YO/Prabhupada 0439 - My Spiritual Master Found Me A Great Fool: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0439 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1968 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0005 edit: add new navigation bars (prev/next))
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in USA, Los Angeles]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, Los Angeles]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0438 - Cow Dung Dried and Burned into Ashes is used as Toothpowder|0438|YO/Prabhupada 0440 - The Mayavadi Theory is that the Ultimate Spirit is Impersonal|0440}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 19: Line 22:


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/681127BG.LA_clip5.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/681127BG.LA_clip5.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->



Latest revision as of 12:24, 21 September 2017



Lecture on BG 2.8-12 -- Los Angeles, November 27, 1968

Tad vijñānārthaṁ sa gurum evābhigacchet (MU 1.2.12). Tad vijñānārtham, lati mo nipa sayensi mimo yi, agbodo gba guru. Gurum eva, eyan gbodo. Bbeko kolese se. Nitorina ni Arjuna se gba Krsna bi oluko mimo re, gege bi oluko tabi baba, o ni agbara na lati kiloo fun omo re tabi akeko re.. Omode o gbodo binu ti baba re ban kilofun. Iwa to ye ko wa nibikibi leleyi. Ti baba re ba tie ni iwa tio da, omo re gbodo faramo. Apeere to daju ni Prahlada Maharaja. Omo to dara, omo pelu imoye Krsna, sugbon baba re sin fiyaje. Ko so nkankan. " O daa be" Beena Krsna leyin igba todi oluku fun Arjun si pe Arjun l'ode nla. Gege bi Caitanya Mahaprabhu se sowipe " Oluko mimo sofun mi ode nla nimi (CC Adi 7.71)." S'ode ni Caitanya Mahaprabhu je? Seyin rowipe enikan le d'oluko fun Caitanya Mahaprabhu? Nkan mejeji wanyi o lese se. Caitanya Mahaprabhu gan, teyin o ba tie gba wipe o je nkankanna pelu Krsna, teba kan foju alakowe wo, koseni na to logbon to. Sugbon o sowipe " Oluko sowipe didirin mi." Kini itumo re? Pe " Eyan bi temi gbodo wa bi ode niwaju Oluko re. Nkan to da fun niyen." Koseni toye ko kilofun pe " Kilo mo? Mo moju e lo" Ipo yi o daju. Nkan imi to wa ni lati apa akeko, kilode toye ko huwa bi ode niwaju oluko re? Afi timoba je ode bawo lose fe ko mi Eyan gbodo wa oluko, lesekese toba ri eyan na gbodo wa bi ode, botilejepe eyan na gan logbon, sugbon nkan to da niwipe ogbodo wa bayi. Beena Arjuna, dipo to ma wa bi ore Krsna, si gba ki Krsna je oluko re, osi di didirin niwaju Krsna. Beena Krsna ti gba pe " Ode ni e> On soro bi alakowe sugobn didirin loje, nitoripe on sunkun fun nkan tio ye ko sunkun." Itumo re niwipe " awon ode lon sukun," pe " Ode loje". Nitorina ode ni e." Oro ton f'ogbon so... gege bi eto ogbon, kilon pe? Parenthesis? tabi kilon pe. Beeni, pe tinba sowipe "O dabi wipe iwo lo ji ago mi, " Itumo re niwipe " O dabi ole." Beena Krsna ti salaaye bayi pe "Arjuna mi, on soro bi alakowe, sugbon on sunkun lori nkan tio ye ki alakowe sukun."