YO/Prabhupada 1073 - Beena botilejepe awa o le ye ironu lati d'oga iseda aye yi kuro l'okan: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba) Pages with Videos Category:Prabhupada 0001 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - L...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 1: Line 1:
<!-- BEGIN CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN CATEGORY LIST -->
[[Category:1080 Yoruba) Pages with Videos]]
[[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]]
[[Category:Prabhupada 0001 - in all Languages]]
[[Category:Prabhupada 1073 - in all Languages]]
[[Category:YO-Quotes - 1966]]
[[Category:YO-Quotes - 1966]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
Line 8: Line 8:
[[Category:YO-Quotes - Introduction to Bhagavad-gita As It Is]]
[[Category:YO-Quotes - Introduction to Bhagavad-gita As It Is]]
[[Category:Introduction to Bhagavad-gita As It Is in all Languages]]
[[Category:Introduction to Bhagavad-gita As It Is in all Languages]]
[[Category:YorubaLanguage]]
[[Category:Yoruba Language]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 1072 - Ka fi ile aye yi sile ka pada s'aye tio le paari ninu ijoba towa tayeraye|1072|YO/Prabhupada 1074 - Gbogbo iyan tan je ninu aye yi - nitori ara eda tani|1074}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|h6PY9S27t8c|So Long We Do Not Give Up this Propensity of Lording it Over the Material Nature - Prabhupāda 1073}}
{{youtube_right|h6PY9S27t8c|Beena botilejepe awa o le ye ironu lati d'oga iseda aye yi kuro l'okan - Prabhupāda 1073}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>File:660220BG-NEW_YORK_clip17.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/660220BG-NEW_YORK_clip17.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 30: Line 33:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Nisin ninu apa 15 ti Bhagavad-gita, wanti ti juwe gege bi ile aye yi se ri. Wan sowipe
Ni iwọn igba ti bi a ko ba fi iwa yi silẹ lati jẹ oluwa lori awọn ohun elo isẹda Ninu Ori iwe Kẹdogun ti Bhagavad-Gita, a ti ni aworan gidi ti ile aye yi. O ti wi nibẹ:


:ūrdhva-mūlam adhaḥ-śākham
:ūrdhva-mūlam adhaḥ-śākham
Line 36: Line 39:
:chandāṁsi yasya parṇāni
:chandāṁsi yasya parṇāni
:yas taṁ veda sa veda-vit
:yas taṁ veda sa veda-vit
:([[Vanisource:BG 15.1|BG 15.1]])  
:([[Vanisource:BG 15.1 (1972)|BG 15.1]])


Nisin, wanti juwe ile aye yi ninu apa meedogun iwe Bhagavad-gita pe bi igi toni awon gbongbo re soke, urdhva-mulam. Seyin ti ri igi toni awon gbongbo re soke? Awa ti jerisi pe igi toni gbongbo re soke , Taba duro s'eti omi odo, a le ri wipe igi tow leti omi odo na le farahan lori omi pelu awon gbongboo re soke ati awon igi re loke. Beena bi itan ojiji odo metalokan ni ile aye yi je. Gege bi itan ojiji t'igi leti omi odo se dorikodo ninu omi, beena, ile aye , ojiji loje. Ojiji. Ninu ojiji kosi nkankam gidi ninu re, sugobn lasiko kanna, lat'ojiji yi o le ye wa wipe nkan gidi n'be. Fun apeere, ojiji omi to wa ninu ile gbigbe, o fi yewa wipe ni ile gbigbe ko s'omi, sugbon omi wa. Beena, ninu ojiji odo metalokna, tabi ile aye yi, kosi idunnu kankan, kos'omi kankan. Sugbon idunnu at'oimi gidi wa ninu odo metalok Oluwa ti fi ye wa wipe eyan gbodo wa si odo metalokan pel'ona toti da sile, nirmāna-mohā.  
Nisin, ile aye yi ti ni apejuwe ninu ori iwe kedogun iwe mimo Bhagavad-gita bi igi ti gbongbo rẹ wá ni oke, urdhva-mulam. Se ẹ ni iriri igi ti gbongbo rẹ wa l’oke? A ni iriri igi ti gbongbo rẹ wa l’oke, nipa ojiji. Ti eniyan ba dúró l’eti odo tabi eyikeyi orisun omi, o le ri pe ojiji awọn igi ninu omi dorikodò, awọn ẹka lọ sisalẹ awọn gbongbo si wá sókè. Bákan náà, ni aye yi se jẹ ojiji ti ọrun ẹmi. Gege bi ojiji awọn igi ninu omi se dorikodò l'eti omi, Bákan náà, ni aye yi se jẹ ojiji ti ọrun ẹmi. Ninu ojiji ko si otitọ nibẹ tabi ohun ojulowo, sugbọn lati ojiji a le ni oye wipe awọn nkan gidi wa ti wọn jẹ otitọ. Fun apeere, aṣálẹ ko si omi nibẹ, ojiji omi to wa ninu ile gbigbe, ṣugbọn ilẹ to nse bi dingi lokere d’àba wipe iru nkan bi omi wa. Bee na, ninu ojiji ti ọrun ẹmi, tabi ile aye yi, kosi idunnu kankan, kos'omi kankan. ṣugbọn omi gidi ti ayọ gangan wa nibẹ ninu isalu ọrun. Oluwa da ni imọran wipe a le wọ ijọba ọrun ni awọn ọna wọnyi, nirmāna-mohā.  


:nirmāna-mohā jita-saṅga-doṣā
:nirmāna-mohā jita-saṅga-doṣā
Line 44: Line 47:
:dvandvair vimuktāḥ sukha-duḥkha-saṁjñair
:dvandvair vimuktāḥ sukha-duḥkha-saṁjñair
:gacchanty amūḍhāḥ padam avyayaṁ tat
:gacchanty amūḍhāḥ padam avyayaṁ tat
:([[Vanisource:BG 15.5|BG 15.5]]).
:([[Vanisource:BG 15.5 (1972)|BG 15.5]])


padam avyayam yi, odo metalokan yi , eni toje nimana-moha lole dee be. Nirmāna-mohā. Awon ton feran ipo nitumo Nirmāna. Awon eyan feran yiyan. Awon fe d'oga, awon imi fe d'Oluwa, awon imi fe di Olori ijoba, tabi elomi fe d'olowo, elomi fe di nkan bayi bayi, Oba. Gbogbo awon yiyan wanyi, botijepe ani awon ife okan si won.. Nitoripe leyin gbogbo awon yiyan wanyi fun ara wa, ayato si ara eda yi. Imoye t'alakoko ninu imo mimo. Beena awa o gbodo ni ifarasi iru awon yiyan wanyi. Ati jita-saṅga-doṣā, saṅga-doṣā. Nisin ati ni asepo pelu awon ipo meta ile aye yi, taba si yo ara wa kuro pelu ise ifarasi Oluwa... Boti jepe awa o ni ifarasi fun ise Oluwa, awa o le yo ara wa kuro ninu awon ipo meta aye yi. Nitorina Olyuwa sowipe, vinivṛtta-kāmāḥ, awon ipo wanyi tabi awon idimu aye yi nitotri ifekufe lonti wa, ife okan. Afe d'oga ile aye yi. Titi d'igba t'aba fi iwa yi sile lati d'oga ninu aye yi, titi digba na kole si basele pada si ijoba Oluwa, sanatana-dhama. Dvandvair vimuktāḥ sukha-duḥkha-saṁjñair gacchanty amūḍhāḥ, amūḍhāḥ padam avyayaṁ tat ([[Vanisource:BG 15.5|BG 15.5]]). Odo metalokan tayeraye, tio le paare bi ile aye yi, afi taba di amūḍhāḥ. Itumo Amūḍhāḥ l'eni tio ni idamu kankan, Eni tio ni idamu kankan lati awon ifarasi fu igbadun aye yi. Eni toba de wa ninu ise fun Oluwa, Oun leni to daju lati wole sinu odo metalokan. orun o wulo ninu odo metalokan yi, osupa tabi ina monamona. Iwo ni soki nipa odo metalokan niyen.  
Padam avyayam na, tabi ijọba ọrun, ẹni ti o ba jẹ nirmāna-moha ni o le de bẹ. Nirmāna-mohā. Kíni eyi tumọ si? A nlepa lati l’àmi lori. Lorieke a fẹ àmi lori. Ẹnikan fẹ lati di "sa," ẹnikan fẹ lati di "oluwa," awon imi fe di Olori ijoba, tabi elomi fe d'olowo, elomi fe di nkan bayi bayi, Oba. Fun iwọn igba ti a ba ti ni ipọnle fun awọn àmi wọnyi... Nitoripe nigbẹhin gbogbo awọn àmi jẹ ti ara, awa ki ise awọ ara yi. Imọ yi ni ipele akọkọ ninu iriri ẹmí. Bee na ami ara ko gbodo fawa lokan. Ati jita-saṅga-doṣā, saṅga-doṣā. ti ni nkan ṣe pẹlu awọn ipa mẹta ti isẹda, sugbọn a gbọdọ s’ẹtọ nipa iṣẹ ẹsin fun Oluwa. Ti a ko ba ni ipọnle fun iṣẹ ẹsin ti Oluwa, nigbana a ko ni le se ikora nijanu lọwọ ipa ti awọn ohun elo isẹda. Nitorina Olyuwa sowipe, vinivṛtta-kāmāḥ, Ifẹkufẹ ati ifẹ aye ni wọn nfa isàmi ati ipọnra-ẹnile Ifẹ wa ni lati jẹ oluwa lori awọn ohun elo isẹda. Ni iwọn igba ti bi a ko ba fi iwa yi silẹ lati jẹ oluwa lori awọn ohun elo isẹda, ko si seese lati pada si ijọba ọrun, sanatana-dhāma. Ijọba ainipẹkun, Dvandvair vimuktāḥ sukha-duḥkha-saṁjñair gacchanty amūḍhāḥ, amūḍhāḥ padam avyayaṁ tat ([[Vanisource:BG 15.5 (1972)|BG 15.5]]). Odo metalokan tayeraye, tio le paare bi ile aye yi, le see sumọn fun, amūḍhāḥ. Itumo Amūḍhāḥ l'eni ti ko ni idamu kankan, Eni ti ifalọkan awọn igbadun eke aye ko si se ni dãmu. ẹni ti o wa ninu iṣẹ Oluwa Atobiju, Ẹni to ba ti wa bayi ni o le fi rọrun sunmọ ibugbe na ti o ga julọ. aye ainipẹkun yi ko nilo oorun, osupa tabi ina mọnamọna kankan. Eyini ni soki nipa isunmọ ijọba aye ainipẹkun.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:31, 14 June 2018



660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Ni iwọn igba ti bi a ko ba fi iwa yi silẹ lati jẹ oluwa lori awọn ohun elo isẹda Ninu Ori iwe Kẹdogun ti Bhagavad-Gita, a ti ni aworan gidi ti ile aye yi. O ti wi nibẹ:

ūrdhva-mūlam adhaḥ-śākham
aśvatthaṁ prāhur avyayam
chandāṁsi yasya parṇāni
yas taṁ veda sa veda-vit
(BG 15.1)

Nisin, ile aye yi ti ni apejuwe ninu ori iwe kedogun iwe mimo Bhagavad-gita bi igi ti gbongbo rẹ wá ni oke, urdhva-mulam. Se ẹ ni iriri igi ti gbongbo rẹ wa l’oke? A ni iriri igi ti gbongbo rẹ wa l’oke, nipa ojiji. Ti eniyan ba dúró l’eti odo tabi eyikeyi orisun omi, o le ri pe ojiji awọn igi ninu omi dorikodò, awọn ẹka lọ sisalẹ awọn gbongbo si wá sókè. Bákan náà, ni aye yi se jẹ ojiji ti ọrun ẹmi. Gege bi ojiji awọn igi ninu omi se dorikodò l'eti omi, Bákan náà, ni aye yi se jẹ ojiji ti ọrun ẹmi. Ninu ojiji ko si otitọ nibẹ tabi ohun ojulowo, sugbọn lati ojiji a le ni oye wipe awọn nkan gidi wa ti wọn jẹ otitọ. Fun apeere, aṣálẹ ko si omi nibẹ, ojiji omi to wa ninu ile gbigbe, ṣugbọn ilẹ to nse bi dingi lokere d’àba wipe iru nkan bi omi wa. Bee na, ninu ojiji ti ọrun ẹmi, tabi ile aye yi, kosi idunnu kankan, kos'omi kankan. ṣugbọn omi gidi ti ayọ gangan wa nibẹ ninu isalu ọrun. Oluwa da ni imọran wipe a le wọ ijọba ọrun ni awọn ọna wọnyi, nirmāna-mohā.

nirmāna-mohā jita-saṅga-doṣā
adhyātma-nityā vinivṛtta-kāmāḥ
dvandvair vimuktāḥ sukha-duḥkha-saṁjñair
gacchanty amūḍhāḥ padam avyayaṁ tat
(BG 15.5)

Padam avyayam na, tabi ijọba ọrun, ẹni ti o ba jẹ nirmāna-moha ni o le de bẹ. Nirmāna-mohā. Kíni eyi tumọ si? A nlepa lati l’àmi lori. Lorieke a fẹ àmi lori. Ẹnikan fẹ lati di "sa," ẹnikan fẹ lati di "oluwa," awon imi fe di Olori ijoba, tabi elomi fe d'olowo, elomi fe di nkan bayi bayi, Oba. Fun iwọn igba ti a ba ti ni ipọnle fun awọn àmi wọnyi... Nitoripe nigbẹhin gbogbo awọn àmi jẹ ti ara, awa ki ise awọ ara yi. Imọ yi ni ipele akọkọ ninu iriri ẹmí. Bee na ami ara ko gbodo fawa lokan. Ati jita-saṅga-doṣā, saṅga-doṣā. ti ni nkan ṣe pẹlu awọn ipa mẹta ti isẹda, sugbọn a gbọdọ s’ẹtọ nipa iṣẹ ẹsin fun Oluwa. Ti a ko ba ni ipọnle fun iṣẹ ẹsin ti Oluwa, nigbana a ko ni le se ikora nijanu lọwọ ipa ti awọn ohun elo isẹda. Nitorina Olyuwa sowipe, vinivṛtta-kāmāḥ, Ifẹkufẹ ati ifẹ aye ni wọn nfa isàmi ati ipọnra-ẹnile Ifẹ wa ni lati jẹ oluwa lori awọn ohun elo isẹda. Ni iwọn igba ti bi a ko ba fi iwa yi silẹ lati jẹ oluwa lori awọn ohun elo isẹda, ko si seese lati pada si ijọba ọrun, sanatana-dhāma. Ijọba ainipẹkun, Dvandvair vimuktāḥ sukha-duḥkha-saṁjñair gacchanty amūḍhāḥ, amūḍhāḥ padam avyayaṁ tat (BG 15.5). Odo metalokan tayeraye, tio le paare bi ile aye yi, le see sumọn fun, amūḍhāḥ. Itumo Amūḍhāḥ l'eni ti ko ni idamu kankan, Eni ti ifalọkan awọn igbadun eke aye ko si se ni dãmu. ẹni ti o wa ninu iṣẹ Oluwa Atobiju, Ẹni to ba ti wa bayi ni o le fi rọrun sunmọ ibugbe na ti o ga julọ. aye ainipẹkun yi ko nilo oorun, osupa tabi ina mọnamọna kankan. Eyini ni soki nipa isunmọ ijọba aye ainipẹkun.