YO/Prabhupada 0640 - You can Find out Rascal Declaring himself as God - Kick on his Face: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0640 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1973 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 6: Line 6:
[[Category:YO-Quotes - in United Kingdom]]
[[Category:YO-Quotes - in United Kingdom]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0639 - The Individual Soul is in Every Body and the Supersoul is the Real Proprietor|0639|YO/Prabhupada 0641 - A Devotee Has No Demand|0641}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:


<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/730831BG-LON_clip_06.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/730831BG-LON_clip_06.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 26: Line 29:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT (from DotSub) -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT (from DotSub) -->
Ei rūpe. Aimoye awon eda towa ninu ile aye yi. Wansin yika ninu awon ara eda 8,400,00 - Wan yika ninu ibimo, iku, ati ibimo... Ninu gbogbo won, ti ikan ba soriri, won le fun laye, guru-kṛṣṇa-prasāde pāya bhakti-latā-bīja. Pelu ore-ofe ti guru ati Krsna, o le gba irugin ise ifarasi fun Krsna. Toba si l'ogbon, afi toba logbon bawo lose fe gba irugbin ise yi? Itebomi mimo niyen. Gege bi teba ni irugbin to da, e gbodo fi sinu ilele, pel'omi idie... lehin na o ma hu. Beena, enikeni toba pada imoye Krsna yi lati ore-ofe to ni, oye ko d'omi si irugbin ise ifarasi fun Oluwa yi. Kini omi na? Śravaṇa-kīrtana-jale karaye secana ([[Vanisource:CC Madhya 19.152|CC Madhya 19.152]]). Omi dida na leleyi. Igboran ati orin kiko nipa Krsna yi. Omi dida na leleyi. Ema se aimasi ninu awon ikeeko wanyi. Igboran ati orin kiko yi lon d'omi si irugbin ise ifarsi oluwa yi. Teyin ba bere iwa yi, t'en se aimasi ninu awon ikeeko wanyi.... Nkan tose pataki ju leleyi. Śravaṇaṁ kīrtanaṁ viṣṇoḥ ([[Vanisource:SB 7.5.23|SB 7.5.23]]). Nkan tose pataki ju niyen. Śravaṇaṁ kīrtanaṁ , ko kin sepe awa ma korin nipa eda imi ju Oluwa lo, itumo re ko niyen. Rara. Viṣṇu. Śravaṇaṁ kīrtanam. Awon asiwere wanyi ti "kali kirtan sile." Nibo ninu sastra wan soro nipa kali-kirtan, siva- kirtana? Rara. Ka yin Oluwa, Krsna logo nitumo Kirtana, kirtana niyen. Ko kin se kirtana imi. Sugbon nisin... wan farawe wa, kali-kirtan. Nibo ni kali-kirtana wa ninu sastra? Durga-kirtana? Iranu ni gbogbo eleyi. Krsna nikan. Śravaṇaṁ kīrtanaṁ viṣṇoḥ smaraṇaṁ pāda-sevanam ([[Vanisource:SB 7.5.23|SB 7.5.23]]). Oye ka gbadura si Krsna, oye ka gbo nipa Krsna, oye ka korin nipa Krsna, oye ka ranti Krsna. Bayi eyin ma ni ilosiwaju ninu imoye Krsna.
Ei rūpe. Aimoye awon eda towa ninu ile aye yi. Wansin yika ninu awon ara eda 8,400,00 - Wan yika ninu ibimo, iku, ati ibimo... Ninu gbogbo won, ti ikan ba soriri, won le fun laye, guru-kṛṣṇa-prasāde pāya bhakti-latā-bīja. Pelu ore-ofe ti guru ati Krsna, o le gba irugin ise ifarasi fun Krsna. Toba si l'ogbon, afi toba logbon bawo lose fe gba irugbin ise yi? Itebomi mimo niyen. Gege bi teba ni irugbin to da, e gbodo fi sinu ilele, pel'omi idie... lehin na o ma hu. Beena, enikeni toba pada imoye Krsna yi lati ore-ofe to ni, oye ko d'omi si irugbin ise ifarasi fun Oluwa yi. Kini omi na? Śravaṇa-kīrtana-jale karaye secana ([[Vanisource:CC Madhya 19.152|CC Madhya 19.152]]). Omi dida na leleyi. Igboran ati orin kiko nipa Krsna yi. Omi dida na leleyi. Ema se aimasi ninu awon ikeeko wanyi. Igboran ati orin kiko yi lon d'omi si irugbin ise ifarsi oluwa yi. Teyin ba bere iwa yi, t'en se aimasi ninu awon ikeeko wanyi.... Nkan tose pataki ju leleyi. Śravaṇaṁ kīrtanaṁ viṣṇoḥ ([[Vanisource:SB 7.5.23-24|SB 7.5.23]]). Nkan tose pataki ju niyen. Śravaṇaṁ kīrtanaṁ , ko kin sepe awa ma korin nipa eda imi ju Oluwa lo, itumo re ko niyen. Rara. Viṣṇu. Śravaṇaṁ kīrtanam. Awon asiwere wanyi ti "kali kirtan sile." Nibo ninu sastra wan soro nipa kali-kirtan, siva- kirtana? Rara. Ka yin Oluwa, Krsna logo nitumo Kirtana, kirtana niyen. Ko kin se kirtana imi. Sugbon nisin... wan farawe wa, kali-kirtan. Nibo ni kali-kirtana wa ninu sastra? Durga-kirtana? Iranu ni gbogbo eleyi. Krsna nikan. Śravaṇaṁ kīrtanaṁ viṣṇoḥ smaraṇaṁ pāda-sevanam ([[Vanisource:SB 7.5.23-24|SB 7.5.23]]). Oye ka gbadura si Krsna, oye ka gbo nipa Krsna, oye ka korin nipa Krsna, oye ka ranti Krsna. Bayi eyin ma ni ilosiwaju ninu imoye Krsna.


Ese pupo. Hare Krsna. (opin)
Ese pupo. Hare Krsna. (opin)
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:20, 14 June 2018



Lecture on BG 2.30 -- London, August 31, 1973

Ei rūpe. Aimoye awon eda towa ninu ile aye yi. Wansin yika ninu awon ara eda 8,400,00 - Wan yika ninu ibimo, iku, ati ibimo... Ninu gbogbo won, ti ikan ba soriri, won le fun laye, guru-kṛṣṇa-prasāde pāya bhakti-latā-bīja. Pelu ore-ofe ti guru ati Krsna, o le gba irugin ise ifarasi fun Krsna. Toba si l'ogbon, afi toba logbon bawo lose fe gba irugbin ise yi? Itebomi mimo niyen. Gege bi teba ni irugbin to da, e gbodo fi sinu ilele, pel'omi idie... lehin na o ma hu. Beena, enikeni toba pada imoye Krsna yi lati ore-ofe to ni, oye ko d'omi si irugbin ise ifarasi fun Oluwa yi. Kini omi na? Śravaṇa-kīrtana-jale karaye secana (CC Madhya 19.152). Omi dida na leleyi. Igboran ati orin kiko nipa Krsna yi. Omi dida na leleyi. Ema se aimasi ninu awon ikeeko wanyi. Igboran ati orin kiko yi lon d'omi si irugbin ise ifarsi oluwa yi. Teyin ba bere iwa yi, t'en se aimasi ninu awon ikeeko wanyi.... Nkan tose pataki ju leleyi. Śravaṇaṁ kīrtanaṁ viṣṇoḥ (SB 7.5.23). Nkan tose pataki ju niyen. Śravaṇaṁ kīrtanaṁ , ko kin sepe awa ma korin nipa eda imi ju Oluwa lo, itumo re ko niyen. Rara. Viṣṇu. Śravaṇaṁ kīrtanam. Awon asiwere wanyi ti "kali kirtan sile." Nibo ninu sastra wan soro nipa kali-kirtan, siva- kirtana? Rara. Ka yin Oluwa, Krsna logo nitumo Kirtana, kirtana niyen. Ko kin se kirtana imi. Sugbon nisin... wan farawe wa, kali-kirtan. Nibo ni kali-kirtana wa ninu sastra? Durga-kirtana? Iranu ni gbogbo eleyi. Krsna nikan. Śravaṇaṁ kīrtanaṁ viṣṇoḥ smaraṇaṁ pāda-sevanam (SB 7.5.23). Oye ka gbadura si Krsna, oye ka gbo nipa Krsna, oye ka korin nipa Krsna, oye ka ranti Krsna. Bayi eyin ma ni ilosiwaju ninu imoye Krsna.

Ese pupo. Hare Krsna. (opin)