YO/Prabhupada 0249 - Awon eyan sin beere kilode ti gbogbo aye sen jagun: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0249 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1973 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 6: Line 6:
[[Category:YO-Quotes - in United Kingdom]]
[[Category:YO-Quotes - in United Kingdom]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0248 - Iyawo to koja ẹgbàájọ ni Krishna fe , pelu ija lo si se igbeyawo gbogbo won|0248|YO/Prabhupada 0250 - E sise fun Krishna, fun Olorun, E ma sise fun igbadun ara yin|0250}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 14: Line 17:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|F8EpbZvJezI|The Question was Raised that, Why War Takes Place? - Prabhupāda 0249}}
{{youtube_right|F8EpbZvJezI|Awon eyan sin beere kilode ti gbogbo aye sen jagun - Prabhupāda 0249}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/730806BG.LON_clip2.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/730806BG.LON_clip2.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 26: Line 29:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Ko soro pe Arjuna rori wo boya o fe ja tabi rara Krsna ti fi ase si, gege na ogbudo jagun Nigbami awon eyan fe mo kini idi fun ogun? Iyen o le ati mo, nitoripe gbogbo la ni emi to feran ija Awon omode man ja, aja ati ologbo, awon eye, awon kokor. Gbogbo wa ti ri Kilode ti awon eyan na o ni ja? Emi jija ogun ti wan be aami eyan to wa laaye ni yen. Jija ogun Nigbawo ni ija yen ma sele? Ni asiko tawa yi, Awon onijoba ma ja Ti eyan ba jagun gege bi awon iwe mimo Veda se so, dharma-yuddha ni itumo ogun yi laisi idi ti oṣelu gege bi isin awon apa meeji fe jagun, awon ẹgbẹ́ kọ́múnístì ati awon olówó Wan si fe pa ogun ti, sugbon wan sin jagun na Lesekese ti America ba lo si ibikan, Russia na ma debe Ni ogun to kehin laarin Orile-ede India ati Pakistan, lesekese ti olórí Nixon se ran awon jagunjagun lo lori Okun India, ni iwaju India Iwa yi lòdì sófin sugbon America si ni igberaga wan ran awon jagunjagun na lati fun Pakistan ni iranlowo sugbon Lesekese, ore wa Russia na si farahan Nitorina, Orile-ede America na si pada wa bibeko, O jo miloju pe Orile-ede o ba gbeja Pakistan  
Ko soro pe Arjuna rori wo boya o fe ja tabi rara Krsna ti fi ase si, gege na ogbudo jagun Nigbami awon eyan fe mo kini idi fun ogun? Iyen o le ati mo, nitoripe gbogbo la ni emi to feran ija Awon omode man ja, aja ati ologbo, awon eye, awon kokor. Gbogbo wa ti ri Kilode ti awon eyan na o ni ja? Emi jija ogun ti wan be aami eyan to wa laaye ni yen. Jija ogun Nigbawo ni ija yen ma sele? Ni asiko tawa yi, Awon onijoba ma ja Ti eyan ba jagun gege bi awon iwe mimo Veda se so, dharma-yuddha ni itumo ogun yi laisi idi ti oṣelu gege bi isin awon apa meeji fe jagun, awon ẹgbẹ́ kọ́múnístì ati awon olówó Wan si fe pa ogun ti, sugbon wan sin jagun na Lesekese ti America ba lo si ibikan, Russia na ma debe Ni ogun to kehin laarin Orile-ede India ati Pakistan, lesekese ti olórí Nixon se ran awon jagunjagun lo lori Okun India, ni iwaju India Iwa yi lòdì sófin sugbon America si ni igberaga wan ran awon jagunjagun na lati fun Pakistan ni iranlowo sugbon Lesekese, ore wa Russia na si farahan Nitorina, Orile-ede America na si pada wa bibeko, O jo miloju pe Orile-ede o ba gbeja Pakistan.


Eyan o le fi ipaari si awon ogun wanyi Opolopo awon eyan fe fi ipaari si ogun, ko lesese Iranu ni yen je. Nitoripe emi ija wa ninu gbogbo wa aami to wa ninu eda ni yen awon omode ti o mo nkankan nipa oṣelu, wan si ja fun iseju maarun, lehin na wan di ore pada gege na bawo ni eyan sele lo emi ij to wa ninu wa bayi Imoye Krsna si wa awa so sipe " Ema jagun mo, "ese bayi" , rara Iwaasu wa ni wipe, ese gbogbo nkan pelu imoye Krsna Nirbandha-kṛṣṇa-sambandhe. Ounkooun ti eyan ba fe se, ogbudo ni itelorun fun Oluwa Ti Krsna ba ni itelorun, nigbana ele se ise Kṛṣṇendriya tṛpti vāñchā tāra nāma prema ([[Vanisource:CC Adi 4.165|CC Adi 4.165]]). Ife ni yen Te ba ferann enikan, ele se ounkooun to ba fe, nigbami a le se gan gege na nkankanna ni ke se fun Krsna. Otan E gbiyanju lati ni ife Krsna, ke si se ise fun Krsna idi igbese aye wa ni yen. Sa vai puṁsāṁ paro dharmo yato bhaktir adhokṣaje ([[Vanisource:SB 1.2.6|SB 1.2.6]]). ise ni itumo Bhakti, bhaja-sevāyām. iwulo bhaj-dhātu, ni fun ise sise ni ilo ọrọ dajudaju ede Sanskrit, kti-pratyaya, ma sodi ẹka-ọrọ orukọ ẹka-ọrọ iṣe ni eleyi je nkankanna ni bhakti pelu bhaj-dhātu kti Itumo bhakti ni itelorun Krsna. Eyan o le lo Bhakti fun elomi ju Oluwa Ti eyan ba so wipe "Elesin Kali ni mi", Orisa kali Bhakti ko ni yen, iṣowo niyen nitoripe ko s'eyan to ma gba aduro si orisa lai ni nkan to fe awon eyan ton fe jeran lon man saba s'adura si Orisa kali Ni asa veda, wan ti p'ase fun awon eyan ton jeran pe " ema je eran ti ran loja" Ni aye igbayen ko si ile-ton pẹran Aye isin ni iyen ti bere Nigbami taban soro pelu awon Onigbagbo, mo man bi wan pe Jesu Kristi si so wipe " iwo osi ni fi iku pa", kilode ti eyin se fi iku pa awon eranko? Nigbami wan man so wipe Jesu Kristi na o jeran ri Nigbami O si jeran, Ko si isoro. Sugbon se Jesu Kristi so fun yin pe ke si ile ton pẹran? Ko sogbon lori wan, ti Jesu ba jeran boya nigbana ko si nkan mi to le je. Kini eyin ma se? Sugbon oro mi ni yen, Ti o ba si ounje mi Asiko na ma wa ti ounje onito fun awon eyan Ni apa mejila iwe Śrīmad-Bhāgavatam ti salaaye gbogbo eleyi Ko ni si iresi, koni si wara, koni si ṣuga Eyan gbudo jeran. Bi nkan se ma ri niyen boya awon ma je ara wan na Ile-aye yi asi kunfun ese to je pe, awon ma wonu ese lo Tān aham dviṣataḥ krūrān kṣīpāmy ajasram andhe-yoniṣu ([[Vanisource:BG 16.19|BG 16.19]]) awon ton ni iwa Esu, ton feran ese, awon lon ma wa ninu iru ipo bayi Asi ni iwa esu to po si, gege na kole ni oye Olorun mo Ofin iseda ni yen teba fe gbagbe Olorun, Olorun na asi fun yin ni ipo lati le gbagbe e. Ile-aye awon Esu ni yen. Asiko na ooni pe wa Ni asiko ta wa yi, awon ton fe mo nipa Olorun, iwonba kekere lon je Arto arthārtī jijñāsu jñānī ([[Vanisource:CC Madhya 24.95|CC Madhya 24.95]]). Sugbon asiko ma de to je pe, koseni to ma l'ogbon ati fi ni ife Oluwa Opin Kali-yuga ni yen, Nigbana Kalkī avatāra ma wa Nigbana koni si iwaasu mo, a ko wa anpa awon ey Kalkī avatāra asi wa pa awon eyan pelu idà Lehin na, Satya-yuga ma wa.. asiko wura ni eleyi
Eyan o le fi ipaari si awon ogun wanyi Opolopo awon eyan fe fi ipaari si ogun, ko lesese Iranu ni yen je. Nitoripe emi ija wa ninu gbogbo wa aami to wa ninu eda ni yen awon omode ti o mo nkankan nipa oṣelu, wan si ja fun iseju maarun, lehin na wan di ore pada gege na bawo ni eyan sele lo emi ij to wa ninu wa bayi Imoye Krsna si wa awa so sipe " Ema jagun mo, "ese bayi" , rara Iwaasu wa ni wipe, ese gbogbo nkan pelu imoye Krsna Nirbandha-kṛṣṇa-sambandhe. Ounkooun ti eyan ba fe se, ogbudo ni itelorun fun Oluwa Ti Krsna ba ni itelorun, nigbana ele se ise Kṛṣṇendriya tṛpti vāñchā tāra nāma prema ([[Vanisource:CC Adi 4.165|CC Adi 4.165]]). Ife ni yen Te ba ferann enikan, ele se ounkooun to ba fe, nigbami a le se gan gege na nkankanna ni ke se fun Krsna. Otan E gbiyanju lati ni ife Krsna, ke si se ise fun Krsna idi igbese aye wa ni yen. Sa vai puṁsāṁ paro dharmo yato bhaktir adhokṣaje ([[Vanisource:SB 1.2.6|SB 1.2.6]]). ise ni itumo Bhakti, bhaja-sevāyām. iwulo bhaj-dhātu, ni fun ise sise ni ilo ọrọ dajudaju ede Sanskrit, kti-pratyaya, ma sodi ẹka-ọrọ orukọ ẹka-ọrọ iṣe ni eleyi je nkankanna ni bhakti pelu bhaj-dhātu kti Itumo bhakti ni itelorun Krsna. Eyan o le lo Bhakti fun elomi ju Oluwa Ti eyan ba so wipe "Elesin Kali ni mi", Orisa kali Bhakti ko ni yen, iṣowo niyen nitoripe ko s'eyan to ma gba aduro si orisa lai ni nkan to fe awon eyan ton fe jeran lon man saba s'adura si Orisa kali Ni asa veda, wan ti p'ase fun awon eyan ton jeran pe " ema je eran ti ran loja" Ni aye igbayen ko si ile-ton pẹran Aye isin ni iyen ti bere Nigbami taban soro pelu awon Onigbagbo, mo man bi wan pe Jesu Kristi si so wipe " iwo osi ni fi iku pa", kilode ti eyin se fi iku pa awon eranko? Nigbami wan man so wipe Jesu Kristi na o jeran ri Nigbami O si jeran, Ko si isoro. Sugbon se Jesu Kristi so fun yin pe ke si ile ton pẹran? Ko sogbon lori wan, ti Jesu ba jeran boya nigbana ko si nkan mi to le je. Kini eyin ma se? Sugbon oro mi ni yen, Ti o ba si ounje mi Asiko na ma wa ti ounje onito fun awon eyan Ni apa mejila iwe Śrīmad-Bhāgavatam ti salaaye gbogbo eleyi Ko ni si iresi, koni si wara, koni si ṣuga Eyan gbudo jeran. Bi nkan se ma ri niyen boya awon ma je ara wan na Ile-aye yi asi kunfun ese to je pe, awon ma wonu ese lo Tān aham dviṣataḥ krūrān kṣīpāmy ajasram andhe-yoniṣu ([[Vanisource:BG 16.19 (1972)|BG 16.19]]) awon ton ni iwa Esu, ton feran ese, awon lon ma wa ninu iru ipo bayi Asi ni iwa esu to po si, gege na kole ni oye Olorun mo Ofin iseda ni yen teba fe gbagbe Olorun, Olorun na asi fun yin ni ipo lati le gbagbe e. Ile-aye awon Esu ni yen. Asiko na ooni pe wa Ni asiko ta wa yi, awon ton fe mo nipa Olorun, iwonba kekere lon je Arto arthārtī jijñāsu jñānī ([[Vanisource:CC Madhya 24.95|CC Madhya 24.95]]). Sugbon asiko ma de to je pe, koseni to ma l'ogbon ati fi ni ife Oluwa Opin Kali-yuga ni yen, Nigbana Kalkī avatāra ma wa Nigbana koni si iwaasu mo, a ko wa anpa awon ey Kalkī avatāra asi wa pa awon eyan pelu idà Lehin na, Satya-yuga ma wa.. asiko wura ni eleyi.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 23:42, 13 June 2018



Lecture on BG 2.6 -- London, August 6, 1973

Ko soro pe Arjuna rori wo boya o fe ja tabi rara Krsna ti fi ase si, gege na ogbudo jagun Nigbami awon eyan fe mo kini idi fun ogun? Iyen o le ati mo, nitoripe gbogbo la ni emi to feran ija Awon omode man ja, aja ati ologbo, awon eye, awon kokor. Gbogbo wa ti ri Kilode ti awon eyan na o ni ja? Emi jija ogun ti wan be aami eyan to wa laaye ni yen. Jija ogun Nigbawo ni ija yen ma sele? Ni asiko tawa yi, Awon onijoba ma ja Ti eyan ba jagun gege bi awon iwe mimo Veda se so, dharma-yuddha ni itumo ogun yi laisi idi ti oṣelu gege bi isin awon apa meeji fe jagun, awon ẹgbẹ́ kọ́múnístì ati awon olówó Wan si fe pa ogun ti, sugbon wan sin jagun na Lesekese ti America ba lo si ibikan, Russia na ma debe Ni ogun to kehin laarin Orile-ede India ati Pakistan, lesekese ti olórí Nixon se ran awon jagunjagun lo lori Okun India, ni iwaju India Iwa yi lòdì sófin sugbon America si ni igberaga wan ran awon jagunjagun na lati fun Pakistan ni iranlowo sugbon Lesekese, ore wa Russia na si farahan Nitorina, Orile-ede America na si pada wa bibeko, O jo miloju pe Orile-ede o ba gbeja Pakistan.

Eyan o le fi ipaari si awon ogun wanyi Opolopo awon eyan fe fi ipaari si ogun, ko lesese Iranu ni yen je. Nitoripe emi ija wa ninu gbogbo wa aami to wa ninu eda ni yen awon omode ti o mo nkankan nipa oṣelu, wan si ja fun iseju maarun, lehin na wan di ore pada gege na bawo ni eyan sele lo emi ij to wa ninu wa bayi Imoye Krsna si wa awa so sipe " Ema jagun mo, "ese bayi" , rara Iwaasu wa ni wipe, ese gbogbo nkan pelu imoye Krsna Nirbandha-kṛṣṇa-sambandhe. Ounkooun ti eyan ba fe se, ogbudo ni itelorun fun Oluwa Ti Krsna ba ni itelorun, nigbana ele se ise Kṛṣṇendriya tṛpti vāñchā tāra nāma prema (CC Adi 4.165). Ife ni yen Te ba ferann enikan, ele se ounkooun to ba fe, nigbami a le se gan gege na nkankanna ni ke se fun Krsna. Otan E gbiyanju lati ni ife Krsna, ke si se ise fun Krsna idi igbese aye wa ni yen. Sa vai puṁsāṁ paro dharmo yato bhaktir adhokṣaje (SB 1.2.6). ise ni itumo Bhakti, bhaja-sevāyām. iwulo bhaj-dhātu, ni fun ise sise ni ilo ọrọ dajudaju ede Sanskrit, kti-pratyaya, ma sodi ẹka-ọrọ orukọ ẹka-ọrọ iṣe ni eleyi je nkankanna ni bhakti pelu bhaj-dhātu kti Itumo bhakti ni itelorun Krsna. Eyan o le lo Bhakti fun elomi ju Oluwa Ti eyan ba so wipe "Elesin Kali ni mi", Orisa kali Bhakti ko ni yen, iṣowo niyen nitoripe ko s'eyan to ma gba aduro si orisa lai ni nkan to fe awon eyan ton fe jeran lon man saba s'adura si Orisa kali Ni asa veda, wan ti p'ase fun awon eyan ton jeran pe " ema je eran ti ran loja" Ni aye igbayen ko si ile-ton pẹran Aye isin ni iyen ti bere Nigbami taban soro pelu awon Onigbagbo, mo man bi wan pe Jesu Kristi si so wipe " iwo osi ni fi iku pa", kilode ti eyin se fi iku pa awon eranko? Nigbami wan man so wipe Jesu Kristi na o jeran ri Nigbami O si jeran, Ko si isoro. Sugbon se Jesu Kristi so fun yin pe ke si ile ton pẹran? Ko sogbon lori wan, ti Jesu ba jeran boya nigbana ko si nkan mi to le je. Kini eyin ma se? Sugbon oro mi ni yen, Ti o ba si ounje mi Asiko na ma wa ti ounje onito fun awon eyan Ni apa mejila iwe Śrīmad-Bhāgavatam ti salaaye gbogbo eleyi Ko ni si iresi, koni si wara, koni si ṣuga Eyan gbudo jeran. Bi nkan se ma ri niyen boya awon ma je ara wan na Ile-aye yi asi kunfun ese to je pe, awon ma wonu ese lo Tān aham dviṣataḥ krūrān kṣīpāmy ajasram andhe-yoniṣu (BG 16.19) awon ton ni iwa Esu, ton feran ese, awon lon ma wa ninu iru ipo bayi Asi ni iwa esu to po si, gege na kole ni oye Olorun mo Ofin iseda ni yen teba fe gbagbe Olorun, Olorun na asi fun yin ni ipo lati le gbagbe e. Ile-aye awon Esu ni yen. Asiko na ooni pe wa Ni asiko ta wa yi, awon ton fe mo nipa Olorun, iwonba kekere lon je Arto arthārtī jijñāsu jñānī (CC Madhya 24.95). Sugbon asiko ma de to je pe, koseni to ma l'ogbon ati fi ni ife Oluwa Opin Kali-yuga ni yen, Nigbana Kalkī avatāra ma wa Nigbana koni si iwaasu mo, a ko wa anpa awon ey Kalkī avatāra asi wa pa awon eyan pelu idà Lehin na, Satya-yuga ma wa.. asiko wura ni eleyi.