YO/Prabhupada 0544 - We are Especially Stressing on the Mission of Bhaktisiddhanta Sarasvati Thakura: Difference between revisions
(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0544 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1976 Category:YO-Quotes - Le...") |
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists) |
||
Line 7: | Line 7: | ||
[[Category:YO-Quotes - in India, Mayapur]] | [[Category:YO-Quotes - in India, Mayapur]] | ||
<!-- END CATEGORY LIST --> | <!-- END CATEGORY LIST --> | ||
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE --> | |||
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0543 - It is not That you Have to Make a Gigantic Show of Becoming Guru|0543|YO/Prabhupada 0545 - Real Welfare Activity Means to See to the Interest of the Soul|0545}} | |||
<!-- END NAVIGATION BAR --> | |||
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK--> | <!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK--> | ||
<div class="center"> | <div class="center"> | ||
Line 19: | Line 22: | ||
<!-- BEGIN AUDIO LINK --> | <!-- BEGIN AUDIO LINK --> | ||
<mp3player> | <mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/760221BA.MAY_Bhaktisiddhanta_App_01.mp3</mp3player> | ||
<!-- END AUDIO LINK --> | <!-- END AUDIO LINK --> | ||
Line 39: | Line 42: | ||
:([[Vanisource:CC Adi 9.41|CC Adi 9.41]]) | :([[Vanisource:CC Adi 9.41|CC Adi 9.41]]) | ||
Ise-apinfunni Caitanya Mahāprabhu niyen, para-upakāra. lati huwa to da fun awon eyan nitumo Para-upakāra ninu awujo awon eyan orisiri ipo lowa. kese nkan dada fun awon eyan - awon egbe iranlowo eyan - to posi tabi to kere si Kilode to posi tabi ton kere si? awon eyan bayi rowipe a nkankana lonje pelu ara wan, pe tonba de sise iranlowo die fun ara wan. sugbon ise iranlowo koniyen. nitoripe ninu Bhagavad-gītā atini oye to daju gan, antavanta ime dehaḥ nityasyoktāḥ śarīriṇaḥ. antavat ni ara yi je. Itunmo Anta niwipe ara yi ma tan gbogbo eyan lomope fun igba die loma wa. gbogbo nka aye yi - bhūtvā bhūtvā pralīyate ([[Vanisource:BG 8.19|BG 8.19]]) - osi ni ojo ton bi, a duro fun igba die, lehin na asi paari. Lati le mowipe " moyato si ara mi" ni ibere eto-iwe mimo" Eto-iwe mimi leleyi. ninu Bhagavad-gita itosona alakoko ti Krsna fun Arjun niwipe ayato si ara wa. nitoripe Arjuna nsoro lati ipo ara, Krsna si kigbe mo, pe aśocyān anvaśocas tvaṁ prajñā-vādāṁś ca bhāṣase: ([[Vanisource:BG 2.11|BG 2.11]]) "Arjuna on soro bi alakowe, sugbon on sukoun nitori nkan aye yi nkan toje pe awon alakowe gidi ole sukun fun." Aśocyān anvaśocas tvam. | Ise-apinfunni Caitanya Mahāprabhu niyen, para-upakāra. lati huwa to da fun awon eyan nitumo Para-upakāra ninu awujo awon eyan orisiri ipo lowa. kese nkan dada fun awon eyan - awon egbe iranlowo eyan - to posi tabi to kere si Kilode to posi tabi ton kere si? awon eyan bayi rowipe a nkankana lonje pelu ara wan, pe tonba de sise iranlowo die fun ara wan. sugbon ise iranlowo koniyen. nitoripe ninu Bhagavad-gītā atini oye to daju gan, antavanta ime dehaḥ nityasyoktāḥ śarīriṇaḥ. antavat ni ara yi je. Itunmo Anta niwipe ara yi ma tan gbogbo eyan lomope fun igba die loma wa. gbogbo nka aye yi - bhūtvā bhūtvā pralīyate ([[Vanisource:BG 8.19 (1972)|BG 8.19]]) - osi ni ojo ton bi, a duro fun igba die, lehin na asi paari. Lati le mowipe " moyato si ara mi" ni ibere eto-iwe mimo" Eto-iwe mimi leleyi. ninu Bhagavad-gita itosona alakoko ti Krsna fun Arjun niwipe ayato si ara wa. nitoripe Arjuna nsoro lati ipo ara, Krsna si kigbe mo, pe aśocyān anvaśocas tvaṁ prajñā-vādāṁś ca bhāṣase: ([[Vanisource:BG 2.11 (1972)|BG 2.11]]) "Arjuna on soro bi alakowe, sugbon on sukoun nitori nkan aye yi nkan toje pe awon alakowe gidi ole sukun fun." Aśocyān anvaśocas tvam. | ||
awon ise iranlowo fun ara wa, bi awon ile-iwosan ati nkan mi, gbogbo wan lon da sugbon emi lose paptaki ju. Ipinnu wa niyen. Itosoan gbogbo Veda niyen. Krsna si bere lati bi. Dehino 'smin yathā dehe kaumāraṁ yauvanaṁ jarā ([[Vanisource:BG 2.13|BG 2.13]]). | awon ise iranlowo fun ara wa, bi awon ile-iwosan ati nkan mi, gbogbo wan lon da sugbon emi lose paptaki ju. Ipinnu wa niyen. Itosoan gbogbo Veda niyen. Krsna si bere lati bi. Dehino 'smin yathā dehe kaumāraṁ yauvanaṁ jarā ([[Vanisource:BG 2.13 (1972)|BG 2.13]]). | ||
<!-- END TRANSLATED TEXT --> | <!-- END TRANSLATED TEXT --> |
Latest revision as of 00:10, 14 June 2018
Prabhupāda: Eni ni ojo tose pataki fun Oluko wa Oṁ Viṣṇupāda Paramahaṁsa Parivrājakācārya Aṣṭottara-śata Śrīmad Bhaktisiddhānta Sarasvatī Ṭhākura Prabhupāda. ise-apinfunni Śrīla Bhaktisiddhānta Sarasvatī Ṭhākura lehin bi ile-aye re se ri, awa fe soro lori bi Ise re apifunni Śrīla Bhaktisiddhānta Sarasvatī Ṭhākura se ri. teletele Miyapura ni oruka Mayapura nisin. awon muslumman lon kun nibe. bakanna oruko na yi lati Mayapur si Miyapur osini awon eyan tio mo ibiti aaye ibimo Śrī Caitanya Mahāprabhu wa Bhaktivinoda Ṭhākura si bere sini sewaadi nipa ibi ti aaye na wa. labe idari Jagannātha dāsa Bābājī Mahārāja, wansi riwipe Yogapīṭha towanisin ni ibi ibimo Caitanya Mahāprabhu. Bhaktivinoda Ṭhākura sife tunbe se kiakia kosi dara fun oruko mimo Śrī Caitanya Mahāprabhu beena lo bere sini seto atune Mayapur, sugbon kole paari ise na, osi fun Bhaktisiddhānta Sarasvatī Ṭhākura. pelu awon akeko toni, wansi sise gan nibi, ise awa na ni lati tunbi se. Nitorina lase soloruko ile-Olorun Māyāpur Chandrodaya awa na fe tunbi se dada, kosi rewa, nisin pelu ore-ofe Olorun atini atiseyin awon ara ilu America anfanni Bhaktivinoda Ṭhākura iwipe awon eyan ma wa lati orile-ede America sibi wansi tunbi se, wande korin pelu awon omo-ilu India Ala toni pelu ase Caitanya Mahāprabhu
- pṛthivīte āche yata nagarādi grāma
- sarvatra pracāra haibe mora nāma
- (CB Antya-khaṇḍa 4.126)
Caitanya Mahāprabhu si fe ki gbogbo awon omo-ilu India kon ti egbe yi siwaju.
- bhārata bhūmite manuṣya-janma haila yāra
- janma sārthaka kari' kara para-upakāra.
- (CC Adi 9.41)
Ise-apinfunni Caitanya Mahāprabhu niyen, para-upakāra. lati huwa to da fun awon eyan nitumo Para-upakāra ninu awujo awon eyan orisiri ipo lowa. kese nkan dada fun awon eyan - awon egbe iranlowo eyan - to posi tabi to kere si Kilode to posi tabi ton kere si? awon eyan bayi rowipe a nkankana lonje pelu ara wan, pe tonba de sise iranlowo die fun ara wan. sugbon ise iranlowo koniyen. nitoripe ninu Bhagavad-gītā atini oye to daju gan, antavanta ime dehaḥ nityasyoktāḥ śarīriṇaḥ. antavat ni ara yi je. Itunmo Anta niwipe ara yi ma tan gbogbo eyan lomope fun igba die loma wa. gbogbo nka aye yi - bhūtvā bhūtvā pralīyate (BG 8.19) - osi ni ojo ton bi, a duro fun igba die, lehin na asi paari. Lati le mowipe " moyato si ara mi" ni ibere eto-iwe mimo" Eto-iwe mimi leleyi. ninu Bhagavad-gita itosona alakoko ti Krsna fun Arjun niwipe ayato si ara wa. nitoripe Arjuna nsoro lati ipo ara, Krsna si kigbe mo, pe aśocyān anvaśocas tvaṁ prajñā-vādāṁś ca bhāṣase: (BG 2.11) "Arjuna on soro bi alakowe, sugbon on sukoun nitori nkan aye yi nkan toje pe awon alakowe gidi ole sukun fun." Aśocyān anvaśocas tvam.
awon ise iranlowo fun ara wa, bi awon ile-iwosan ati nkan mi, gbogbo wan lon da sugbon emi lose paptaki ju. Ipinnu wa niyen. Itosoan gbogbo Veda niyen. Krsna si bere lati bi. Dehino 'smin yathā dehe kaumāraṁ yauvanaṁ jarā (BG 2.13).