YO/Prabhupada 0310 - Jesus is the Representative of God, and Hari-nama is God
Lecture -- Seattle, October 2, 1968
Prabhupāda: Kilode?
Mahāpuruṣa: Prabhupāda, se idamu kankan wa, nitoripe Oluwa Jesu Kristi ati Oluwa Caitanya wan jo wa ninu asiko Kali, ati wipe Oluwa jesu Kristi sowipe " koseni tole wa si Olorun lai koja mi. E nigbagbo ninu mi tabi ke teriba simi," ati wipe Oluwa Caitanya si kowa wipe afi hari-nama, ko sona mi ninu asiko tawayi lati ni oye Olorun?
Prabhupāda: Nibo ni iyato na wa? Ti Jesu Kristi ba sowipe "lati emi," itume re niwipe asoju Olorun loje, sugbon Olorun ni hari-nama. Gege na boya lati Olorun tabi asoju Olorun nkankana loje. Olorun ati awon asoju re kosi iyato kankan. Ninu awon eto kekere tawa gan tin ba ran asoju mi ko lo tewe funmi9, mo gbudo gba nitoripe asoju mi loje. gege na, ale summon Olorun lati awon asoju re. Nkankana loje. Iyato to wa ni oye to wa nibe. Nitoripe Oluwa Jesu Kristi salaye fun awon eyan tio fi be l'opolo. eyn na le ri fun ara yin, nitoripe wan si fi ku pa eyan pataki Olorun. Eyin na le ri ipo awujo yi. Nitorina ale sowipe awon oniranu lon wa ninu awujo yi. Wan eyan wanyi ole ni oye nipa eto Olorun. Otobe. "Olorun da aye yi. Egba gbe." Awon eyan yi o lo mo bi Olorun se da ile aye yi. Toba jepe wan logon wan o ni fiku pa Jesu Krsiti. Agbudo ni oye nipa eto awujo tawayi. gege bi Koran, Muhammad si sowipe " lati oni lo ema ni imo ako ati abo pelu iya yin mo." Sele ri iru awujot toje. Agbudo wo iru asiko wo loje, iru nkan wo lonje sele nigbana taba fe se iwaasu. Fun awon awujo bayi kosi bonsele ni oye nipa awon nkan nipa emi, gege bi Bhagavad-gita se so. Suggbon nkan to se pataki niwipe, Olorun ni Oludari, awon iwe mimo Bibeli ati Bhagavad-gita si sobe. Bibeli sowipe Olorun ni Oludari gbogbo wa, Bhagavad-gta sowipe "E teriba fun." Kini iyato to wa nibe? Nkan to wa niwipe, bin se salaye yato nitori, asiko, awujo ati ibij ton wa. Otan. Arjuna ko ni awon eyan. se bayi? Awon nkan to ma ye arjuna konse awon nkan to ma ye iru awon eyan ton fi ku pa Jesu Kristi. Egbudo ka awon iwe pelu oju kanna. Nkankana. Iwe-itumo, iwe kekere, iwe omo fun itumo oro, ati iwe itumo fun gbogbo awon orile-ede, iwe itumo ni gbogbo wanje, sugbon iyi wan yato. Nkan wa fun awon omode, ikeji fun awon agba alakowe. Sugbon kosi besele sowipe iwe itunmo kon lonje. Eyin o le sobe. Iwe itunmo ni awon mejeji je. agbudo wo asiko, ibi, awon eyan, gbogbo nkan bayi. gege bi Oluwa Buddha, osowipe " ema pa awon eranko wanyi mo". Ise apinfunni to mu wa niyen. Awon eyan tio logbon rara niwan je. sugbon lati fun wan ni ilosiwaju, Oluwa Buddha si sowipe ema se iranu yi mo: " Ema pa awon eranko yi mo." Gege na orisirisi awon asoju Olorun lonwa lati ko awon eyann ni awon asiko toyato si ra wan. gege na nitori asiko to yato, awon ijuwe na le yato si ra wan, sugbon oro pataki to wa, nkankan loje. Oluwa Buddha sowipe, " Kos'Olorun E teriba funmi." Kini iyato? Itumo re niwipe agbudo gba idari Olorun bakanna tabi keji.