YO/Prabhupada 0557 - We Should Be Very Strongly Inclined to Krishna Consciousness Like Haridasa Thakura: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0557 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1968 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0005 edit: add new navigation bars (prev/next))
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in USA, Los Angeles]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, Los Angeles]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0556 - First Understanding of Self-realization, that Soul is Eternal|0556|YO/Prabhupada 0558 - Our Position is Marginal. At Any Moment, We Can Fall Down|0558}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 19: Line 22:


<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/681219-BG_part9_clip.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/681219-BG_part9_clip.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->



Latest revision as of 12:43, 21 September 2017



Lecture on BG 2.62-72 -- Los Angeles, December 19, 1968

Tamāla Kṛṣṇa: Oro imoye nikan loje ati gbigba eto yi Khaṭvāṅga Mahārāja si de ipo to gaju yi niseju kan ko to ku nitoripe osi teriba fun Krsna. Lati fi ipaari si ona ile aye yi nitumo Nirvāṇa. Gege bi imoye Buddha yi se so, ofurufu nikan lowa lehin ile aye yi. Sugbon nkan to yato ni Bhagavad-gita kowa. Lootoo aye wa ma bere nigbati ile aye yi ba tan. Fun awon ton feran aye yi, fun won o too lati fi ipaari si ile aye yi. sugbon fun awon eyan mimo, ile aye imi wa leyin ile aye yi. Nitorina, koto pari aye re, teyan ba ni ori-ore lati ni imoye Krsna, o daju pe lesekese loma de ipo brahma-nirvana. Kosiyato laarin ijoba odo metalokan ati ise s'Oluwa. Nitoripe awon mejeji wa lori ipo pipe, lati sise ninu ise Oluwa nkankana loje pelu wipe awa ni odo metalokan. Ninu ile aye yi awon ise fun igbadun ara wa lowa, sugbon ni odo metalokan awon ise nibe ni imoye Krsna. Nitorina tabe de ipo imoye Krsna ninu aye yi lesekese lama de ipo Brahman, enikeni toba wa lori ipo imoye Krsna eni na ti wole sinu odo metalokan. Oluwa. Śrīla Bhaktivinoda Ṭhākura tise ìṣoníṣókí si apa keji ninu Bhagavad-gita pe koko oro gbogbo iwe loje. Ninu Bhagavad-gita, oro pataki to wa ni karma-yoga, jñāna-yoga..."

Prabhupāda: Jñāna-yoga.

Tamāla Kṛṣṇa: "...jñāna-yoga ati bhakti-yoga. Ninu apa keji, wanti salaaye nipa karma-yoga ati jñāna-yoga, wande ti fun wa ni soki nipa bhakti-yoga. Eleyi je ipaari ijabo Bhaktivedanta lori apa keji ninu Śrīmad Bhagavad-gītā lori eto akoonu re."

Prabhupāda:Ese pupo. Se ibeere kankan wa? Beeni.

Tamāla Kṛṣṇa: moni idaamu kan .. Won sowipe awon olufokansi mimo bi Haridasa Thakura o le bosinu ìdánwòêtàn ti Mayadevi, sugbon Brahma, Siva, won bosinuu asise yi. Mosi rowipe awonn Olufokansi mimo niwon.

Prabhupāda: Rara. Olufokansi mimo niwon, sugbon gunavatara na lonje. Gege bi Brahma seje eda to gaju ninu aye yi. Oun ni baba gbogbo eda. Looto, taba wo dada,, Haridasa Thakura gaju Brahma lo ninu eto ise ifarasi Oluwa. Botilejepe eda atunwa latii Brahma loje, Brahma Haridasa. Beena ema jeko funyin ni idaamu teba ri Brahma ati Siva ninu asise wanyi. Agbodoo gba itosona wanyi pe ti Brahma, ati Siva le bosinu owo maya nigbami, tal'aje? Nitorina oye ka se jeje gan. Awon eyan pataki bi Brahma ati Siva gan won le subu lati ipo toni, kama wa so eyan bi tawa. Nitorina lasen soro wipe emu imoye Krsna yi nipataki bi Haridasa Thakura. Lehin na awon ìdánwòêtàn maya o le fun wa ni isoro kankan. Oye ko yewa. " kon sepe Brahma o lagbara" Rara. Lati fi salaaye funwa loje.