supreme Personality of Godhead



Lecture on CC Adi-lila 1.10 -- Mayapur, April 3, 1975

Nisin, ibeere to po wa: bawo ni okun wanyi se wa?" Awon oni sayensi sowipe akojopo hydrogen ati oxygen nibo ni afefe yi ti wa? Idaaun yi wa nibi. Lat'afefe yi l'omi tin jade. Teyan bati koko pel'omi ton h lori ina, teruko ba jade, ema ri omi die ninu e. Lati afefe yi l'omi tin jade, lat'omi na l'afefe tin jade. Iseda niyen.. Sugbon omi talakoko lati aagun Garbhodakaśāyī Viṣṇu loti wa. Gege beyin na sen laagun. Iwonda die ni aagun tole jade kuro ninu ara yin pelu oru ara. Awa ti jerisi. Teyin ba le yo iwonba omi die yi lat'ara yin, kilodde t'Olorun o le yo aimoye omi l'atara re? Kilole lati mo nibe? eda kekere leyin je, eyin si l'ara kekere. omi die lele mu jade lat'aagun yin. Olorun toni ara nla, kilode tikole da omi to po sile, Garbhodakaśāyī, omi garbhodaka? kosejo pe eyin o ni gbagbo.

Nkan ton pe ni acintya sakti leleyi, agbara to ju wa lo. Afi teyin ba gba wipe Olorun l'agbara yi, kosi itumo si Olorun. Teyin ba rowipe eyan bi eyin tab'emi... BEeni, bi eyin tabi emi, bi eyan na l'Orun je. Awon Veda ti sobe na: nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām (Kaṭha Upaniṣad 2.2.13). awon cetanas po gan, awon eda aye yi, wan wa tayeraye. Wan po gan, Nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām. sugbon nita imi wa, nityo nityānāṁ, meji. Ikan je eyokan, ikeji je meji. Kini iyato? Iyato to wa ni eko yo bahūnāṁ vidadhāti kāmān. Ikan soso yi lo lagbara ju nitoripe oun lon seto ti'keji. Awon eda aye yi nikeji, anantāya kalpate, eyin o le ka aduru eda rto wa nibe. sugbon t'alakoko yi lon toju wan. Oyato to wa niyen. Eyan l'Olorun je; eyan na leyin je; eyan na nimi. Gbogbo wa ti wa tayeraye, wanti salaye ninu Bhagavad-gita. Krsna sofun Arjuna pe " Ewo at'emi ati gbogbo awon oba wanyi ta kojo sibi, gbogbo wa lati wa teletele. Wanti wa tipe, wansi wa l'ojowaju." nityānāṁ cetanānām lon pewon.