YO/Prabhupada 0502 - Give up Nonsense Conceptions - Take the Broader Life of Krishna Consciousness: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0502 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1972 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in India, Hyderabad]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Hyderabad]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0501 - We Cannot be Anxiety-free Unless we Come to Krishna Consciousness|0501|YO/Prabhupada 0503 - To Accept Guru Means to Inquire from Him About the Absolute Truth|0503}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 19: Line 22:


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/721121BG.HYD_clip6.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/721121BG.HYD_clip6.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 27: Line 30:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Prahlāda Mahārā ti salaaye funwa, efi gbogbo iranu yi sile Vanaṁ gato yad dharim āśrayeta ([[Vanisource:SB 7.5.5|SB 7.5.5]]). vanaṁ gataḥ, Itumo re niwipe agbudo jade kuro ninu aye gṛham andha-kūpam Egba imoye Krsna sokan, Inuyin asi dun. Hitvātma-pātaṁ gṛham andha-kūpaṁ vanaṁ gato yad dharim āśrayeta ([[Vanisource:SB 7.5.5|SB 7.5.5]]). Harim āśrayeta. harim āśrayeta ni ise tawa ni. Vanaṁ gataḥ. elosinu oko ni itumo Vanaṁ gataḥ. Teletele inu oko ni awon gṛhastha , vānaprastha ati sannyāsa n'gbe. sugon ati losinu oko ko ni igbese aye wa. Orisirisi eranko lowa ninu oko, seyen sowipe wan ni ilosiwaju ninu aye mimo? Nkan tonpe ni markaṭa-vairāgya. Iwa oobo ni itumo Markaṭa-vairāgya Awon Oobo tusi ihoho. Nāga-bābā wansi je awon eso, wansi gbe labe igi. sugbon oni iyawo to koja mejila. Iru iwa markaṭa-vairāgya, kole ranwa lowo. Itumo Ipati-nkan aye yi niwipe agbudo fi aye andha-kupa sile, agbudo teriba fun Kṛṣṇa, harim āśrayeta. teba teriba fun Krsna lehin na lele fi'ipari si gbogbo awon nkan bayi. Bibeko, kole sese. ema bosinu awon ejo repete laye yi. hitvātma-pātaṁ gṛham andha-kūpaṁ vanaṁ gato yad dharim āśrayeta ([[Vanisource:SB 7.5.5|SB 7.5.5]]) teba fi nkan sile, egbudo gba bkan mi. bibeko, idamu ma muyin. bon se salaaye niyen: paraṁ dṛṣṭvā nivartate ([[Vanisource:BG 2.59|BG 2.59]]). ele fi awon ebiyin, aye awujo, aye oselu, ati gbogbo nkan ten se sile teba mu imoye Krsna yi s'okan. Bibeko kole sese. Bibeko egbudo gba aye yi, kosejo ominiran. kosejo igbala lowo gbogbo isoro aye yi. ilana towa niyen.
Prahlāda Mahārā ti salaaye funwa, efi gbogbo iranu yi sile Vanaṁ gato yad dharim āśrayeta ([[Vanisource:SB 7.5.5|SB 7.5.5]]). vanaṁ gataḥ, Itumo re niwipe agbudo jade kuro ninu aye gṛham andha-kūpam Egba imoye Krsna sokan, Inuyin asi dun. Hitvātma-pātaṁ gṛham andha-kūpaṁ vanaṁ gato yad dharim āśrayeta ([[Vanisource:SB 7.5.5|SB 7.5.5]]). Harim āśrayeta. harim āśrayeta ni ise tawa ni. Vanaṁ gataḥ. elosinu oko ni itumo Vanaṁ gataḥ. Teletele inu oko ni awon gṛhastha , vānaprastha ati sannyāsa n'gbe. sugon ati losinu oko ko ni igbese aye wa. Orisirisi eranko lowa ninu oko, seyen sowipe wan ni ilosiwaju ninu aye mimo? Nkan tonpe ni markaṭa-vairāgya. Iwa oobo ni itumo Markaṭa-vairāgya Awon Oobo tusi ihoho. Nāga-bābā wansi je awon eso, wansi gbe labe igi. sugbon oni iyawo to koja mejila. Iru iwa markaṭa-vairāgya, kole ranwa lowo. Itumo Ipati-nkan aye yi niwipe agbudo fi aye andha-kupa sile, agbudo teriba fun Kṛṣṇa, harim āśrayeta. teba teriba fun Krsna lehin na lele fi'ipari si gbogbo awon nkan bayi. Bibeko, kole sese. ema bosinu awon ejo repete laye yi. hitvātma-pātaṁ gṛham andha-kūpaṁ vanaṁ gato yad dharim āśrayeta ([[Vanisource:SB 7.5.5|SB 7.5.5]]) teba fi nkan sile, egbudo gba bkan mi. bibeko, idamu ma muyin. bon se salaaye niyen: paraṁ dṛṣṭvā nivartate ([[Vanisource:BG 2.59 (1972)|BG 2.59]]). ele fi awon ebiyin, aye awujo, aye oselu, ati gbogbo nkan ten se sile teba mu imoye Krsna yi s'okan. Bibeko kole sese. Bibeko egbudo gba aye yi, kosejo ominiran. kosejo igbala lowo gbogbo isoro aye yi. ilana towa niyen.


tattva-darśibhiḥ, nkankan niyen awon eyan to mo nipa otito to gaju... Vedānta-sūtra... ti sofun wa wipe athāto brahma jijñāsā, Ni aana, omo okurin kan si beere lowo mi: Kini itumo Vedanta, kini itumo Vedanta?" O rorun gan. Imoye ni itumo Veda, to gaju ni itumo anta. gege na imoye to gaju ni itumo Vedanta. Krsna deni imoye yi. Krsna sowipe, vedaiś ca sarvair aham eva vedyo vedānta-kṛd veda-vid ca aham. Oun lo da Vedanta sile, oun lode mo na. bawo losele ko Vedanta tobajepe oun ko lo mo? Ni otooro Vyasadeva lo ko awon Vedanta, nkankana lje pelu Krsna. vedānta-kṛt ati vedānta-vit loje. Ibeere to wa niwipe se advaita-vada tabi dvaita-vada ni itumo Vedanta? osi rorun lati mo. Oro alakoko ninu Vedanta: athāto brahma jijñāsā, lati mo nipa Brahman, otito to gaju. nibo lama beere? Egbudo losodo eyan to mo, teba fe beere. nitorina ni apa mejeji yi sewa ni ibere Vedānta-sūtra, Eyan gbudo beere, osi gbudo daaun. Athāto brahma jijñāsā. Ninu Vedānta-sūtra bawo lese femo toba je advaita-vada? dvaita-vada loje lati'bere. Athāto brahma jijñāsā Eyan gbudo beere kini Brahman, asi gbudo daaun, tabi Oluko, tabi akeko. apa mejeji niyen. bawo lese femo tobaje advaita-vada? agbudo keko nipa eto na. Nibi wan sowipe,tattva-darśibhiḥ. itumo tattva-darśibhiḥ ni vedānta-vit, tabi eyan toba mo Vedānta. Janmādy asya yataḥ ([[Vanisource:SB 1.1.1|SB 1.1.1]]). enikeni toba mo nipa otito to gaju latibi ti gbogbo nkan ti bere. Janmādy asya yataḥ. Ibere Śrīmad-Bhāgavatam niyen.
tattva-darśibhiḥ, nkankan niyen awon eyan to mo nipa otito to gaju... Vedānta-sūtra... ti sofun wa wipe athāto brahma jijñāsā, Ni aana, omo okurin kan si beere lowo mi: Kini itumo Vedanta, kini itumo Vedanta?" O rorun gan. Imoye ni itumo Veda, to gaju ni itumo anta. gege na imoye to gaju ni itumo Vedanta. Krsna deni imoye yi. Krsna sowipe, vedaiś ca sarvair aham eva vedyo vedānta-kṛd veda-vid ca aham. Oun lo da Vedanta sile, oun lode mo na. bawo losele ko Vedanta tobajepe oun ko lo mo? Ni otooro Vyasadeva lo ko awon Vedanta, nkankana lje pelu Krsna. vedānta-kṛt ati vedānta-vit loje. Ibeere to wa niwipe se advaita-vada tabi dvaita-vada ni itumo Vedanta? osi rorun lati mo. Oro alakoko ninu Vedanta: athāto brahma jijñāsā, lati mo nipa Brahman, otito to gaju. nibo lama beere? Egbudo losodo eyan to mo, teba fe beere. nitorina ni apa mejeji yi sewa ni ibere Vedānta-sūtra, Eyan gbudo beere, osi gbudo daaun. Athāto brahma jijñāsā. Ninu Vedānta-sūtra bawo lese femo toba je advaita-vada? dvaita-vada loje lati'bere. Athāto brahma jijñāsā Eyan gbudo beere kini Brahman, asi gbudo daaun, tabi Oluko, tabi akeko. apa mejeji niyen. bawo lese femo tobaje advaita-vada? agbudo keko nipa eto na. Nibi wan sowipe,tattva-darśibhiḥ. itumo tattva-darśibhiḥ ni vedānta-vit, tabi eyan toba mo Vedānta. Janmādy asya yataḥ ([[Vanisource:SB 1.1.1|SB 1.1.1]]). enikeni toba mo nipa otito to gaju latibi ti gbogbo nkan ti bere. Janmādy asya yataḥ. Ibere Śrīmad-Bhāgavatam niyen.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:05, 14 June 2018



Lecture on BG 2.15 -- Hyderabad, November 21, 1972

Prahlāda Mahārā ti salaaye funwa, efi gbogbo iranu yi sile Vanaṁ gato yad dharim āśrayeta (SB 7.5.5). vanaṁ gataḥ, Itumo re niwipe agbudo jade kuro ninu aye gṛham andha-kūpam Egba imoye Krsna sokan, Inuyin asi dun. Hitvātma-pātaṁ gṛham andha-kūpaṁ vanaṁ gato yad dharim āśrayeta (SB 7.5.5). Harim āśrayeta. harim āśrayeta ni ise tawa ni. Vanaṁ gataḥ. elosinu oko ni itumo Vanaṁ gataḥ. Teletele inu oko ni awon gṛhastha , vānaprastha ati sannyāsa n'gbe. sugon ati losinu oko ko ni igbese aye wa. Orisirisi eranko lowa ninu oko, seyen sowipe wan ni ilosiwaju ninu aye mimo? Nkan tonpe ni markaṭa-vairāgya. Iwa oobo ni itumo Markaṭa-vairāgya Awon Oobo tusi ihoho. Nāga-bābā wansi je awon eso, wansi gbe labe igi. sugbon oni iyawo to koja mejila. Iru iwa markaṭa-vairāgya, kole ranwa lowo. Itumo Ipati-nkan aye yi niwipe agbudo fi aye andha-kupa sile, agbudo teriba fun Kṛṣṇa, harim āśrayeta. teba teriba fun Krsna lehin na lele fi'ipari si gbogbo awon nkan bayi. Bibeko, kole sese. ema bosinu awon ejo repete laye yi. hitvātma-pātaṁ gṛham andha-kūpaṁ vanaṁ gato yad dharim āśrayeta (SB 7.5.5) teba fi nkan sile, egbudo gba bkan mi. bibeko, idamu ma muyin. bon se salaaye niyen: paraṁ dṛṣṭvā nivartate (BG 2.59). ele fi awon ebiyin, aye awujo, aye oselu, ati gbogbo nkan ten se sile teba mu imoye Krsna yi s'okan. Bibeko kole sese. Bibeko egbudo gba aye yi, kosejo ominiran. kosejo igbala lowo gbogbo isoro aye yi. ilana towa niyen.

tattva-darśibhiḥ, nkankan niyen awon eyan to mo nipa otito to gaju... Vedānta-sūtra... ti sofun wa wipe athāto brahma jijñāsā, Ni aana, omo okurin kan si beere lowo mi: Kini itumo Vedanta, kini itumo Vedanta?" O rorun gan. Imoye ni itumo Veda, to gaju ni itumo anta. gege na imoye to gaju ni itumo Vedanta. Krsna deni imoye yi. Krsna sowipe, vedaiś ca sarvair aham eva vedyo vedānta-kṛd veda-vid ca aham. Oun lo da Vedanta sile, oun lode mo na. bawo losele ko Vedanta tobajepe oun ko lo mo? Ni otooro Vyasadeva lo ko awon Vedanta, nkankana lje pelu Krsna. vedānta-kṛt ati vedānta-vit loje. Ibeere to wa niwipe se advaita-vada tabi dvaita-vada ni itumo Vedanta? osi rorun lati mo. Oro alakoko ninu Vedanta: athāto brahma jijñāsā, lati mo nipa Brahman, otito to gaju. nibo lama beere? Egbudo losodo eyan to mo, teba fe beere. nitorina ni apa mejeji yi sewa ni ibere Vedānta-sūtra, Eyan gbudo beere, osi gbudo daaun. Athāto brahma jijñāsā. Ninu Vedānta-sūtra bawo lese femo toba je advaita-vada? dvaita-vada loje lati'bere. Athāto brahma jijñāsā Eyan gbudo beere kini Brahman, asi gbudo daaun, tabi Oluko, tabi akeko. apa mejeji niyen. bawo lese femo tobaje advaita-vada? agbudo keko nipa eto na. Nibi wan sowipe,tattva-darśibhiḥ. itumo tattva-darśibhiḥ ni vedānta-vit, tabi eyan toba mo Vedānta. Janmādy asya yataḥ (SB 1.1.1). enikeni toba mo nipa otito to gaju latibi ti gbogbo nkan ti bere. Janmādy asya yataḥ. Ibere Śrīmad-Bhāgavatam niyen.