YO/Prabhupada 0092 - A ni lati ko awon ipa ara wa lati se ife Olorun: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0092 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1968 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0023: VideoLocalizer - changed YouTube player to show hard-coded subtitles version)
 
Line 5: Line 5:
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, Seattle]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, Seattle]]
[[Category:YO-Quotes - in USA]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0091 - Duro sibi nihoho|0091|YO/Prabhupada 0093 - Bhagavad-gita tun je Krishna|0093}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 14: Line 18:

<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|N8Ob9ddXF6w|We Have to Train our Senses to Satisfy Kṛṣṇa - Prabhupāda 0092}}
{{youtube_right|WCDUusj97vU|We Have to Train our Senses to Satisfy Kṛṣṇa - Prabhupāda 0092}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->

<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/681014BG.SEA_clip.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/681014BG.SEA_clip.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 26: Line 30:

<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Enikeni ninu ile aye yi, gbogbo won ni won wa ninu ide igbadun ti ara. Boya ninu awon aye orun to ga tabi awon ti won kere. Gege bi ninu ijoba eranko iwuri ara wa nbe, bee na ni odo omo eniyan. Kini ohun ti omo eniyan je? A ti wa ni ilaju, Kini a nse? Ohun kanna. Jijeun, sisun, ibarasun. Ohun kanna bi aja se nse. Bee na nibi gbogbo ninu ile aye yi, boya ni aye to ga tabi ni aye to isale, igbadun ara yi lokiki. Ninu aye orun emi nikan ni ko si igbadun ara. Ilepa lati se ife Olorun nikan lo wa nbe. Iyen ni... Nibi gbogbo eniyan ngbiyanju lati se ife ara won. Iyen ni ofin ti ile aye ohun elo. Ile aye ohun elo l'eri yen. Ni iwon igba ti e ba ngbiyanju lati se ife ara yin, iyen je igbesi aye yin. Ati ni kete bi e ba ti yi ra yin pada lati se ife Olorun, iyen ni igbesi aye emi yin. O je ohun kan ti o rorun. Nipo ti a ba fi ma se ife... Hrsikena hrsikesa-sevanam ([[Vanisource:CC Madhya 19.170|CC Madhya 19.170]]). Iyen ni bhakti. E ti ni awon ipa ara. E ni lati telorun. Awon ipa ara, pelu awon ipa ara ni eni lati telorun. Boya e se itelorun ara yin... Sugbon eyin ko mo. Emi ti o wa ni ide ko mo wipe ise itelorun ti Olorun, ni ise itelorun ara eni lowo kanna. Apeere kanna. Bi a se nf'omi si idi... Tabi awon ika yi, won je ipa ara mi, Nipa fifi ounje fun inu, ni owo na ma fi ni itelorun lowo kanna. Asiri yi se wa ni airi. A nlero wipe inu wa ma dun nipa sise ife ti awon ipa ara. Isokan Olorun tumo si wipe, ma se gbiyanju lati se itelorun ara re. E gbiyanyu lati se ife Olorun; lowo kanna ni ara yin o ni itelorun. Eyi ni asiri isokan ti Olorun. Awon idakeji, awon nlero wipe, "Ah, kilode ti mo gbodo se itelorun enikan? Kini idi e ti mo gbodo sise fun Olorun ni gbogbo ojo ati ale? E je ki ngbiyanju fun awon karmis. Gege bi e se nse ise losan ati looru fun Olorun, won nro wipe, "Awon omugo wo ni yi. Awa ni oye gan. Awa nsise fun igbadun ara wa losan ati looru, ati kilode ti won sise fun Olorun? Eyi ni iyato laarin oluse-aye ati oluse-ti-emi. Ilepa onise-emi ni lati se ise loosan ati looru lagbara lagbara laisi iduro, fun Olorun nikan. Iyen ni ile aye-emi. Ati onise-aye tumo si ilepa kanna, ti won nfi gbogbo igba ngbiyanju lati te ra won lorun. Iyen ni iyato laarin onise-aye ati onise-emi. Bee ni egbe isokan Olorun tumo si wipe a ni lati ko awon ipa ara wa lati se ife Olorun. Ko ju yen lo. Ni iwon igba miran, tele tele, aimoye igba egbe gberun lona egbe egberun igbesi aye, a ti gbiyanju nikan lati se itelorun awon ipa ara wa, awon ipa ti ara eni. E je ki a fi aye yi jin fun ise itelorun ti Olorun. Iyen ni isokan Olorun. Igbesi aye kan. A ti, opolopo igbesi aye, ni a ti gbiyanju lati se itelorun ara wa. E je ki igbesi aye yi, bi o ti le kere igbesi aye kan, je ki ngbiyanju, ka si wo bo se ma ri. Bee ni a ki se onipadanu. Ti a ba tile mo inira pupo nipa aise itelorun ara wa, sugbon a ki se onipadanu. E gbiyanju lati se ife Olorun nikan; nigbana gbogbo nkan a si ni iyoju.
Enikeni ninu ile aye yi, gbogbo won ni won wa ninu ide igbadun ti ara. Boya ninu awon aye orun to ga tabi awon ti won kere. Gege bi ninu ijoba eranko iwuri ara wa nbe, bee na ni odo omo eniyan. Kini ohun ti omo eniyan je? A ti wa ni ilaju, Kini a nse? Ohun kanna. Jijeun, sisun, ibarasun. Ohun kanna bi aja se nse. Bee na nibi gbogbo ninu ile aye yi, boya ni aye to ga tabi ni aye to isale, igbadun ara yi lokiki. Ninu aye orun emi nikan ni ko si igbadun ara. Ilepa lati se ife Olorun nikan lo wa nbe. Iyen ni... Nibi gbogbo eniyan ngbiyanju lati se ife ara won. Iyen ni ofin ti ile aye ohun elo. Ile aye ohun elo l'eri yen. Ni iwon igba ti e ba ngbiyanju lati se ife ara yin, iyen je igbesi aye yin. Ati ni kete bi e ba ti yi ra yin pada lati se ife Olorun, iyen ni igbesi aye emi yin. O je ohun kan ti o rorun. Nipo ti a ba fi ma se ife... Hrsikena hrsikesa-sevanam ([[Vanisource:CC Madhya 19.170|CC Madhya 19.170]]). Iyen ni bhakti.  
 
E ti ni awon ipa ara. E ni lati telorun. Awon ipa ara, pelu awon ipa ara ni eni lati telorun. Boya e se itelorun ara yin... Sugbon eyin ko mo. Emi ti o wa ni ide ko mo wipe ise itelorun ti Olorun, ni ise itelorun ara eni lowo kanna. Apeere kanna. Bi a se nf'omi si idi... Tabi awon ika yi, won je ipa ara mi, Nipa fifi ounje fun inu, ni owo na ma fi ni itelorun lowo kanna. Asiri yi se wa ni airi. A nlero wipe inu wa ma dun nipa sise ife ti awon ipa ara. Isokan Olorun tumo si wipe, ma se gbiyanju lati se itelorun ara re. E gbiyanyu lati se ife Olorun; lowo kanna ni ara yin o ni itelorun. Eyi ni asiri isokan ti Olorun. Awon idakeji, awon nlero wipe, "Ah, kilode ti mo gbodo se itelorun enikan? Kini idi e ti mo gbodo sise fun Olorun ni gbogbo ojo ati ale? E je ki ngbiyanju fun awon karmis. Gege bi e se nse ise losan ati looru fun Olorun, won nro wipe, "Awon omugo wo ni yi. Awa ni oye gan. Awa nsise fun igbadun ara wa losan ati looru, ati kilode ti won sise fun Olorun?  
 
Eyi ni iyato laarin oluse-aye ati oluse-ti-emi. Ilepa onise-emi ni lati se ise loosan ati looru lagbara lagbara laisi iduro, fun Olorun nikan. Iyen ni ile aye-emi. Ati onise-aye tumo si ilepa kanna, ti won nfi gbogbo igba ngbiyanju lati te ra won lorun. Iyen ni iyato laarin onise-aye ati onise-emi. Bee ni egbe isokan Olorun tumo si wipe a ni lati ko awon ipa ara wa lati se ife Olorun. Ko ju yen lo. Ni iwon igba miran, tele tele, aimoye igba egbe gberun lona egbe egberun igbesi aye, a ti gbiyanju nikan lati se itelorun awon ipa ara wa, awon ipa ti ara eni. E je ki a fi aye yi jin fun ise itelorun ti Olorun. Iyen ni isokan Olorun. Igbesi aye kan. A ti, opolopo igbesi aye, ni a ti gbiyanju lati se itelorun ara wa. E je ki igbesi aye yi, bi o ti le kere igbesi aye kan, je ki ngbiyanju, ka si wo bo se ma ri. Bee ni a ki se onipadanu. Ti a ba tile mo inira pupo nipa aise itelorun ara wa, sugbon a ki se onipadanu. E gbiyanju lati se ife Olorun nikan; nigbana gbogbo nkan a si ni iyoju.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 18:55, 14 October 2018

Lecture on BG 2.20-25 -- Seattle, October 14, 1968

Enikeni ninu ile aye yi, gbogbo won ni won wa ninu ide igbadun ti ara. Boya ninu awon aye orun to ga tabi awon ti won kere. Gege bi ninu ijoba eranko iwuri ara wa nbe, bee na ni odo omo eniyan. Kini ohun ti omo eniyan je? A ti wa ni ilaju, Kini a nse? Ohun kanna. Jijeun, sisun, ibarasun. Ohun kanna bi aja se nse. Bee na nibi gbogbo ninu ile aye yi, boya ni aye to ga tabi ni aye to isale, igbadun ara yi lokiki. Ninu aye orun emi nikan ni ko si igbadun ara. Ilepa lati se ife Olorun nikan lo wa nbe. Iyen ni... Nibi gbogbo eniyan ngbiyanju lati se ife ara won. Iyen ni ofin ti ile aye ohun elo. Ile aye ohun elo l'eri yen. Ni iwon igba ti e ba ngbiyanju lati se ife ara yin, iyen je igbesi aye yin. Ati ni kete bi e ba ti yi ra yin pada lati se ife Olorun, iyen ni igbesi aye emi yin. O je ohun kan ti o rorun. Nipo ti a ba fi ma se ife... Hrsikena hrsikesa-sevanam (CC Madhya 19.170). Iyen ni bhakti.