YO/Prabhupada 0309 - Spiritual Master is Eternal

Revision as of 12:02, 21 September 2017 by Vanibot (talk | contribs) (Vanibot #0005 edit: add new navigation bars (prev/next))
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Lecture -- Seattle, October 2, 1968

Madhudviṣa: Se ona wa fun awon elesin Kristiani, laini oluko ninu eto emi, lati de ijoba orun tonba gbokan le awon oro Jesu Kristi, tonba de gbiyanju lati tele awon ilana to fisi le?

Prabhupada: Ko yemi.

Tamala Krsna: Se eyan toje Kristiani ni asiko tawayi, laini Oluko mimo, sugbon ton ka bibeli, to sin tele awon oro Jesu...

Prabhupada: Teyan na ban ka bibeli, oun tele oluko niyen. Bawo lesele sowipe koni oluko? Lesekese teyin ba ka Bibeli, itumo re niwipe eyin tin tele awon ilana Jesu Kristi niyen, etin tele Oluko mimi yin niyen. Nibo l'oro pe'yan o ni Oluko mimo wa?

Mudhudvisa: Mon soro nipa Oluko to wa laaye.

Prabhupada: Fun ayeraye ni oluko mimo yi wa fun. Ibeere re ni wipe laisi Oluko mimo. Kosi besele wa laisi Oluko mimi ninu aye yin. Ele tele Oluko yi tabi imi. Iyen o wulo. Sugbon egbudo gba'kan. Lesekese teyin ban ka bibeli, etin tele Oluko mimo niyen tosi leyan bi awon alufaa toje asoju fun, gege bi Oluwa Jesu Kristi. gege na, egbudo tele oluko mimo. Kosejo pe eyin o ni Oluko kankan. So ye e?

Mudhudvisa: Nkan ti mon so niwipe kosi basle ni oye nipa Bhagavad-gita laisi iranlowo yin.

Prabhupada: Gege na tebafe ni oye nipa Bibeli egbudo gba iranlowo lati alufaa ninu ile-adura.

Madhudvisa: Beeni. Sugbon bawo lase femo toba je wipe nkan ton so lati awon ton siwaju re loti wa? Nitoripe adabiwipe isotunmo ninu bibeli awon asisie kan wa n'be. Orisirisi egbe Kristiani man fun Bibeli wan ni orisirisi isotunmo.

Prabhupada: Beeni, kosi besele se isotunmo si bibeli. Toba jebe kosejo pe Bibeli je iwe tole fun awon eyan ni'dari. teyin ba fun nkan ni isotunmo... E pe awon nkan gege bon se je." Teyin ba so nkan imi, oluko kon niyen. Gege bi ago owo yi, gbogbo eyan lon pe l'ago, sugbon temi ba bere sini pe ni igo-oju, kini iwulo mi bhi Oluko mimo? Mo kan tan awon eyan je. Ago loje, mogbudo so be. (Erin) Toban se istotunmo ti o daju, Oluko mimo to daju koniyen. Iru eyan bayi o kin se Oluko mimo to daju. Tin ba fe ko e lati ka ago, mo le sowipe " Ago leleyi, owo ago leleyi, nkan ta fin mo nkan t'aago n'so leleyi.. nkan to da niyen. Sugbon tin ba sowipe " gbogbo eyan n'pe l'aago sugbon emi ma pe ni igo oju," iru oluko wo nimo je? Efi iru eyan bayi sile lesekese. Egbudo l'ogbon lati mo eni toje oluko gidi ati awon oni ro. Bibeko wan ma tanyin je. Nkan ton sele niyen, gbogbo eyan n'se isotunmo bonsefe. Aimoye Bhagavad-gita to wa teletele, gbogbo wan lon se isotunmo bonsefe, sugbon iranu ni gbogbo e. Ko so gbogbo wan danu. eyin gbudo ka Bhagvad-gita gege boseje. Leyin na gbogbo e loma ye yin. Kejo pe eyin se isatunmo. Tobajebe, idari lori re ti ton. Lesekese teba se isotunmo kosejo idari mo Iwe ofin. Seyin fe sowipi ninu ile-adajo ele sofun adajo , " Oga mi, emi fe se isotunmo bayi si ofin yi," seyij rope oma gba? Lesekese ni adajo na ma sofun yin, " Taloje tofe se isotunmo si awon ofin? iwo o l'agbara yen." Ki wa ni idari ninu awon iwe ofin ti gbogbo eyan ba sowipe " Bo se yemi leleyi"? Igba wo loyeke se isotunmo? Nigbati nkan o ba ye awon eyan. Tin ma sowie, "Aago leleyi," ti gbogbo eyan mo pe aago leleyi kini iwulo pe mofe salaaye pe igo-oju leleyi? Ti awon ba ni oye nipa oro na boseje... gege bi bibeli, " Olorun sowipe, " Ka'aaye yi da, ayi si wa" Kini iwulo isotunmo? Beeni. Oluwa ti daa. Eyin o le daa nkankan. kini iwulo isotunmo? Awon isotunmo orisirisi wanyi o wul, ko de daju, awon eyan ton sin se isotunmo orisirisi, oye ke pawanti lesekese. Lesekese, lai rori wo. Olorun ti sowipe, " K'aaye si daa." Aye si daa. Nkan to rorun niyen. Ki lon fe se isotunmo si? Iru isotunmo wo lonfe sse nibi? Sele sofunmi iru isotunmo wo lole wa. Se oto oror koni mo so? Ni ibere bibeli wan so bayi? " Olorun sowipe, " Kayesi wa, aye si da. Kini isotunmo yin? Esofunmi kini isotunmo yin. Se isotunmo imi lelwa? Sele sofunmi? Nibo ni isotunmo lewa ninu eleyi? Sele sofunmi. Nkan imi niyen. sugbon pe Olorun ti da aye yi, iyen gbudo wa. Kosi besele yipada. Nisin, bi iseda yi se sele, Bhagavatam ti salaaye: Ni alakoko, afefe lowa, lehin na ohun, lehin na orisirisi nkan. Ilana iseda niyen, nkan imi niyen. Sugbon otito oro pe Olorun lo da aye yi, kosi besele yipada. Kon sepe awon oniranu sayeni a sowipe, " Okuta kan wa to laa simeji, Lehin na awon isogbe orun na wa jade. Iranu ni gbogbo eleyi. Wan kon se isotunmo bonsefe Sayenis ko niyeh- teyin ban sowipe "boya" "odabiwipe" Kilode toseje "boya"? Oro to daju leleyi, " Olorun ti da." Otan.