YO/Prabhupada 1069 - Awon esin aye isin man soro nipa igbagbo. Igbagbo awon eyan le yipo - sugbon Sanatana dharma o le yipo

Revision as of 11:09, 27 March 2015 by YamunaVani (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 1069 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com

660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Nitorina, sanatana-dharma, basele salaaye tele, pe Oluwa ni sanatana, odo metalokan, leyin awon sanmo mimo yi, sanatana na niyen. Awon eda aye yi, sanatana na ni won. Beena pelu asepo laarin Oluwan sanatana, awon eda sanatana, ninu odo metalokan sanatana ni ipinnu aye eda eyan. Oluwa si ni ore-ofe to po gan fun awon eda nitoripe awon dabi omo s'Oluwa. Oluwa gan ti sowipe sarva-yoniṣu kaunteya sambhavanti mūrtayo yāḥ (BG 14.4). Gbogbo awon eda.. Awon orisirisi eda lowa pelu karma orisirisi, sugbon Oluwa ti sowipe oun ni baba gbogbo won, beena lati fun won nigbala ni Oluwa sen sokale wa lati mu won pada si sanātana-dhāma, si sanma sanātana, beena awon eda sanatana le beere lati tun ipo sanatana won se ninu asepo pel'Oluwa. Oun gan fun ara re lon wa ninu orisirisi irisi. Nigbami asi ran awon iranse re bi omo re tabi alabasepo tabi acarya lati mu awon eda wanyi pada.

Nitorina sanatana-dharma o kin s'esin fun awon egbe kan soso. Ise tayeraye fun awon eda ninu asepo ton ni pelu Oluwa towa tayeraye. Beena ise tayeraye nitumo sanatana-dharma Śrīpāda Rāmānujācārya ti salaaye nipa oro sanatana " nkan tio n ibeere tabi ipaari." taba de fe soro lori sanatana-dharma agbodo mowipe lori ase Śrīpāda Rāmānujācārya , koni ibeere tab'opin kankan. Oro ton pe l'esin yato si sanatana-dharma. Igbagbo nitumo Esin. Igbagbo yi le yipo. Eyan le ni'gbagbo ninu nkan, toba de ya keyan na si ni igbagbo ninu nkan imi. Sugbon itumo sanatana-dharma ni oun teyin o le yipo. gege bi omi ati sisan. Kosi beyin sele se k'omi ma san. Oru at'ina. Kosi besele yo oru kuro ninu ina. Beena, Ise tayeraye eda ni sanatana-dharma kode si beyin sele yipo. Kosi besele yipo re. Agbodo gbiynaju lati mo nkan toje ise tayeraye fun awon eda. T'a ba n'soro nipa sanatana-dharma agbodo gba wipe lori ase Śrīpāda Rāmānujācārya, koni ibeere ati ipaari. Nkan tio l'opin, ko ni'bere, kode gbodo wa fun esin kan soso. Tawa ban se alapejo lori sanatana-dharma, awon eyan lati awon esin toyato le bere sini rowipe pe awa n'soro lori awon nkan fun esin wa. Sugbon taba wole sinu koko oro, taba si wo gbogbo nkan labe ina sayensi, O daju pe a le ri sanatana-dharma bi'se fun gbogbo awon eda aye yi, rara, gbogbo eda lori agbye yi yi. Awon esin tio mo nipa sanatana, le beere die ninu awujo eda eyan, sugbon kole si itan akoole kankan lori sanatana-dharma nitoripe lati'gba ti aawon eda ti wa loti wa. Beena, lori oro awon eda, a ti ri ninu awon sastra wipe awon eda o le ni iibio tabi iku kankan. Ninu Bhagavad-gita wan ti salaaye wipe awon eda o le ni ibimo, kode si bonsele ku. Tayeraye lo wa fun, asi wa laye leyin igba ti ara eda yi ba tan.