YO/Prabhupada 0401 - The Purport Excerpt to Sri Sri Siksastakam: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0401 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1968 Category:YO-Quotes - Pu...")
 
No edit summary
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in USA, Los Angeles]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, Los Angeles]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0400 - The Purport to Sri Sri Siksastakam|0400|YO/Prabhupada 0402 - The Purport to Vibhavari Sesa|0402}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 19: Line 22:


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>File:V14-6_681228PU_LA_sri_sri_siksastakam_purport.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/purports_and_songs/V14-6_681228PU_LA_sri_sri_siksastakam_purport.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->



Latest revision as of 06:21, 17 February 2019



Purport Excerpt to Sri Sri Siksastakam -- Los Angeles, December 28, 1968

Oluwa Caitanya Mahāprabhu ti salaaye fun awon akeko re lati ko awon iwe lori sayensi nipa imoye Krsna. Ise ti awon olufokansi sin se titi di ojo oni. Isotunmo ati ijuwe lori imoye ti Oluwa Caitanya, si je imoye to se pipe ju, nitori asa ona ti awon akeko ati oluko ni aye yi. Sugbon Oluwa Caitanya toje alakowe giga nigba ojo idodo re, kosi ko ju ese iwe mejo lo tonpe ni Śikṣāṣṭaka.

gbogbo ogo fun śrī-kṛṣṇa-saṅkīrtana, ton nu okan wa lati gbogbo idoti toti koja lati gbogbo odun seyin. Nitorina ina ile aye yi, ton mu si iyika ibimo ati iku ti paare. Ese iwe keji. Oluwa mi oruko yin nikan le fun gbogbo awon eda aye yi n'ibukun, nitorina eyin si ni aimoye oruko bi Krsna, Govinda, bayi bayi lo. Ninu awon oruko mimo re yi, eti fi agbara mimo yin sinu gbogbo won, kode si ofin tole kankan ta gbodo ni lati le korin oruko yin. Oluwa mi, E ti se ko rorun lati summon yin pelu oruko yin, sugbon nitorioe mio ni ori re kankan, mio ni ifarasi won. Iketa. Eyan le korin oruko Olorun pelu okan to resile, toba si ronu nipa ara re bi eni loju titi, kosi ni suuru ju igi lo, lai ni igberaga kankan, kosi mo lati bowo fun awon eyan. pelu okan bayi leyan le korin oruko Olorun dada.