YO/Prabhupada 0335 - Educating People to Become First-class Yogi: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0335 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1972 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in India, Hyderabad]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Hyderabad]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0334 - The Real Necessity of Life is to Supply the Comforts of the Soul|0334|YO/Prabhupada 0336 - How is it, They are Mad After God?|0336}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 19: Line 22:

<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/721128BG.HYD_clip.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/721128BG.HYD_clip.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 27: Line 30:

<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
awon brahmana man gbadura si Krsna: " Oluwa mi moti iranse awo iye ara mi" Nibi gbogbo eyan ti di iranse si iye ara wan.. Wanfe gbadun ara wan. Igbadun ko - wanfe sise fun iye ara wan. Ahon mi asowipe, " Mumi losi iru ile-ounje bayi bayi, mofe je obe adiye." Lesekese ni moma lo. Igbadun ko, sugbon mon jise ahon mi. nitorina awon kan sise fu awon iye-ara wa, pe awan gbadun. ni ede Sanskrit wan pe ni go-dasa. Oye-ara nitumo Go Afi teyin ba di gosvai, ile-aye yin ti baje. Gosvami. Kosi besele feti si ase awon iye ara. Egbudo p'ase fun iye-ara yin. Lesekese ti ahon yin ba sowipe mumi losi ile-ounje bayi bayi kin ba le fa siga," teba sowipe, "rara, kosi siga kanka, kosi ile-oujne kankan, afi Krsna-prasada, lehin na a le sowipe gosvai leje. Gosvami leje. Awon amuye to wa niyuen, sanatana. Nitoripe emi ni iranse tayeraye Krsna. kan ton pe ni sanatana-dharma niyen. awa ti salaaye ninu Ajāmila-upākhyāna. Ale de ipo yi. Tapasā brahmacaryeṇa śamena damena śaucena tyāgena yamena niyamena ([[Vanisource:SB 6.1.13|SB 6.1.13]]).
awon brahmana man gbadura si Krsna: " Oluwa mi moti iranse awo iye ara mi" Nibi gbogbo eyan ti di iranse si iye ara wan.. Wanfe gbadun ara wan. Igbadun ko - wanfe sise fun iye ara wan. Ahon mi asowipe, " Mumi losi iru ile-ounje bayi bayi, mofe je obe adiye." Lesekese ni moma lo. Igbadun ko, sugbon mon jise ahon mi. nitorina awon kan sise fu awon iye-ara wa, pe awan gbadun. ni ede Sanskrit wan pe ni go-dasa. Oye-ara nitumo Go Afi teyin ba di gosvai, ile-aye yin ti baje. Gosvami. Kosi besele feti si ase awon iye ara. Egbudo p'ase fun iye-ara yin. Lesekese ti ahon yin ba sowipe mumi losi ile-ounje bayi bayi kin ba le fa siga," teba sowipe, "rara, kosi siga kanka, kosi ile-oujne kankan, afi Krsna-prasada, lehin na a le sowipe gosvai leje. Gosvami leje. Awon amuye to wa niyuen, sanatana. Nitoripe emi ni iranse tayeraye Krsna. kan ton pe ni sanatana-dharma niyen. awa ti salaaye ninu Ajāmila-upākhyāna. Ale de ipo yi. Tapasā brahmacaryeṇa śamena damena śaucena tyāgena yamena niyamena ([[Vanisource:SB 6.1.13-14|SB 6.1.13]]).

Nitorina lati ni idari lori iye-ara wa nidi fun awon iwe Veda. Yoga. Yoga indriya-saṁyama. Yoga niyen. Lati fi agbara idna han awon eyan ko nitumo Yoga. Agbar Idan lati ipo to gaju leleyi. teyin ba se yoga... moti ri awon ton pe ara wan ni yogi sugbon wan o le fi ipari si siga fiafa. se ri bayi. Wan fa siga ati orisirisi nkan. Sugbon wan peran wan ni yogi. Iru yogi wo leleyi? Eyan tole ni idari lori iye-ara re ni yogi. Śamena damena brahmacaryeṇa. Ninu Bhagavad-gita wa nti salaaye ninu apa iwe ton soro nipa awon eto yoga. odun egberun marun seyin, Arjuna ti gbo nipa eto yoga yi, basele ni'dari lori awon iye ara wa. grhastha ati oniselu loje, nitoripe, o wa ninu ebi awon oba. Osin jagun lati ni isegun fun ijoba re. Arjuna si sowipe , " Krsna niotooro, emi o le di yogi, nitoripe ise to le gan niyen. Eyin fe kin joko sibi kan, ni ile mimo, kin joko pelu ara to na, kin si wo imu mi, orisirisi nkan.. emi o le se." O sope oun o le se. Krsna lati jeki inu ore ati elesin re dun O mowipe Inu Arjuna ti baje. Osi sowipe aoun o le se. Niotooro oniselu loje, bawo lose fe di yogi? Sugbon oniselu lasiko wayi, wan se yoga. Iru yoga wo leleyi? Se awon eyan yi ti da ju arjuna lo? Ninu asiko alebu ta wayi? L'odun egberun marun seyin, nigbati awon nkan si da Nisin awon nkan to baje, esi fe di yogi? Kolese se. Kṛte yad dhyāyato viṣṇum ([[Vanisource:SB 12.3.52|SB 12.3.52]]). Itumo yoga ni lati sasaro lori Visnu. O sese ni Satya-yuga. Gege bi Valmiki. O sasaro fun odun oke-meta, lehin o di pipe. talo ma wa laye fun odun oke-meta? kolese se. Lati jekinu re dun, Krsna... Oti salaaye idi fun yoga si Arjuna,

Line 35: Line 38:
:śraddhāvān bhajate yo māṁ
:śraddhāvān bhajate yo māṁ
:sa me yuktatamo mataḥ
:sa me yuktatamo mataḥ
:([[Vanisource:BG 6.47|BG 6.47]])
:([[Vanisource:BG 6.47 (1972)|BG 6.47]])

Tani yogi to gaju? Yoginām api sarveṣāṁ mad-gatenāntar-ātmanā. Ton ronu nioa mi nigbogbo gba, Krsna.
Tani yogi to gaju? Yoginām api sarveṣāṁ mad-gatenāntar-ātmanā. Ton ronu nioa mi nigbogbo gba, Krsna.
Line 45: Line 48:
:sa guṇān samatītyaitān
:sa guṇān samatītyaitān
:brahma-bhūyāya kalpate
:brahma-bhūyāya kalpate
:([[Vanisource:BG 14.26|BG 14.26]])
:([[Vanisource:BG 14.26 (1972)|BG 14.26]])

enito tini imo ara re, brahma-bhūta, ([[Vanisource:SB 4.30.20|SB 4.30.20]]) brahma-bhūtaḥ prasannātmā ([[Vanisource:BG 18.54|BG 18.54]]), kilo kun fun? Ipinnu aye yi niyen, lati di ahaṁ brahmāsmi. Awon iwe Veda ti ko wa pe," Ema rowipe ara yi leje. Brahman leje." Krsna ni Para-brahman, brahman kekere ni gbogbo wa je. Nitya-kṛṣṇa-dāsa. Iranse Brahman niwa. Ouni Olori Brahman. Sugon dipo tama ronu wipe emi ni iranse Brahman awa fe ronu pe Olori Brahman niwa. Itanra eni niyen. Itara eni imi.
enito tini imo ara re, brahma-bhūta, ([[Vanisource:SB 4.30.20|SB 4.30.20]]) brahma-bhūtaḥ prasannātmā ([[Vanisource:BG 18.54 (1972)|BG 18.54]]), kilo kun fun? Ipinnu aye yi niyen, lati di ahaṁ brahmāsmi. Awon iwe Veda ti ko wa pe," Ema rowipe ara yi leje. Brahman leje." Krsna ni Para-brahman, brahman kekere ni gbogbo wa je. Nitya-kṛṣṇa-dāsa. Iranse Brahman niwa. Ouni Olori Brahman. Sugon dipo tama ronu wipe emi ni iranse Brahman awa fe ronu pe Olori Brahman niwa. Itanra eni niyen. Itara eni imi.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 23:50, 13 June 2018

Lecture on BG 2.24 -- Hyderabad, November 28, 1972

awon brahmana man gbadura si Krsna: " Oluwa mi moti iranse awo iye ara mi" Nibi gbogbo eyan ti di iranse si iye ara wan.. Wanfe gbadun ara wan. Igbadun ko - wanfe sise fun iye ara wan. Ahon mi asowipe, " Mumi losi iru ile-ounje bayi bayi, mofe je obe adiye." Lesekese ni moma lo. Igbadun ko, sugbon mon jise ahon mi. nitorina awon kan sise fu awon iye-ara wa, pe awan gbadun. ni ede Sanskrit wan pe ni go-dasa. Oye-ara nitumo Go Afi teyin ba di gosvai, ile-aye yin ti baje. Gosvami. Kosi besele feti si ase awon iye ara. Egbudo p'ase fun iye-ara yin. Lesekese ti ahon yin ba sowipe mumi losi ile-ounje bayi bayi kin ba le fa siga," teba sowipe, "rara, kosi siga kanka, kosi ile-oujne kankan, afi Krsna-prasada, lehin na a le sowipe gosvai leje. Gosvami leje. Awon amuye to wa niyuen, sanatana. Nitoripe emi ni iranse tayeraye Krsna. kan ton pe ni sanatana-dharma niyen. awa ti salaaye ninu Ajāmila-upākhyāna. Ale de ipo yi. Tapasā brahmacaryeṇa śamena damena śaucena tyāgena yamena niyamena (SB 6.1.13).

Nitorina lati ni idari lori iye-ara wa nidi fun awon iwe Veda. Yoga. Yoga indriya-saṁyama. Yoga niyen. Lati fi agbara idna han awon eyan ko nitumo Yoga. Agbar Idan lati ipo to gaju leleyi. teyin ba se yoga... moti ri awon ton pe ara wan ni yogi sugbon wan o le fi ipari si siga fiafa. se ri bayi. Wan fa siga ati orisirisi nkan. Sugbon wan peran wan ni yogi. Iru yogi wo leleyi? Eyan tole ni idari lori iye-ara re ni yogi. Śamena damena brahmacaryeṇa. Ninu Bhagavad-gita wa nti salaaye ninu apa iwe ton soro nipa awon eto yoga. odun egberun marun seyin, Arjuna ti gbo nipa eto yoga yi, basele ni'dari lori awon iye ara wa. grhastha ati oniselu loje, nitoripe, o wa ninu ebi awon oba. Osin jagun lati ni isegun fun ijoba re. Arjuna si sowipe , " Krsna niotooro, emi o le di yogi, nitoripe ise to le gan niyen. Eyin fe kin joko sibi kan, ni ile mimo, kin joko pelu ara to na, kin si wo imu mi, orisirisi nkan.. emi o le se." O sope oun o le se. Krsna lati jeki inu ore ati elesin re dun O mowipe Inu Arjuna ti baje. Osi sowipe aoun o le se. Niotooro oniselu loje, bawo lose fe di yogi? Sugbon oniselu lasiko wayi, wan se yoga. Iru yoga wo leleyi? Se awon eyan yi ti da ju arjuna lo? Ninu asiko alebu ta wayi? L'odun egberun marun seyin, nigbati awon nkan si da Nisin awon nkan to baje, esi fe di yogi? Kolese se. Kṛte yad dhyāyato viṣṇum (SB 12.3.52). Itumo yoga ni lati sasaro lori Visnu. O sese ni Satya-yuga. Gege bi Valmiki. O sasaro fun odun oke-meta, lehin o di pipe. talo ma wa laye fun odun oke-meta? kolese se. Lati jekinu re dun, Krsna... Oti salaaye idi fun yoga si Arjuna,

yoginām api sarveṣāṁ
mad-gatenāntar-ātmanā
śraddhāvān bhajate yo māṁ
sa me yuktatamo mataḥ
(BG 6.47)

Tani yogi to gaju? Yoginām api sarveṣāṁ mad-gatenāntar-ātmanā. Ton ronu nioa mi nigbogbo gba, Krsna.

Egbe imoye Krsna yi sin ko wa basele di awon yogi to gaju. E ronu nipa Krsna. Hare Kṛṣṇa, Hare Kṛṣṇa, Kṛṣṇa Kṛṣṇa, Hare Hare/ Hare Rāma, Hare Rāma, Rāma Rāma, Hare Hare. konse nkan eke. Otoooro loje. Eledi yogi. Eledi Brahman. Brahma-bhūyāya kalpate.

māṁ ca yo 'vyabhicāreṇa
bhakti-yogena sevate
sa guṇān samatītyaitān
brahma-bhūyāya kalpate
(BG 14.26)

enito tini imo ara re, brahma-bhūta, (SB 4.30.20) brahma-bhūtaḥ prasannātmā (BG 18.54), kilo kun fun? Ipinnu aye yi niyen, lati di ahaṁ brahmāsmi. Awon iwe Veda ti ko wa pe," Ema rowipe ara yi leje. Brahman leje." Krsna ni Para-brahman, brahman kekere ni gbogbo wa je. Nitya-kṛṣṇa-dāsa. Iranse Brahman niwa. Ouni Olori Brahman. Sugon dipo tama ronu wipe emi ni iranse Brahman awa fe ronu pe Olori Brahman niwa. Itanra eni niyen. Itara eni imi.