YO/Prabhupada 0641 - A Devotee Has No Demand
Lecture on BG 6.1 -- Los Angeles, February 13, 1969
Olufokansi: Apa Kefa. Sankhya Yoga. Ese iwe kini. " Oluwa rere sowipe, Eni tioba feran awon ijeere ise re ton sise boseye ko sise, onitoun ti bosi ipo aye toti fi ife awon nkan aye yi sile, iru eyan bayi loje alagbara idan to daju. Konse eni tio le dana, tio de fe sise kankan." (BG 6.1) Alaye. Ninu apa iwe yi Oluwa ti salaye nipa ilana ona mejo ti yoga pe ona lati fi ni idari lori okan ati iye ara wa loje. Bakana, eleyi le gan fun awon eyan lati se, nipataki ninu asiko Kali Botilejepe wanti seduro nipa ilana ona mejo ti yoga yi ninu apa iwe na, Oluwa t salaye wipe ilana karma-yoga tabi ise ninu imoye Krsna si daa ju eleyi lo. Gbogbo eyan ninu aye yi n'sise lati toju ebi wan ati awon ophun elo toni sugbon koseni ton sise lai ni nkan ton reti, tabi igbadun ninu ise na, ole je nkan to po tabi nkan kekere. Oye ka lo lati fi sise ninu imoye Krsna, konsepe ka gbadun awon ijeere ise na. Lati sise ninu imoye Krsna ni ise gbogbo awon eda , nitoripe nkankan pelu Eledumare niwa. Awon apa eda sin sise fun igbadun gbogbo ara eda. Kosi bi owo at'ese se fe sise fun igbadun ara won sugbon fun igbadun gbogbo ara eda. Beena awon eda,ton sise fun igbadun eledumare, tio sise fun igbadun ara re, oun ni sannyasi toje pipe, yogi to gaju. " Nigbami awon sannyasi man rowipe wanti ni igbala lati awon ise ile aye yi, nitorina won o nife se awon ebo agni-hotra, ebo ina."
Prabhupada: Awon yajna kan wa toye ki onikaluku se fun iwenu ara. Beena koyeki awon sannyasi se awon yajna wanyi. Beena nitoripe wanti fi ipaari si awon ebo ti yajna wanyi, wanle bere sini rowipe wan ti ni gbala. Sugbon, afi tonba wa sori ipo imoye Krsna, kosejo pe wanti ni gbala. Tesiwaju.
Olufokansi: " Sugbon niootoro, nkan to wa lokan wan ni lati d'ikan pelu Brahman."
Prabhupada: Beeni. Ibere na wa. Awon alainigbagbo, wan si ni ibere kan, pe wan fe di'kankana pelu eledumare. sugbon eni toje olufokansi koni iru ibere bayi. O kan sise fun Krsna , fun itelorun Krsna. Won o fe nkankan fun ara won. Ise ifarasi to gaju niyen. Gege bi Oluwa Caitanya se so, na dhanaṁ na janaṁ na sundarīṁ kavitāṁ vā jagadīśa kāmaye: (CC Antya 20.29, Siksastaka 4) " Mio fe owo kankan, mio fe awon akeko kankan, Mio fe iyawo to da. E kan jekin sise fun yin." Mio fe iyawo to da. E kan jekin sise funyin." Nigbati Oluwa Nrsimhadeva bere lowo Prahlada Maharaja, " Oko mi, oti jiya gan funmi, beena ounkou toba fe bere nisin." Beena ko bere nkankan. " Oga mi, ise oro aje ko nimon se pelu yin, pe mofe gba nkan die fun ise tinba se funyin." Ise ifarasi to gaju niyen. Beena awon yogi tabi jnani, wan bere pe wanfe di'kan pelu Eledumare. KIlode teyin sefe di'ka pelu Eledumare? Nitoripe awa si ni iriri tio da, lati isoro ile aye yi. Sugbon awon olufokansi o ni iru nkan bayi. Awon olufokansi ma wa, sugbon loototo lat'Oluwa, On gbadun ninu ise Oluwa. Tesiwaju.
Olufokansi:" Iru ife okan yi lagbara ju gbogbo ife okan lo. Sugbon ife okan si wa ninu re. Been awon yogi alagbara idan tonse ilana yoga yi pel'oju to wa ni idaji sisi, toti fi ipaari si gbogbo ise ile aye yi, awon ife okan fun igbadun ara re.
Prabhupada: Looto awon yogi si fe igbara idan wanyi. Ipo to gaju ninu yoga niyen. Konse ipo to gaju, sugbon ikan ninu awon ilana na. Gege beyin tinse adase ninu awon ofin yoga, lehin na eyin na le ni awon agbara mejo wanyi. Eyin le fuye ju owu lo, esi le wiwo ju okuta lo. Ele ni ounkoun teba fe lesekese. Nigbami ele da awon isogbe gan, Iru awon yogi alagbara wanyi wa. Visvamitra yogi, o se iru nkan bayi. Osi gbiynaju lati da eda eyan lati igi ope. " Kilode tojepe awon eda okurin gbodo duru sinu oyun iya wan fun ose mewa? Oye kan wa s'aye bi awon eso. " Osi se beena. Beena nigbai awon yogi wanyi man lagbara gan, wanle se iru nkan bayi. Beena na agbara ile aye yi nigbogbo eleyi. Iru awon yogi yi, wan sile fi ku pa won. Fun igbamelo leyin le wa ninu ile aye yi? Beena won bhakti-yogi, wan o fe iru nkan bayi. Tesiwaju. Beeni.
Olufokansi: " Sugbon eni ton sise ninu imoye Krsna sin sise fun iteloorun gbogbo nkan lai wa ijeere ara re. Eni toni imoye Krsna koni ife okan fun itelorun ara -re. Aami aseyori re ni itelorun Krsna. beena oun ni sannyasi tabi yogi to gaju. Oluwa Caitanya, toje aami ilosiwaju to gaju ninu imoye Krsna si gbadura pe: "Oh Olorun alagbara, mio ni ife okan kankan fun owo, tabi lati gbadun awon obirin. mio sife awon akeeko to po. Ore-ofe yin fun ise ifarasi fun yin nimofe lat'aye kan sikeji."
Prabhupada: Beena awon olufokansi o fe ni igbala gan. Kilode ti Oluwa Caitanya se sowuipe " Lati ibimo kan sikeji?" Awon ton feran igbala won fe fi ipaari si, awon alanigbagbo, fe fi ipaari si ile aye yi. Sugbon Caitanya Mahaprabhu sowipe, " lati ibimo kan sikeji." Itumore niwipe O le gba gbogbo inira ile aye yi sara lati ibimo kan sijeki Sugbon kilo fe? O fe sise ninu ise ifarafun Oluwa. Ipo to gaju niyen. O le fi daduro. Fi ipaari sibe.