YO/Prabhupada 0556 - First Understanding of Self-realization, that Soul is Eternal
Lecture on BG 2.62-72 -- Los Angeles, December 19, 1968
Prabhupāda: Awon eyan aye yi o mo nipa ojo'waju. Won rowipe ara eda yi nigbogbo nkan. " Ati ni ara eda yi, nigbato ba tan, oti tan niyen." Awon ibeere wanyi ati salaaye tele. Sugbon looto beeko loje. Imoye talakoko niu eto imora-eni leleyi, emi wa tayeraye, kole paari t'ara eda yi ba paari. Ibere imora-eni leleyi. Beena koye awon eyan wanyi. Ko jowon loju. Orun sisun won niyen. Ibanuje aye won niyen. Tesiwaju.
Tamāla Kṛṣṇa: " Asi tesiwaju pelu awon ise re lati ni imo ara re laini inira kankan lati awon ibajade aye yi." 70: " Enikeni t'okan re bale botilejepe ife okan ton wole sinu okan re po bi omi odo sinu omi okun, ton posi nigbogbo'gba sugbon tosi dake, eyan bayi nikan lole ni alafia, kon se okurin tofe gbadun awon ife okan wanyi."
Prabhupāda:Nisin, eyan to feran awon ohun aye yi, oni awon ife okan re. Kasowipe on sise ton pa owo. Asi gbadun ife okan re bosefe si. sugbon eni toni imoye Krsna, kasowipe oun na sin se bayi, osin seto lati se nkan lehin imoye Krsna re. Beena awon ise mejeji wanyi yato si'ra won. Tesiwaju.
Tamāla Kṛṣṇa: 70: Eni tio kin.... 71: Enito ti fi gbogbo ife okan lati gbadun sile, tio ni ife okan mo, tio fe sebi onile ohun ini re tiosi ni igberaga kankan, oun nikan lole ni alaafia to daju."
Prabhupāda: Beeni. Eni to ti fi gbogbo ife okan lati gbadun sile Awa o gbodo pa awon ife okan wa. Bawo lese fe pa if okan yi gan? Ife okan wanyi, nkan tawa ole fi sile loje. Aami eda to wa laaye niyen. Nitroripe moje eda to wa laaye, eyin na je eda to wa laaye, moni awon ife okan mi, eyin na ni awon ife okan yi. Tabili yi ko. Tabili yi o l'emi kankan, nitorina ko ni ife okan kankan. Tabili yi o le sowiep " moti duro sibi fun aimoye osu. Edakun e mumi losibomi." Rara. Nitoripe koni ife okan kankan. Sugbon motin joko sibi nisin fun wakati meta, oh, masowipe, " OH oti remi. Edakun e mumi kuro nibi.. Edakun emumi losi'bomi. Ife okan yi gbodo wa nitoripe eda to wa laaye ni wa. Agbdo ni iyipada ni ife okan wa. Taba fi ife okan wa fi gbadun ara wa , nkan aye yi niyen je. sugbon taba fi ife okan yi fi sise fun Krsna, ife okan wa ti tan niyen. àmúyẹ ìwárí to wa niyen.
Tamāla Kṛṣṇa: 72: "Ona ile aye mimo leleyi, lehin igba tojepe ogbon okurin o le salo mo. Pelu okan bayi tasiko iku bade, eyan le pada si odo Metalokan." Iye: " Eyan le ni imoye Krsna niseju kan, tabi lehin aimoye ibimo saye yi."
Prabhupāda: Aimoye igba ti awon eyan ti beere " Fun igba melo loma gba lati ni imoye Krsna yi?" Moti daaun pe niseju kan ele se. Nkankana lon salaaye. Tesiwaju.